YO/Prabhupada 0235 - Guru tio daju tumosi eni ti ko le fun awon akeko re ni itosona to da: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0235 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1973 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0005 edit: add new navigation bars (prev/next))
 
Line 6: Line 6:
[[Category:YO-Quotes - in United Kingdom]]
[[Category:YO-Quotes - in United Kingdom]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0234 - Idayatọ to gaju ni lati di olufokansi Olorun|0234|YO/Prabhupada 0236 - Awon Brahmana, awon Sannyasi wanle toro je sugbon awon Kshatriya ati Vaishya won ogbudo se bee|0236}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 14: Line 17:

<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|Onop2_v4d6c|Unqualified Guru Means Who Does not Know How to Guide the Disciple - Prabhupāda 0235}}
{{youtube_right|Onop2_v4d6c|Guru tio daju tumosi eni ti ko le fun awon akeko re ni itosona to da - Prabhupāda 0235}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->

<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/730805BG.LON_clip4.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/730805BG.LON_clip4.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->

Line 26: Line 29:

<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
gurūn ahatvā. Ti Oluka na o ba jẹrisi.... itumo Oluko ti ko jẹrisi ni Oluko ni o le fun awon akeko re ni atọ́nà to ye wan ise Guru ni lati fun awon akeko re ni atọ́nà , gege na ti Guru na o le fun yin ni ilana eyan gbudo fi guru bayi si le. bi Jīva Gosvāmī se wi ni yen... Kārya-kāryam ajānataḥ. Ti guru na oba mo iyato laarin awon nkan ti awa o le se ati nkan to ye ka se, e paátì te ba paátì, e le wa Guru to da ju Eyan o le fi ku pa Guru, sugbon e le paátì. Nkan ti iwe shastea so ni yen Gege na guru ni Bhīṣmadeva ati Droṇācārya je sugbon Krsna si so fun Arjuna.. pe, " botilejepe guru ni wan je, paa wan ti Kārya-kāryam ajānataḥ. Alai ni oye ni wan je Bhīṣmadeva, ni ife ipo re.. O si mo gbogbo nkan lori awon Pandava alainibaba ati iya lon je oun na lo si to ju wan lati kekere o si ni ife to po fun wan igbati wa n si le wan jade, Bhīṣmadeva, si sun ekun awon okurin marun wonyi, okan wan si da, olooto ni wan si je Arjuna ati Bhima jagunjagun alagbara ni wan, Orisa oloore ni Iyawo wan Drauadi Olorun Krsna si je ore taya tay si wan Sugbonn wan sin jiya. O si sun ekun. O si ni ife wan gan Nitorina Arjuna ronu bawo ni mo sele fi iku pa Bhisma? Sugbon agbudo se ise wa Krsna si so wi pe, O gbudo fi iku pa, nitoripe O ti tele ẹgbẹ keeji lo O ti gbagbe ise re. bibeko o ye ko wa si odo ti yin Nitorina kole je guru si E mo O gbudo fi iku pa Bi oun na se tele ẹgbẹ keeji, ko si nkan to baje to ba fi iku pa Gege bi Dronacarya. O ye mi pe awan eyan pataki ni awon eyan yi je, mo de mo pe ife wan lati inu okan wa loti wa Sugbon wan ti tele egbe kee ji lo, nitori awọn ohun elo ti aye yi Bhisma si ronu pe " Owo Duryodhana ni mo fin to ju ara mi" Duryodhana lon toju mi, ew si ti ba ni isin tin ba lo si egbe keeji, alaimoore ni awan ma pe mi O si ti pe ton toju mi ni isin, lasiko ewu ti mo ba lo si egbe keeji, sugbon Ko ronu pe, Durodhana ton toju re, àbùdá awon Pandava ti Duryodhan ti fi agidi gba lon lo. Sugbon o si mo wi pe, ko seni to le fi iku pa Arjuna nitoripe Krsna wan be pelu re gege na nitori nkan ti Duryodhana ti se fun mi mo gbudo s'ope fun Nkankanna ni pelu Droncarya. Wan si toju re na
Gurūn ahatvā. Ti Oluka na o ba jẹrisi.... itumo Oluko ti ko jẹrisi ni Oluko ni o le fun awon akeko re ni atọ́nà to ye wan ise Guru ni lati fun awon akeko re ni atọ́nà , gege na ti Guru na o le fun yin ni ilana eyan gbudo fi guru bayi si le. bi Jīva Gosvāmī se wi ni yen... Kārya-kāryam ajānataḥ. Ti guru na oba mo iyato laarin awon nkan ti awa o le se ati nkan to ye ka se, e paátì te ba paátì, e le wa Guru to da ju Eyan o le fi ku pa Guru, sugbon e le paátì. Nkan ti iwe shastea so ni yen Gege na guru ni Bhīṣmadeva ati Droṇācārya je sugbon Krsna si so fun Arjuna.. pe, " botilejepe guru ni wan je, paa wan ti Kārya-kāryam ajānataḥ. Alai ni oye ni wan je Bhīṣmadeva, ni ife ipo re.. O si mo gbogbo nkan lori awon Pandava alainibaba ati iya lon je oun na lo si to ju wan lati kekere o si ni ife to po fun wan igbati wa n si le wan jade, Bhīṣmadeva, si sun ekun awon okurin marun wonyi, okan wan si da, olooto ni wan si je Arjuna ati Bhima jagunjagun alagbara ni wan, Orisa oloore ni Iyawo wan Drauadi Olorun Krsna si je ore taya tay si wan Sugbonn wan sin jiya. O si sun ekun. O si ni ife wan gan Nitorina Arjuna ronu bawo ni mo sele fi iku pa Bhisma? Sugbon agbudo se ise wa Krsna si so wi pe, O gbudo fi iku pa, nitoripe O ti tele ẹgbẹ keeji lo O ti gbagbe ise re. bibeko o ye ko wa si odo ti yin Nitorina kole je guru si E mo O gbudo fi iku pa Bi oun na se tele ẹgbẹ keeji, ko si nkan to baje to ba fi iku pa Gege bi Dronacarya. O ye mi pe awan eyan pataki ni awon eyan yi je, mo de mo pe ife wan lati inu okan wa loti wa Sugbon wan ti tele egbe kee ji lo, nitori awọn ohun elo ti aye yi Bhisma si ronu pe " Owo Duryodhana ni mo fin to ju ara mi" Duryodhana lon toju mi, ew si ti ba ni isin tin ba lo si egbe keeji, alaimoore ni awan ma pe mi O si ti pe ton toju mi ni isin, lasiko ewu ti mo ba lo si egbe keeji, sugbon Ko ronu pe, Durodhana ton toju re, àbùdá awon Pandava ti Duryodhan ti fi agidi gba lon lo. Sugbon o si mo wi pe, ko seni to le fi iku pa Arjuna nitoripe Krsna wan be pelu re gege na nitori nkan ti Duryodhana ti se fun mi mo gbudo s'ope fun Nkankanna ni pelu Droncarya. Wan si toju re na.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 11:50, 21 September 2017

Lecture on BG 2.4-5 -- London, August 5, 1973