YO/Prabhupada 0354 - Blind Man Leading Other Blind Men



Lecture on SB 2.3.2-3 -- Los Angeles, May 20, 1972

Pradyumna: " Isotunmo: Ninu awujo awon eyan aimoye okurin at'obirin to wa, sugbon opolopo ninu an o logbon nitoripe wan o mo nipa emi.

Prabhupada: idanwo wa niyen, aimoye Okurin ati obrin to wa laayeyi, sugbon koseyi to logbon. Ipenija wa niyen. Gege na awon eyan le rowipe iranu ni egbe imoye Krsna yi, tabi kawa sofun wan pe " gbogbo yin ti ya were." Nitorina a si iwe kekere kan, " Tal'ori re o pe?" Nitoripe wan rowipe awon omo-okurin wanyi ton fa irun ori wan ti ya were. sugbon awon lon yawere. Nitoripe wan o logbon. Kilode? Wan o mo nipa emi. Imoye eranko. Aja, ologbo, wan rope ara wan lonje.

yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke
sva-dhīḥ kalatrādiṣu bhauma ijya-dhīḥ
yat tīrtha-buddhiḥ salile na karhicij
janeṣv abhijñeṣu sa eva go-kharaḥ
(SB 10.84.13)

Go-khara. Maalu nitumo Go, ketekete itunmo ass. Awon eyan tonn feran ara wan ton rowipe " Ara mi, nimoje." kasowipe 99.9% awon eyan ninu aye ri bayi, " ara mi nimo je" " omo ilu America nimi, omo-ilu India nim, African nimi... wan ja bi aja at'ologbo. Ologbo ni mi aja nie, Aja ni e, ologbo nimi. Otan. gege na oro yi ta sowipe, "oniranu ni gbogbo yin," oro tole gan ni, sugbon otoooro loje. otooror loje. Egbe iyipada loje, awa fe pe gbogbo eyan nija pe " Ketekete ati maalu at'eranko ni gbogbo yin, nitoripe eyin o ni imoye kankan to koja ara yi." Nitorina moti salaaye tele. " Nitoripe wan ni imoye die nipa emi, awon eya yi o gbon. Moti ba awon alamodaju nla nla soro. NI Moscow, okurin na, alamodaju Kotovsky o sowipe, Swamiji lehin iku kosi nkankan mo, gbogbo nkan ti tan." sugbon oun ni ikan ninu awon alamodaju ninu orile-ede na. alebu awujo aye isin leleyi, pe awon ologbo ati aja loje Olori awon ilu wanyi. Bawo lesefe ni alalafia ati ilosiwaju? Kolese se. Andhā yathāndhair upanīyamānāḥ.

Afoju ton f'ona han awon afoju imi. Toba loju, o le fona han awon eyan to po gan, " e dakun e tele mi ka soda titi." Sugbon teyan toba wa ni waju ba foju bawo lesefe ranwanlowo? Andhā yathāndhair upanīyamānāḥ. Gege na Bhāgavata, sowipe kosi afiwe kankan. kole si. Sayensi to daju leleyi. Andhā yathāndhair upanīyamānās te 'pīśa-tantryām uru-dāmni baddhāḥ (SB 7.5.31). Īśa-tantryām, awon afoju meta, wan wa ninu idinmu awo opin ile-aye yi, wansi fun awon eyan ni ona abayo. Iru ona abayo wo lon fe fun awon eyan?