YO/Prabhupada 0001 - Ki egbe wa fe s'egbe-gberun lona mewa: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:YO-Quotes - 1975 Category:YO-Quotes - Lectures, Caitanya-caritamrta Category:YO-Quotes - in India Category:YO-Quotes - in I...")
 
(Vanibot #0023: VideoLocalizer - changed YouTube player to show hard-coded subtitles version)
 
Line 1: Line 1:
<!-- BEGIN CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN CATEGORY LIST -->
[[Category:1080 Yoruba Pages with Videos]]
[[Category:Prabhupada 0001 - in all Languages]]
[[Category:YO-Quotes - 1975]]
[[Category:YO-Quotes - 1975]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Caitanya-caritamrta]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Caitanya-caritamrta]]
[[Category:YO-Quotes - in India]]
[[Category:YO-Quotes - in India]]
[[Category:YO-Quotes - in India, Mayapur]]
[[Category:YO-Quotes - in India, Mayapur]]
[[Category:1080 Yoruba Pages with Videos]]
[[Category:First 11 Pages in all Languages]]
[[Category:Yoruba Language]]
[[Category:Yoruba Language]]
[[Category:First 11 Pages in all Languages]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 1080 - Isonisoki ti Bhagavad-gita - Oluwa ni Krishna. Oluwa fun awon egbe eyan kan soso ko ni Krishna je|1080|YO/Prabhupada 0002 - Ilosiwaju asiwere|0002}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 16: Line 20:

<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|TG60mjnVoaw|Expand to Ten Million - Prabhupāda 0001}}
{{youtube_right|c3QboP7pX10|Expand to Ten Million - Prabhupāda 0001}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->

<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/750406CC.MAY_clip.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/750406CC.MAY_clip.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->

Line 28: Line 32:

<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
TRANSLATION
Chaitanya Mahaprabhu so fun gbogbo awon Asaju/Acaryas: Nityananda Prabhu, Avaita Prabhu, Srivas ati gbogbo awon omo leyin won pe gbogbo won ni won se iranse akede fun Sri Chaitanya Mahaprabhu Nitori naa e gbinyanju lati téle ilana awon asaju Nigba na ni igbesi aye yin o se aseyori. Ati lati di Asaju ko tile soro rara. Ni akoko lati di olufookansin tootô fun Asaju ré, téle ilana ré gidi gan O ni lati gbiyanju lati té é lôrun, ki o si se ijéri imôlé Krishna O pari. Ko soro rara. Gbiyanju lati téle ilana Olukô Imôlé, Guru Maharaja, ré, ki o si fi imole Krishna mon kari ayè. Eyi ni asé Oluwa Chaitanya.
 
:āmāra ajñāya guru hañā tāra' ei deśa
:yāre dekha tāre kaha 'kṛṣṇa'-upadeśa
:([[Vanisource:CC Madhya 7.128|CC Madhya 7.128]])
 
"Ni pa titélè asé mi, iwo na a di olukô, guru" Ti a ba si télè ilana akose awon asaju pelu otitô ati ododo Ti asi gbiyanju lati jire imo Olorun, Krishna Yāre dekha tāre kaha 'kṛṣṇa'-upadeśa ([[Vanisource:CC Madhya 7.128|CC Madhya 7.128]]). Ona meji ni Krishna-upadesa Upadesa tumo si ilana Ilana lati ôdô Krishna wa, ohun na ni Krishna upadesa ati ilana ti a gba nipa Krishna, eyi naa ni Krishna-upadesa Kṛṣṇasya upadeśa iti kṛṣṇa upadeśa. Samāsa, śāsti-tat-puruṣa-samāsa. Ati Kṛṣṇa viṣayā upadeśa, eyi na ni se Kṛṣṇa upadeśa. Bāhu-vrīhi-samāsa. Eyi ni ona lati se atupale ilana ede lilo Sanskrit ati itumô ré Nitori na Krishna upadesa ni (iwe mimo) Bhagavad-gita Oluwa fun ra ré ni oun fun wa ni ilana Eni ti oun se ihinrere Krishna-upadesa, gbôdô se atunwi oun ti Krishna ba wi, ni igba naa ni o di Asaju tabi Olukoni. Ko soro rara. Gbogbo ré a ti kô si lé A gbô dô se atunwi bi èyè awoko Bi ti èyè awoko gan-gan kô. Eyè awoko o mon itumo oun ti ohun sô, o kan un se atunwi lasan ni Sugbon eyin ni lati ni oye itumo yi bakannaa Bi beko bawo ni iwo o se se alaye? Nitori naa a fé se ihinrere imolé Olorun, Krishna Nibayi, e mura si lé lati se atunwi awon ilana Krishna dara dara, laini asise tabi abuku ninu Nigba naa, ni ôjô ôla... Ka gba wipe é ni égbaarun l'oni A so di egberun lona ogorun Eyi ni a fé. Leyin eyi egberun lona egberun, ati egbe- gberun lona mewa.
 
