YO/Prabhupada 0223 - Agbudo ni ile-eko lati le fun gbogbo agbaye l'eko: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0223 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1977 Category:YO-Quotes - Co...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 7: Line 7:
[[Category:YO-Quotes - in India, Bombay]]
[[Category:YO-Quotes - in India, Bombay]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0222 - Ema gbowole ninu eto lati fun egbe wa ni ilosiwaju|0222|YO/Prabhupada 0224 - E ma ko ile giga lori ipile tio da|0224}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 15: Line 18:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|t2_pDR9dRVg|This Institution Must be There for Educating the Whole Human Society - Prabhupāda 0223}}
{{youtube_right|t2_pDR9dRVg|Agbudo ni ile-eko lati le fun gbogbo agbaye l'eko<br />- Prabhupāda 0223}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/770415R1-BOM_clip2.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/770415R1-BOM_clip2.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 31: Line 34:
Mr. Rajda: ko le si oro atako.  
Mr. Rajda: ko le si oro atako.  


Prabhupāda: gbogbo eyan lo gba Iwe mimo Bhagavad-gītā. Bi mo se gbo na pe nigbati awon Olopa wa mu Morarji O so fun wan pe " e duro e je kin ka iwe mimo Bhagavad-gītā mi tan" Mo ri bayi ninu iwe irohin  
Prabhupāda: gbogbo eyan lo gba Iwe mimo Bhagavad-gītā. Bi mo se gbo na pe nigbati awon Olopa wa mu Morarji O so fun wan pe " e duro e je kin ka iwe mimo Bhagavad-gītā mi tan" Mo ri bayi ninu iwe irohin.


Mr. Rajda: Beeni, O so be.  
Mr. Rajda: Beeni, O so be.  
Line 37: Line 40:
Prabhupāda: Elesin iwe mimo Bhagavad-gītā lo je, ati awon eyan to po na Gege na kilode to ye ka fun gbogbo aye ni iwaasu yi?  
Prabhupāda: Elesin iwe mimo Bhagavad-gītā lo je, ati awon eyan to po na Gege na kilode to ye ka fun gbogbo aye ni iwaasu yi?  


Mr. Rajda: Lojojumo, o ma ji ni ago meta-abo laaro asi gba aadura, asi ka iwe mimo Bhagavad-gītā gbogbo eleyi ma gba wakati meta, lehin l'aago mesan asi lo si we. A de pade..  
Mr. Rajda: Lojojumo, o ma ji ni ago meta-abo laaro asi gba aadura, asi ka iwe mimo Bhagavad-gītā gbogbo eleyi ma gba wakati meta, lehin l'aago mesan asi lo si we. A de pade...


Prabhupāda: Awon Omo Orile-ede geesi yi na, wan man ji ni ago meta abo, wan si se eto iwe mimo Bhagavad-gītā titi di ago mesan aabo Wan o ni ise imi Se ti ri be na. L'ojojumo ni wan se bayi, gbogobo wan Lati ago meta abo titi di ago mesan aabo, ise iwe mimo Bhagavad-gītā lon se  
Prabhupāda: Awon Omo Orile-ede geesi yi na, wan man ji ni ago meta abo, wan si se eto iwe mimo Bhagavad-gītā titi di ago mesan aabo Wan o ni ise imi Se ti ri be na. L'ojojumo ni wan se bayi, gbogobo wan Lati ago meta abo titi di ago mesan aabo, ise iwe mimo Bhagavad-gītā lon se.


Mr. Rajda: Iyanu ni eyi je.  
Mr. Rajda: Iyanu ni eyi je.  


