YO/Prabhupada 0002 - Ilosiwaju asiwere



Lecture on SB 6.1.49 -- New Orleans Farm, August 1, 1975

Harikeśa: Isotunmo... Bi éniti o wa ni oju ala se nse ni oju orun gégé bi ara oju ala ré tabi ki o gba ara ré bi oun gan gan Bakanna, O se afihan ara re gégé bi oun naa eyi ti o gbe wo gege bi ere igbesi aye mimo tabi aimo ti aye akowa, ti ko si ni anfaani lati mo igbesi aye ré akowa tabi ti ojo ola

Prabhupāda:

yathājñas tamasā (yukta)
upāste vyaktam eva hi
na veda pūrvam aparaṁ
naṣṭa-janma-smṛtis tathā
(SB 6.1.49)

Ipo wa ni yi. Eyi ni won pe ni ilosiwaju ninu ijinlé sayénsi Ti a ko mo nkan ti a jé ni le aye akowa ati nkan ti emi o da ni eyin aye yi? Aye o lopin. Eyi ni imolé émimo. Sugbon won ko ti lé mo wi pe ile aye omo eda ko lopin Won ro wi pe "lairo télé ni mo waye yi, ati pe aye naa o wa si opin léyin iku" Ko si ibeere lori ana, oni abi ola. " E jé ki a ma gbaadun" Aimokan ni eyi njé, tamasa, aye aibikita Niitori naa, ajnah. Ajnah tumo si alaimokan Ati tani eni naa ti ko ni imo? Nibayi, tamasa. Awon ti o wa ni igbekun aimoran Orisi méta ohun ilo séda lowa: sattva, raja, tamas Sattva-guna tumo si, ohun gbogbo han ketekete, prakāśa. Bi nisinyi, ofuurufu bo oju orun; imolé oorun ko da momo Sugbon imolé wa lori ofuurufu, ohun gbogbo molé Ninu ofuurufu ko si imolé Bakanna, awon ti o wa ni sattva-guna, ohun gbogbo molé si won ati awon ti won wa ni tamo-guna, ohun gbogbo sokunkun ati awon ti o wa ni idarudapo, ti won ki se rajo-guna (sattva-guṇa) tabi tamo-guna, awon ni a n pe ni rajo-guna guna méta Tamasā. Niitori naa, ifé won wa fun ara yi ni kan lowolowo won ko bikita ohun ti yio sélé ati pe ohun ko ni imo, éda ti o jé télé Alaye yi tun wa ni ibo miran: nūnaṁ pramattaḥ kurute vikarma (SB 5.5.4) Pramattaḥ, bi eni ti o ya were Ti ko mo idi ré ti oun fi ya were. O gbagbe. ati pe ni pa isé owo ré, kini yi o sélé léyin ré, oun ko mo. Asiwere. Nitorinaa, olaju yi, ati olaju ode oni dabi olaju asiwere Won ko ni imo nipa aye awatélé, – tabi ki won ni ife si aye ti o nbo. Nūnaṁ pramattaḥ kurute vikarma (SB 5.5.4) Won si n da ésé tori tésé nitori wi pe won o ni imo ni pa aye iwatélé Gégébi Aja Kilode ti o fi di Aja, iyen ko ye. ati ki ni ipin ré l'ola? nitorinaa, Aja ti le fi igba kan jé Olootu orile-ede kan, sugbon nigbati ti o di Aja, o gbagbe. Eyi je ona miran ti māyā Prakṣepātmikā-śakti, āvaraṇātmikā-śakti. Māyā, ni ohun meji ti o fi nse agbara ti eniyan ba di aja ni pa igbesi aye ésé ré ni aye awatélé ti o si ranti pe oun ti je Olootu orile-ede ri, sugbon nibayi oun ti di Aja aye yio soro fun un lati gbe Nitorinaa māyā bo imo ré Mṛtyu. Mṛtyu tumo si lati gbagbe ohun gbogbo. A n pe eyi ni mṛtyu Nitorinaa ni a se ni iriri ni gbogbo osan ati loru. Nigbati aba la ala ni aaye o to, ni aye ti a pin niya awa gbagbe nipa ara yi, – wipe emi n dubu lé. "Ara mi n du bule ni ayika ti o dara, lori ibusun ti o fani mora." Rara. Gba wipe o n rin kiri lai nidi tabi lori oke. Nitorina, oun ngba, ninu ala, oun gba... Enikokan wa ni ife si ara yi A gbagbe ara ti tele. Eyi je aimokan. Nitorinaa, bi a se gbeyanju ati kuro ninu aimokan losi inu imo, eyi ni aseyori aye. Ti a ba fi ara wa sinu aimokan, eyi ki se aseyori. O ja si wipe a n ba aye je leyi Nitorinaa, égbé imolé Krishna arawa se lati ta eniyan ji kuro ninu aimokan losi inu imo Eyi ni eto imo ti a ti ko si lé lailai: lati tu eniyan sile. Olorun so fun wa ninu Bhagavad-gītā nipa awon olusin - ki ise fun gbogbo eniyan teṣāṁ ahaṁ samuddhartā mṛtyu-saṁsāra-sāgarāt (BG 12.7) Imiran

teṣāṁ evānukampārtham
aham ajñāna-jaṁ tamaḥ
nāśayāmy ātma-bhāvastho
jñāna-dīpena bhāsvatā
(BG 10.11)

Ni Pataki fun Olusin...O wa ninu okan enikokan sugbon fun olusin ti o ngbiyan ju lati mo nipa Krsna, O di oluranlowo re. O ran lowo Fun awon tiki se olusin. Kosi ohun ti okan won nipa …Won dabi eranko-- ti won o mo ju ka jéun, sun, ibalopo ati idabobo Won ko bikita fun ohun kankan, lati mo nipa Olorun ati ibasepo re pelu Olorun Fun awon wonyi won ro wipe kosi Olorun, ati pe Kṛṣṇa so wipe "Beeni, kosi Olorun. Iwo sun" Nitorinaa anilo sat-saṅga, ipejo olusin sat-saṅga, satāṁ prasaṅgāt, yii Nipa ajosepo olusin, awa ta akinkanju wa ji lati se iwadi oun ti o pamo tabi sokunkun nipa Olorun. Nitorina, a nilo awon ibi ipade. Ki se fun lasan ni a nsi ile ijosin kaakiri Rara. Awon ibi ipade yi wa fun lilo ati anfani agbegbe ati awujo wa lapapo.