YO/Prabhupada 0126 - Lati je ki inu Oluko mi dunsi: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0126 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1973 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0023: VideoLocalizer - changed YouTube player to show hard-coded subtitles version)
 
Line 5: Line 5:
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]
[[Category:YO-Quotes - in India, Delhi]]
[[Category:YO-Quotes - in India, Delhi]]
[[Category:YO-Quotes - in India]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0125 - Awujo eyan nibi ti baje|0125|YO/Prabhupada 0127 - Bi awon eyan se ba ajo wa je pelu iwa iranu|0127}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 14: Line 18:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|vzvsim3yz9A|Only For the Satisfaction of My Spiritual Master - Prabhupāda 0126}}
{{youtube_right|vzMpw5CpW0s|Lati je ki inu Oluko mi dunsi - Prabhupāda 0126}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/731103BG.DEL_clip.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/731103BG.DEL_clip.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->



Latest revision as of 19:00, 14 October 2018



Lecture on BG 4.18 -- Delhi, November 3, 1973

Elesin Obirin: Esowipe tawa ban sen nkan, agbudo se idanwo lati mo boya nkanna ma fun Krsna ni itelorun. Kini idanwo na?

Prabhupāda: Toba fun Oluko ni'dunnu, elemope inu Krsna na dunsi. Olorin to salaaye oroyi taan ko lojojumo. Yasya prasādād bhagavat-prasādo yasyāprasādān na gatiḥ kuto 'pi. Ti inu Oluko ba dun, inu Krsna ti dun. Idanwo to waniyen. Ti inure o ba dun, ko s'ona mi.

Ko le ati mo. kasowipe ninu ile-ise, oga yin ni Olori ẹka ile iṣẹ tewa teba sise to mu inu Oga yin dun, O daju pe eti se nkan to maje ki inu Oludari dunsi. Kosi le rara. Oga yin ni asoju Krsna, oyeke se oun toma mu inu re dun. Yasya prasādād bhagavat-prasādo yasya. Nitorina agbudo gba itoni Oluko Caitanya-caritāmṛta ti sofun wa wipe Krsna lonwa ninu irisi Oluko. Guru-kṛṣṇa-kṛpāya. Guru-kṛṣṇa-kṛpāya. guru-kṛpā, Ore-ofe guru ni Ore-ofe Krsna. Teba se oun tomamu inu awon mejeji dun, Ona masi fun yin. Guru-kṛṣṇa-kṛpāya pāya bhakti-latā-bīja (CC Madhya 19.151). Nigbana ni ise ifarafun Oluwa tanse mani ilosiwaju Koseni tosi fojusi oroyi ninu Gurvaṣṭaka? Yasya prasādād bhagavat-prasādo yasyāprasādān na gatiḥ kuto 'pi.

Gege bi egbe wayi, mosi daale lati je ki inu Oluko mi dunsi. Caitanya Mahāprabhu feki egbe wayi tanka ni gbogbo agbaye Osi ran awon egbe mi ninu ajo wa, Konsepe o ran wa lo nikan, O si ran wan losi awon Ilu Geesi, sugbon bakanna, kori ise na se. Wansi pe ko pada. wansi ronu pe, " Ejeki emina gbiyanju bimose daagba bayi". Lati jeki inu Oluko mi dun ni anfaani pere timoni eyinna ti ranmilowo. Atini ilosiwaju gan. iyen ni yasya prasādād bhagavat-prasādaḥ. taba sise nitootọ fun oluko wa, ikan toma mu inu Krsna dun niyen, lehin na Krsna asi ranwalowo ati ni ilosiwaju.