YO/Prabhupada 0470 - Mukti Is Also Another Cheating
Lecture on SB 7.9.9 -- Mayapur, March 1, 1977
Śrīdhara Swāmī ti sowipe itanje imi ni mukti je. Kinidi fun mukti? Krsna o bere pe afi teyin ba di mukta, eni to nigbala, eyin o le sise fun." Rara. Ele sise ninu ipo eyikeyi teba wa. Ahaituky apratihatā. Konsepe awa gbodo nigbala ni alakoko. Nitoripe lesekese teyin ba bere bhakti eyin ti nigbala niyen. Ipo yi se pataki toje pe awon bhakta, tio ni'fe okan imi ju ise fun Oluwa, won ti nigbala. Brahma-bhūyāya sa kalpate.
- māṁ ca ya 'vyabhicāreṇi
- bhakti-yogena yaḥ sevate
- sa guṇān samatītyaitān
- brahma-bhūyāya kalpate
- (BG 14.26)
lesekese.
- sarva dharmān parityajya
- mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja
- ahaṁ tvāṁ sarva-pāpebhyo
- mokṣayiṣyāmi...
- (BG 18.66)
Beena ti Krsna ma seto lati fi ipaari si gbogbo ese ile aye yin, itumo re niwipe lesekese leyin ti di mukta. Itumo igbala yi niwipe... Ati wole sinu idimu ile aye yi nitoripe ati da idimu yi fun ara wa. Nūnaṁ pramattaḥ kurute vikarma (SB 5.5.4). nitoripe a wa ninu iru ipo bayi, pe afe huwa tioye ka se, bobatie jepe eyin o fe... Teyin ba se jeje lati ma fiku pa kokoro sugbon laimo, teban rin aimoye awon kokoro teyin pa. Ema rowipe kos'ese fun iru'wa bayi. Eti d'elese niyen. Nipataki awon eyan tio kinse olufokansi, won gbodo daaun si fun awon eda ton pa, aimoye awon eda ton pa, nigba ton rin tabi ... Ninu awon koko omi, aimoye eda to wa ninu e. teyin ba tie gbe koko omi lasan, aimoye awon eda . teba ba tona si adiro, aimoye awon eda teyin pa. beena laimo, iru ipo bayi lawa ninu ile aye yi pe awa o le se kama see, Seti ri awon Jains, awon eyan tio feran iwa-ipa. won ma fi aso kekere fi bo enu, ki awon kokoro ba le ma wole. Sugbon awon nkan eke leleyi. Ninu afefe awon eda wa ninu omi awon eda na wa, taban m'omi. Kosi besele fi ipaari si. Kolese se. Sugbon teyin ban fokan sinu ise ifarafun Oluwa, eyin o leni idimu kankan.
Yajñārthe karmaṇo 'nyatra loko 'yaṁ karma-bandhanaḥ (BG 3.9). Ti aye yin ba wa fun yajna, fun ise Krsna, lehin na awon ese t'aba se laimo, awa o ni jiya fun. Manye mithe kṛtaṁ pāpaṁ puṇyaya eva kalpate. Beena oye ka fun ile aye wa fun imoye Krsna. Lehin na awa ti ni idaabo to daju. Bibeko awa ti wa ninu idimu aye yi pelu awon ise tanse atun ma wole sinu iyika ibimo ati'ku. Mām aprāpya nivartante mṛtyu-saṁsāra-vartmani (BG 9.3).
- nūnaṁ pramattaḥ kurute vikarma
- yad indriya-prītaya āpṛṇoti
- na sādhu manye yato ātmano 'yam
- asann api kleśada āsa dehaḥ
- (SB 5.5.4)
Idaabo to daju lo niwipe agbodo sise nigbogbo'gba ninu imoye Krsna. Lehin lale ni ilosiwaju ninu eto emi mimo pelu idaabo lati awon ese wa.