Awon Omo Ijô: Ogoo ni fun Oluwa! Ogoo!
 
Prabhupāda: Nipase eyi, ki yi osi owon awon asaju awon eniyan yio ni oye imôlé Olôrun, Krishna ni irôwô rôsè Nitori naa è feyi seto E ma se igberaga lori asan E téle ilana Asaju Ki é si tu ara yin di mimô, dagbasoke. Nigbayi a ti worun lati gbogun le Esu Beeni. Awon Asaju ti gbogun le Esu
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 18:40, 14 October 2018

Lecture on CC Adi-lila 1.13 -- Mayapur, April 6, 1975

Chaitanya Mahaprabhu so fun gbogbo awon Asaju/Acaryas: Nityananda Prabhu, Avaita Prabhu, Srivas ati gbogbo awon omo leyin won pe gbogbo won ni won se iranse akede fun Sri Chaitanya Mahaprabhu Nitori naa e gbinyanju lati téle ilana awon asaju Nigba na ni igbesi aye yin o se aseyori. Ati lati di Asaju ko tile soro rara. Ni akoko lati di olufookansin tootô fun Asaju ré, téle ilana ré gidi gan O ni lati gbiyanju lati té é lôrun, ki o si se ijéri imôlé Krishna O pari. Ko soro rara. Gbiyanju lati téle ilana Olukô Imôlé, Guru Maharaja, ré, ki o si fi imole Krishna mon kari ayè. Eyi ni asé Oluwa Chaitanya.

āmāra ajñāya guru hañā tāra' ei deśa
yāre dekha tāre kaha 'kṛṣṇa'-upadeśa
(CC Madhya 7.128)

"Ni pa titélè asé mi, iwo na a di olukô, guru" Ti a ba si télè ilana akose awon asaju pelu otitô ati ododo Ti asi gbiyanju lati jire imo Olorun, Krishna Yāre dekha tāre kaha 'kṛṣṇa'-upadeśa (CC Madhya 7.128). Ona meji ni Krishna-upadesa Upadesa tumo si ilana Ilana lati ôdô Krishna wa, ohun na ni Krishna upadesa ati ilana ti a gba nipa Krishna, eyi naa ni Krishna-upadesa Kṛṣṇasya upadeśa iti kṛṣṇa upadeśa. Samāsa, śāsti-tat-puruṣa-samāsa. Ati Kṛṣṇa viṣayā upadeśa, eyi na ni se Kṛṣṇa upadeśa. Bāhu-vrīhi-samāsa. Eyi ni ona lati se atupale ilana ede lilo Sanskrit ati itumô ré Nitori na Krishna upadesa ni (iwe mimo) Bhagavad-gita Oluwa fun ra ré ni oun fun wa ni ilana Eni ti oun se ihinrere Krishna-upadesa, gbôdô se atunwi oun ti Krishna ba wi, ni igba naa ni o di Asaju tabi Olukoni. Ko soro rara. Gbogbo ré a ti kô si lé A gbô dô se atunwi bi èyè awoko Bi ti èyè awoko gan-gan kô. Eyè awoko o mon itumo oun ti ohun sô, o kan un se atunwi lasan ni Sugbon eyin ni lati ni oye itumo yi bakannaa Bi beko bawo ni iwo o se se alaye? Nitori naa a fé se ihinrere imolé Olorun, Krishna Nibayi, e mura si lé lati se atunwi awon ilana Krishna dara dara, laini asise tabi abuku ninu Nigba naa, ni ôjô ôla... Ka gba wipe é ni égbaarun l'oni A so di egberun lona ogorun Eyi ni a fé. Leyin eyi egberun lona egberun, ati egbe- gberun lona mewa.