YO/Prabhupada 0355 - I Am Speaking Something Revolutionary

Revision as of 12:10, 21 September 2017 by Vanibot (talk | contribs) (Vanibot #0005 edit: add new navigation bars (prev/next))
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Lecture on SB 5.5.1-8 -- Stockholm, September 8, 1973

awon koseemani nitumo Kaman. Ele ri awon kosemani tefa gba le ro. Teba san ko, ele ri awon woru irugbin, teba sini maalu, eleri wara. Otan. Otito bayi. Sugbon awon Olori sin seto to wan wipe, ti awon eyan yi bani itelorun ninu ile ton ni, pelu woru irugbin ati wara, talo ma sise ninu awon ile-ise ero? Nitorina wan se gba owo-ori to po gna, gege bayi kosi besele gbe ile-aye to rorun- nkan tio wa niyen. Teba tie fe awon Olori lasiko tawayi o ni gba. Wan fe ke sise bi Aja ati elede ati ketekete. bo se jeniyen.

Sugbon, awa na gbudo fi iru ise lile yi sile. Awon oniijoba le fe wa sen nkan simi nitoripe mon soro nipa nkan to le yipada gbogbo agbaye. Beeni. Sugbon otooro niwipe. Kilode tefe ka sise? Olorun tin pese fun awon eye, eranko, kokoro, mode je elesin Olorun, se koi pese funmi? Kini mose tioda? Ema jeki eleyi fun yin ni idamu. Ema ni awon koseemani tefe, sugbon e ma sise yin lo ninu imoye Krsna. Ema jeki ainigbagbo yi funyin ni ibanuje.

Ese Pupo.