YO/Prabhupada 0101 - Ilera wa ni lati gbadun aye ti olopin: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0101 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1974 Category:YO-Quotes - Co...")
 
(Vanibot #0023: VideoLocalizer - changed YouTube player to show hard-coded subtitles version)
 
Line 5: Line 5:
[[Category:YO-Quotes - Conversations]]
[[Category:YO-Quotes - Conversations]]
[[Category:YO-Quotes - in India, Hyderabad]]
[[Category:YO-Quotes - in India, Hyderabad]]
[[Category:YO-Quotes - in India]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0100 - Gbogbo wa jemo Olorun lati igba lailai|0100|YO/Prabhupada 0102 - Iyara ti okan|0102}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 14: Line 18:

<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|n0vPdgdCzGM|Our Healthy Life is to Enjoy Eternal Life<br / >- Prabhupāda 0101}}
{{youtube_right|zqVAMFKlH9k|Our Healthy Life is to Enjoy Eternal Life<br / >- Prabhupāda 0101}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->

<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/740418PC.HYD_clip.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/740418PC.HYD_clip.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->

Line 28: Line 32:
Alejo: Kini igbeyin ilepa isokan Olorun yi?  
Alejo: Kini igbeyin ilepa isokan Olorun yi?  

Prabhupada: Beeni, igbeyin ilepa re, ni.... Rara. Mo le so pe. Igbeyin ilepa re ni, pe lati mo iyato laarin emi ati ohun elo. Bi ile-aye ohun elo se wa, aye-orun na si wa nibe. Paras tasmāt tu bhāvaḥ anyaḥ avyaktaḥ avyaktāt sanātanaḥ ([[Vanisource:BG 8.20|BG 8.20]]). Aye orun je ailopin. Ibugbe ni ile aye ohun elo. Awa je emi-okan. Awa fun ayeraye. Nitorina owo wa ni lati pada si ijoba Orun. ki se ka wa ninu aye ohun elo ki a si ma yi ara pada lati buburu si buru tabi buru si buburu. Iyen ki s'owo wa. Iyen je arun. Ilera wa ni lati gbadun aye ti olopin Yad gatvā na nivartante tad dhāma paramaṁ mama ([[Vanisource:BG 15.6|BG 15.6]]) S'eri, igbesi aye eniyan ye ki o wa nilo fun lati de ipo ainibawon aye wa - ki se lati gba ara ohun elo pupo si ti a tun ni lati yi pada. Eleyi ni ero aye.  
Prabhupada: Beeni, igbeyin ilepa re, ni.... Rara. Mo le so pe. Igbeyin ilepa re ni, pe lati mo iyato laarin emi ati ohun elo. Bi ile-aye ohun elo se wa, aye-orun na si wa nibe. Paras tasmāt tu bhāvaḥ anyaḥ avyaktaḥ avyaktāt sanātanaḥ ([[Vanisource:BG 8.20 (1972)|BG 8.20]]). Aye orun je ailopin. Ibugbe ni ile aye ohun elo. Awa je emi-okan. Awa fun ayeraye. Nitorina owo wa ni lati pada si ijoba Orun. ki se ka wa ninu aye ohun elo ki a si ma yi ara pada lati buburu si buru tabi buru si buburu. Iyen ki s'owo wa. Iyen je arun. Ilera wa ni lati gbadun aye ti olopin Yad gatvā na nivartante tad dhāma paramaṁ mama ([[Vanisource:BG 15.6 (1972)|BG 15.6]]) S'eri, igbesi aye eniyan ye ki o wa nilo fun lati de ipo ainibawon aye wa - ki se lati gba ara ohun elo pupo si ti a tun ni lati yi pada. Eleyi ni ero aye.  

Alejo (2): Se asepe na see se ni igbesi aye kan?  
Alejo (2): Se asepe na see se ni igbesi aye kan?  
Line 38: Line 42:
:ahaṁ tvāṁ sarva-pāpebhyo
:ahaṁ tvāṁ sarva-pāpebhyo
:mokṣayiṣyāmi mā śucaḥ
:mokṣayiṣyāmi mā śucaḥ
:([[Vanisource:BG 18.66|BG 18.66]])  
:([[Vanisource:BG 18.66 (1972)|BG 18.66]])  

A nyi ara pada nitori akoto awon ise elese. sugbon ti e ba jowo fun Olorun at ki e gba isokan Olorun, lesekese ni e ma wa sori ipo ti emi.  
A nyi ara pada nitori akoto awon ise elese. sugbon ti e ba jowo fun Olorun at ki e gba isokan Olorun, lesekese ni e ma wa sori ipo ti emi.  
Line 46: Line 50:
:sa guṇān samatītyaitān
:sa guṇān samatītyaitān
:brahma-bhūyāya kalpate
:brahma-bhūyāya kalpate
:([[Vanisource:BG 14.26|BG 14.26]])  
:([[Vanisource:BG 14.26 (1972)|BG 14.26]])  

Kete ti e ba ti di alainibawon olufokansin ti Olorun lesekese ni e ma te siwaju lori ipo awon ohun elo. Brahma-bhūyāya kalpate. E duro sinu ipo ti emi. Ati ti e ba si ku sinu ipo ti emi, e o si lo si ijoba orun.

<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 18:56, 14 October 2018

Press Conference -- April 18, 1974, Hyderabad

Alejo: Kini igbeyin ilepa isokan Olorun yi?

Prabhupada: Beeni, igbeyin ilepa re, ni.... Rara. Mo le so pe. Igbeyin ilepa re ni, pe lati mo iyato laarin emi ati ohun elo. Bi ile-aye ohun elo se wa, aye-orun na si wa nibe. Paras tasmāt tu bhāvaḥ anyaḥ avyaktaḥ avyaktāt sanātanaḥ (BG 8.20). Aye orun je ailopin. Ibugbe ni ile aye ohun elo. Awa je emi-okan. Awa fun ayeraye. Nitorina owo wa ni lati pada si ijoba Orun. ki se ka wa ninu aye ohun elo ki a si ma yi ara pada lati buburu si buru tabi buru si buburu. Iyen ki s'owo wa. Iyen je arun. Ilera wa ni lati gbadun aye ti olopin Yad gatvā na nivartante tad dhāma paramaṁ mama (BG 15.6) S'eri, igbesi aye eniyan ye ki o wa nilo fun lati de ipo ainibawon aye wa - ki se lati gba ara ohun elo pupo si ti a tun ni lati yi pada. Eleyi ni ero aye.

Alejo (2): Se asepe na see se ni igbesi aye kan?

Prabhupada: Beeni. lesekese gan, ti e ba gba. Olorun so wipe

sarva-dharmān parityajya
mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja
ahaṁ tvāṁ sarva-pāpebhyo
mokṣayiṣyāmi mā śucaḥ
(BG 18.66)

A nyi ara pada nitori akoto awon ise elese. sugbon ti e ba jowo fun Olorun at ki e gba isokan Olorun, lesekese ni e ma wa sori ipo ti emi.

māṁ ca yo 'vyabhicāreṇa
bhakti-yogena sevate
sa guṇān samatītyaitān
brahma-bhūyāya kalpate
(BG 14.26)