YO/Prabhupada 0457 - Only Scarcity is Krishna Consciousness

Revision as of 00:01, 14 June 2018 by Vanibot (talk | contribs) (Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Lecture on SB 7.9.6 -- Mayapur, February 26, 1977

Sayensi ju isewaadi nikan lo, agbodo se idanwo na. Lehin na lo ma daju. Bibeko oror lasan nikan loje. Sayensi ko. beena won ni orisirisi oro tenikeni leso. Sugbon otooro niwipe Krsna je mimo, oun lo gaju. Nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām (Kaṭha Upaniṣad 2.2.13). Itosona veda niyen. Olorun ni nitya to gaju, ati eda to gaju. ninu iwe isotunmo wan sowipe, " Itumo Olorun leda to gaju." " Kosi bosele ye won " Eda to gaju yi." sugbiin ninu awon Veda kon seda eda to gaju nikan, sugbon eda to wa laaye to gaju. Nityo nityānāṁ cetanaś cetānām eko yo bahūnāṁ vidadhāti kāmān (Kaṭha Upaniṣad 2.2.13). Ijuwe Olorun leleyi. Beena o lee gan lati ni oye nipa awon eto mimo, ka ma wa sonipa Olorun. Ibere aye mimo niwipe agbodo mo nipa nkan t'emi je. won si rowipe emi wa nkankana loje pel'ogbon wa. sugbon emi wa ko niyne. o ju bayi lo. Apareyam itas tu viddhi me prakṛtim parā (BG 7.5).

eto pipe leleyi, bi Prahlada Maharaja, lesekese to fowokan Olorun, awa na lese. Nkan tose se loje, osi rorun, sugbon nitoripe awa ti wo lule, mandah - asi buru gan, Mandāḥ ati sumanda-matayo. nitoripe asi buru gan, gbogbo eyan ti da imoye won sile. Sumanda. Mata. Ero nitumo Mata. Kil'ero na? manada nikan ko sugbon sumanda na, osi buru gan. Sumanda-matayo. Mandāḥ sumanda-matayo manda-bhāgyāḥ (SB 1.1.10), ati gbogbo ibanuje kilode? Nigbati'moye na ba kilode teyin ose fe gba. Won ma jiyan. Alaisorire niwon. Imoye to daju, sugbon won ma jiyan, " bayi lose ri, bayi lose, boya.." Nkan ton sele leleyi. Nitorina manda-bhāgyāh. Gege bi owo se wa nibi. Awon eyan o ni gba owo na. won fe sise bi elede at'aja lati pa owo. alaisorire leleyi. Beena mandāḥ sumanda-matayo manda-bhāgyāḥ. Ati nitoripe manda-bhāgyāḥ, upadrutah wa nigbogbo gba, idamu, ogun nibi, ogun nibe, ogun. Lati'bere titi disin, ogun nikan. Kinidi fun awon ogun yi? Kilode ton se ja? koye ki'ja kankan wa, nitoripe gbogbo nkan ti wa ni pipe,pūrṇam idam (ISO Invocation). Ile aye yi kun fun ore-ofe Olorun, nitoripe ijoba... Odo metalokan na loje. Sugbon oti d'orun apaadi nitori gbogbo ogun wanyi. Otan. Bibeko.. fun olufokansi - pūrṇam. Viśvaṁ pūrṇaṁ sukhāyate. kilode ton ja? Olorun ti funwa nigbogbo nkan. S'omi lefe? Omi inu ile aye yi ju idaji aye yi lo. sugbon iyo wa ninu omi yi. Olorun si l'ona lati je k'omi yi dun lenu. Eyin o le se. S'omi lefe. Omi po. kilode t'aini yi sewa? Nisin ni Europu ati gbo wipe won fe bere sini s'ṣàgbéwọlé omi ninu Orile-ede (erin) Se beeko? Beeni. Ni orile-ede geesi won ronu lati s'ṣàgbéwọlé yi na. Solese se? (Erin) sugbon awon asiwere wanyi onisayensi. won fe s'ṣàgbéwọlé . Kilode? Iyika orile-ede geesi omi loje. Kilode teyin o le gb'omi na? Rara. Nire kari bas na me tilo piyas. "mo wa ninu omi, sugbon ofun gbemi." (erin) Imoye awon asiwere wanyi... Nigba t'a kere a ka iwe kan, iwe iwa dada, itan akoole kan wa tojepe, oko-omi nla kan yipo, o si gba iranlowo lati oko-omi kekere kan, sugbon imi niu won ku nitoripe won o le m'omi na. Beena won wa ninu omi na, sugbon orungbe lo pa won. Beena bi aye wa se ri niyen. Gbogbo nkan lowa. Sugbon asin ja t'an p'ara wa. Kinidi fun? Idi to wa niwipe aw o tele Krsna. Idi to wa niwipe: aini imoye Krsna. Guru Maharaja mi man sowipe gbogbo nkan lowa ninu aye yi. Aini kan soso to wa ni imoye Krsna. Aini kan soso. Bibeko kos'aini kankan. Gbogbo nkan lowa. teba si gba itosona ti Krsna lesekese ni inu yi ma dun. Ele jeki inu gbogbo aye dun si. Itosona ti Krsna ninu Bhagavad-gita, wa pipe. Oye ko wa ni pipe, nitoripe on wa lati Krsna. konse awon oro lasan lati awon oni sayensi wanyi. Rara. Itosona to daju. taba si tele awon itosona wanyi, taba lo dada, lehin na gbogbo agbaye, viśvaṁ pūrṇaṁ sukhāyate.