YO/Prabhupada 0089 - Itasan Krishna ni orisun gbogbo nkan: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0089 - in all Languages Category:YO-Quotes - 19 Category:YO-Quotes - Lect...")
 
(Vanibot #0023: VideoLocalizer - changed YouTube player to show hard-coded subtitles version)
 
Line 2: Line 2:
[[Category:1080 Yoruba Pages with Videos]]

[[Category:Prabhupada 0089 - in all Languages]]

[[Category:YO-Quotes - 19]]
[[Category:YO-Quotes - 1976]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]

[[Category:YO-Quotes - in USA]]
[[Category:YO-Quotes - in France]]
[[Category:YO-Quotes - in USA, New York]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0088 - Awon akeko ti won darapo mo wa, won ti fi fun gbigba oro nipa ifetisile|0088|YO/Prabhupada 0090 - Bibeko bawo lase fe se ni ISKCON|0090}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->

<div class="center">
<div class="center">
Line 15: Line 17:

<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|8aBlVR-i3oc|Kṛṣṇa's Effulgence is the Source of Everything - Prabhupāda 0089}}
{{youtube_right|M5-BWW3TPyk|Kṛṣṇa's Effulgence is the Source of Everything - Prabhupāda 0089}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->

<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/760804BG.NMR_clip2.mp3</mp3player>  
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/760804BG.NMR_clip2.mp3</mp3player>  
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->

Line 27: Line 29:

<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Olujosin Fransé: Kini o tumo si nigbati Krishna so wipe "Emi o si ninu won"? Prabhupāda: Huh? "Emi o si ninu won" nitoripe e ko le ri nibe.. Olorun wa nbe, sugbun e ko le Ri. E o ti ni itesiwaju. Gege bi apeere miran. Nibi yi, imole oorun wa nibi. Gbogbo enyan ni oni iriri yi. Sugbon iyen o tumo si wipe oorun wa nibi. Se o daju? Oorun wa nibi a tumo si wipe... Imole oorun wa nibi tumo si wipe oorun wa nibi. Sugbon sibe, ntoripe e wa ninu itansan oorun e ko le so wipe "Emi ti ri oorun mu." Imole wa ninu oorun, sugbon oorun fun ra re ko si ninu itansan oorun. Laisi oorun ko le si itansan oorun. Iyen ko nse wipe itansan oorun ni oorun. Ni ohun kan na, e le so wipe itansan oorun ni oorun.  
Olujosin Fransé: Kini o tumo si nigbati Krishna so wipe "Emi o si ninu won"?  
 
Prabhupāda: Huh? "Emi o si ninu won" nitoripe e ko le ri nibe.. Olorun wa nbe, sugbun e ko le Ri. E o ti ni itesiwaju. Gege bi apeere miran. Nibi yi, imole oorun wa nibi. Gbogbo enyan ni oni iriri yi. Sugbon iyen o tumo si wipe oorun wa nibi. Se o daju? Oorun wa nibi a tumo si wipe... Imole oorun wa nibi tumo si wipe oorun wa nibi. Sugbon sibe, ntoripe e wa ninu itansan oorun e ko le so wipe "Emi ti ri oorun mu." Imole wa ninu oorun, sugbon oorun fun ra re ko si ninu itansan oorun. Laisi oorun ko le si itansan oorun. Iyen ko nse wipe itansan oorun ni oorun. Ni ohun kan na, e le so wipe itansan oorun ni oorun.  

Eyi ni a npe ni acintya-bhedābheda, isekan nigbakanna ti o tun yato. Ninu itansan oorun é o lero niwaju oorun, sugbon ti e ba ni anfaani lati te si nu agbaye oorun, e tun le pade oludari-oorun na. Nitooto, imole oorun na tumo si itansan ara eni ti o ngbe ninu agbaye oorun. Ti o ti wa ni alaaye ninu Brahma-samhitaa, yasya prabhā prabhavato jagad-aṇḍa-koṭi (Bs. 5.40). Lori akoto ti Krishna... E ti ri itansan Krishna ti o mbo. Iyen ni orisun gbogbo nkan. Ti imugborosi itansan na ni brahmajyoti, ati ninu brahmajyoti, awon aye-orun emi ailonka, awon aye ohun-elo, ni won gbejade. Ati ninu ikookan ati gbogbo aye-orun ni orisirisi awon nkan se gbejade. Ni gangan, itansan ara Olorun ni ipilese na, ati ipilese itansan yi ni Olorun.

<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 18:54, 14 October 2018

Lecture on BG 4.24 -- August 4, 1976, New Mayapur (French farm)