Prabhupāda: Awa de ni awon iwe to po ta ba fe soro lori ila kan tathā dehāntara-prāptiḥ ([[Vanisource:BG 2.13|BG 2.13]]), ninu iwe mimo na, o le gba ju ijo kan lo. Mr. Rajda: Emi na ri be Prabhupāda: niisin ti eyi ba je ooto, tathā dehāntara-prāptiḥ and na hanyate hanyamāne śarīre ([[Vanisource:BG 2.20|BG 2.20]]), kilode tan fin se gbogbo eleyi? Iwe mimo Bhagavad-gītā. Na jāyate na mriyate vā kadācin na hanyate hanyamāne śarīre ([[Vanisource:BG 2.20|BG 2.20]]). Nigbana ti iku ba pa ara mi, ma si lo.... awon elesin wa wan si lo lati ile si ile, wan ta awon iwe wa gege na awan se eto egbe wa o si ijoba kan kan to ranmi lowo, tabi eyan Esi si wa ni ile-ifowopamọ America, aduro ajeji paṣipaarọ ti mon mu wa pelu ilera mi ti o da mon sin se ise fun wakati merin ni ale. wan sin ranmi lowo Se ri pe awan lan se ise wa fun ara wa. Se ko ye ke wa si odoo wa? To ba je pe akeko to se pataki iwe mimo Bhagavad-gītā ni eyin je, se ko ye ke wa, ka sowopo? And harāv abhaktasya kuto mahad-guṇā manorathenāsati dhāvato... ([[Vanisource:SB 5.18.12|SB 5.18.12]]). ko si be sele ya awujo awon eyan si Olóòótọ pelu ọna-iṣofin nikan. Ko le se se rara E gbagbe e. Ko se se Harāv abhaktasya kuto.... Yasyāsti bhaktir bhagavaty akiñcanā sarvaiḥ... Ti eyin, tabi eyan ba di iranse Oluwa nigbayen ni gbogbo amuye to dara ma wa harāv abhaktasya kuto mahad sugbon ti eyan na o ban se iranse Oluwa Isekuse la ma sele, pelu gbogbo Ijoba giga ton ni Ni iwe-irohin teeni, mo si ka pe "arakurin yi, ati iyen, wan si ti le wan lo" Kilode? Harāv abhaktasya kuto Kini iwulo pe eyan di olori ti eyan na o ban se elesin Oluwa (ede Hindi) Eyan to l'ogbon ni eyin je, nitorina mo sin gbiyanju ati fun yin ni èrò to daa te ba de ti awan èrò ti mo ti fun yin si waju.. asiri ko lo je. Gbogbo wa ni lati gbiyanju. Agbudo da ile-akeko to ma s'eto ba sele fun agbaye ni eko to da E ma ronu eye awon eyan to wa. ko ba je kekere. Eyen o se pataki. Sugbon egudo so koko oro
Prabhupāda: Awa de ni awon iwe to po ta ba fe soro lori ila kan tathā dehāntara-prāptiḥ ([[Vanisource:BG 2.13 (1972)|BG 2.13]]), ninu iwe mimo na, o le gba ju ijo kan lo.  
 
Mr. Rajda: Emi na ri be  
 
Prabhupāda: niisin ti eyi ba je ooto, tathā dehāntara-prāptiḥ and na hanyate hanyamāne śarīre ([[Vanisource:BG 2.20 (1972)|BG 2.20]]), kilode tan fin se gbogbo eleyi? Iwe mimo Bhagavad-gītā. Na jāyate na mriyate vā kadācin na hanyate hanyamāne śarīre ([[Vanisource:BG 2.20 (1972)|BG 2.20]]). Nigbana ti iku ba pa ara mi, ma si lo.... awon elesin wa wan si lo lati ile si ile, wan ta awon iwe wa gege na awan se eto egbe wa o si ijoba kan kan to ranmi lowo, tabi eyan Esi si wa ni ile-ifowopamọ America, aduro ajeji paṣipaarọ ti mon mu wa pelu ilera mi ti o da mon sin se ise fun wakati merin ni ale. wan sin ranmi lowo Se ri pe awan lan se ise wa fun ara wa. Se ko ye ke wa si odoo wa? To ba je pe akeko to se pataki iwe mimo Bhagavad-gītā ni eyin je, se ko ye ke wa, ka sowopo? And harāv abhaktasya kuto mahad-guṇā manorathenāsati dhāvato... ([[Vanisource:SB 5.18.12|SB 5.18.12]]). ko si be sele ya awujo awon eyan si Olóòótọ pelu ọna-iṣofin nikan. Ko le se se rara E gbagbe e. Ko se se Harāv abhaktasya kuto.... Yasyāsti bhaktir bhagavaty akiñcanā sarvaiḥ... Ti eyin, tabi eyan ba di iranse Oluwa nigbayen ni gbogbo amuye to dara ma wa harāv abhaktasya kuto mahad sugbon ti eyan na o ban se iranse Oluwa Isekuse la ma sele, pelu gbogbo Ijoba giga ton ni Ni iwe-irohin teeni, mo si ka pe "arakurin yi, ati iyen, wan si ti le wan lo" Kilode? Harāv abhaktasya kuto Kini iwulo pe eyan di olori ti eyan na o ban se elesin Oluwa (ede Hindi) Eyan to l'ogbon ni eyin je, nitorina mo sin gbiyanju ati fun yin ni èrò to daa te ba de ti awan èrò ti mo ti fun yin si waju.. asiri ko lo je. Gbogbo wa ni lati gbiyanju. Agbudo da ile-akeko to ma s'eto ba sele fun agbaye ni eko to da E ma ronu eye awon eyan to wa. ko ba je kekere. Eyen o se pataki. Sugbon egudo so koko oro.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 23:38, 13 June 2018



Room Conversation with Ratan Singh Rajda M.P. "Nationalism and Cheating" -- April 15, 1977, Bombay

Prabhupāda: ki l'atako?

Mr. Rajda: ko le si oro atako.

Prabhupāda: gbogbo eyan lo gba Iwe mimo Bhagavad-gītā. Bi mo se gbo na pe nigbati awon Olopa wa mu Morarji O so fun wan pe " e duro e je kin ka iwe mimo Bhagavad-gītā mi tan" Mo ri bayi ninu iwe irohin.

Mr. Rajda: Beeni, O so be.

Prabhupāda: Elesin iwe mimo Bhagavad-gītā lo je, ati awon eyan to po na Gege na kilode to ye ka fun gbogbo aye ni iwaasu yi?

Mr. Rajda: Lojojumo, o ma ji ni ago meta-abo laaro asi gba aadura, asi ka iwe mimo Bhagavad-gītā gbogbo eleyi ma gba wakati meta, lehin l'aago mesan asi lo si we. A de pade...

Prabhupāda: Awon Omo Orile-ede geesi yi na, wan man ji ni ago meta abo, wan si se eto iwe mimo Bhagavad-gītā titi di ago mesan aabo Wan o ni ise imi Se ti ri be na. L'ojojumo ni wan se bayi, gbogobo wan Lati ago meta abo titi di ago mesan aabo, ise iwe mimo Bhagavad-gītā lon se.

Mr. Rajda: Iyanu ni eyi je.

Prabhupāda: Awa de ni awon iwe to po ta ba fe soro lori ila kan tathā dehāntara-prāptiḥ (BG 2.13), ninu iwe mimo na, o le gba ju ijo kan lo.

Mr. Rajda: Emi na ri be

Prabhupāda: niisin ti eyi ba je ooto, tathā dehāntara-prāptiḥ and na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20), kilode tan fin se gbogbo eleyi? Iwe mimo Bhagavad-gītā. Na jāyate na mriyate vā kadācin na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20). Nigbana ti iku ba pa ara mi, ma si lo.... awon elesin wa wan si lo lati ile si ile, wan ta awon iwe wa gege na awan se eto egbe wa o si ijoba kan kan to ranmi lowo, tabi eyan Esi si wa ni ile-ifowopamọ America, aduro ajeji paṣipaarọ ti mon mu wa pelu ilera mi ti o da mon sin se ise fun wakati merin ni ale. wan sin ranmi lowo Se ri pe awan lan se ise wa fun ara wa. Se ko ye ke wa si odoo wa? To ba je pe akeko to se pataki iwe mimo Bhagavad-gītā ni eyin je, se ko ye ke wa, ka sowopo? And harāv abhaktasya kuto mahad-guṇā manorathenāsati dhāvato... (SB 5.18.12). ko si be sele ya awujo awon eyan si Olóòótọ pelu ọna-iṣofin nikan. Ko le se se rara E gbagbe e. Ko se se Harāv abhaktasya kuto.... Yasyāsti bhaktir bhagavaty akiñcanā sarvaiḥ... Ti eyin, tabi eyan ba di iranse Oluwa nigbayen ni gbogbo amuye to dara ma wa harāv abhaktasya kuto mahad sugbon ti eyan na o ban se iranse Oluwa Isekuse la ma sele, pelu gbogbo Ijoba giga ton ni Ni iwe-irohin teeni, mo si ka pe "arakurin yi, ati iyen, wan si ti le wan lo" Kilode? Harāv abhaktasya kuto Kini iwulo pe eyan di olori ti eyan na o ban se elesin Oluwa (ede Hindi) Eyan to l'ogbon ni eyin je, nitorina mo sin gbiyanju ati fun yin ni èrò to daa te ba de ti awan èrò ti mo ti fun yin si waju.. asiri ko lo je. Gbogbo wa ni lati gbiyanju. Agbudo da ile-akeko to ma s'eto ba sele fun agbaye ni eko to da E ma ronu eye awon eyan to wa. ko ba je kekere. Eyen o se pataki. Sugbon egudo so koko oro.