YO/Prabhupada 0237 - Awa leni asepo pelu Krishna taba korin oruko re, Hare Krishna: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0237 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1973 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 6: Line 6:
[[Category:YO-Quotes - in United Kingdom]]
[[Category:YO-Quotes - in United Kingdom]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0236 - Awon Brahmana, awon Sannyasi wanle toro je sugbon awon Kshatriya ati Vaishya won ogbudo se bee|0236|YO/Prabhupada 0238 - Olorun dara, Oun lo daju|0238}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 14: Line 17:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|GrOKlTvHta8|We Become in Touch with Kṛṣṇa by Chanting His Name, Hare Kṛṣṇa - Prabhupāda 0237}}
{{youtube_right|GrOKlTvHta8|Awa leni asepo pelu Krishna taba korin oruko re, Hare Krishna - Prabhupāda 0237}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/730804BG.LON_clip1.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/730804BG.LON_clip1.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 26: Line 29:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Pradyumna: Itumo - ọmọ Pṛthā, ma si se iranu, ewo ju bayi lo dide ko si ni ìgboyà. Ewo to je eyan to le ba awon Ota re wi  
Pradyumna: Itumo - ọmọ Pṛthā, ma si se iranu, ewo ju bayi lo dide ko si ni ìgboyà. Ewo to je eyan to le ba awon Ota re wi.


Prabhupāda: gege na Bhagavān, Kṛṣṇa, si ba Arjuna soro. kśūdraṁ hṛdaya-daurbalyam. Ti eyan to je Ksatriya ko le so wipe " Mi o le pa awon ebi mi, mo fe gbe ohun ijagun mi si le ailera ni yen je. Ki lo de to fin se gbogbo iranu yi?" Kśūdraṁ hṛdaya-daurbalyam. ti eyan ba fi ise re lle gege bi ksatriya ailera okan lon daamu eyan na. Iru oro bayi ko ni itumo Klaibyaṁ ma sma gamaḥ pārtha naitat tvayy upapadyate. kini awon eyan ma so? gege bo se je ore si mi. fi gbogbo ailera okan re sile ko si ni ìgboyà, dide. uttiṣṭha, se ri bi Krsna sen ti aja lati ja awon eyan o si ni opolo, wan si bu Krsna pe " kilode ton ti Arjuna ati Ja" okunrin jeje ni Arjuan, kilode ti krsna fe ko ja nkan ti awn pe ni jaḍa-darśana ni yen. itumo jaḍa-darśana ni iwoye t'aye Nitorina iwe sastra so wi pe ataḥ śrī-kṛṣṇa-nāmādi na bhaved grāhyam indriyaiḥ ([[Vanisource:CC Madhya 17.136|CC Madhya 17.136]]). Śrī-kṛṣṇa-nāmādi. ti eyan ba korin oruko Krsna oma sumo ibẹrẹ asopọ wa pelu Krsna ni yen. Namadi sastra so wi pe, ataḥ śrī-kṛṣṇa-nāmādi. ibere ni itumo Ādi.  
Prabhupāda: Gege na Bhagavān, Kṛṣṇa, si ba Arjuna soro. kśūdraṁ hṛdaya-daurbalyam. Ti eyan to je Ksatriya ko le so wipe " Mi o le pa awon ebi mi, mo fe gbe ohun ijagun mi si le ailera ni yen je. Ki lo de to fin se gbogbo iranu yi?" Kśūdraṁ hṛdaya-daurbalyam. ti eyan ba fi ise re lle gege bi ksatriya ailera okan lon daamu eyan na. Iru oro bayi ko ni itumo Klaibyaṁ ma sma gamaḥ pārtha naitat tvayy upapadyate. kini awon eyan ma so? gege bo se je ore si mi. fi gbogbo ailera okan re sile ko si ni ìgboyà, dide. uttiṣṭha, se ri bi Krsna sen ti aja lati ja awon eyan o si ni opolo, wan si bu Krsna pe " kilode ton ti Arjuna ati Ja" okunrin jeje ni Arjuan, kilode ti krsna fe ko ja nkan ti awn pe ni jaḍa-darśana ni yen. itumo jaḍa-darśana ni iwoye t'aye Nitorina iwe sastra so wi pe ataḥ śrī-kṛṣṇa-nāmādi na bhaved grāhyam indriyaiḥ ([[Vanisource:CC Madhya 17.136|CC Madhya 17.136]]). Śrī-kṛṣṇa-nāmādi. ti eyan ba korin oruko Krsna oma sumo ibẹrẹ asopọ wa pelu Krsna ni yen. Namadi sastra so wi pe, ataḥ śrī-kṛṣṇa-nāmādi. ibere ni itumo Ādi.  


Awa ooni asopo pelu Krsna Sugbon ta be beere sini korin Hare Krsna, lesekese lama ni aye lati ni asepo pelu Krsna lesekese ko lo ma de, eyan gbudo gba eko na sugbon awon eyan ton ti ni ilosiwaju ninu eto yi, wan le ni asepo pelu Krsna lesekese Oruko ni itumo Nāma Oruko lasan ko ni Krsna je. gege bi śravanaṁ kīrtanam ([[Vanisource:SB 7.5.23|SB 7.5.23]]). śravanaṁ kīrtanam, ayin krsna logo O de ni irisi oruko ni itumo nama, irisi ni itumo form Nāma, rūpa... akoko idaraya ni itumo Līlā; guṇa je àmúyẹ; awon elesin re... Ataḥ śrī-kṛṣṇa-nāmādi na bhaved ([[Vanisource:CC Madhya 17.136|CC Madhya 17.136]]). Na bhaved grāhyam indriyaiḥ. pelu ogbon lasan ko le ye wa.. awan sin gbo pelu eti wa oruko krsna sugbon ti awa o ba so eti wa di mimo ba sen gbo si eti wa ma di mimo. agbudo se iranlowo Agbudo yago fun awọn ẹṣẹ itumo iranlowo ni yen,awọn ẹṣẹ mewa gege awa o si se iranlowo fun eto yiya si mimo tin ma fe tan ina, o se dandan pe kin mu igi to gbe gan ko si ni pe to ma gbin na gege na, ti awa ba korin oma ranwa lowo sugbon taba yago fun awon ese na, ale ya si mimo kiakia
Awa ooni asopo pelu Krsna Sugbon ta be beere sini korin Hare Krsna, lesekese lama ni aye lati ni asepo pelu Krsna lesekese ko lo ma de, eyan gbudo gba eko na sugbon awon eyan ton ti ni ilosiwaju ninu eto yi, wan le ni asepo pelu Krsna lesekese Oruko ni itumo Nāma Oruko lasan ko ni Krsna je. gege bi śravanaṁ kīrtanam ([[Vanisource:SB 7.5.23-24|SB 7.5.23]]). śravanaṁ kīrtanam, ayin krsna logo O de ni irisi oruko ni itumo nama, irisi ni itumo form Nāma, rūpa... akoko idaraya ni itumo Līlā; guṇa je àmúyẹ; awon elesin re... Ataḥ śrī-kṛṣṇa-nāmādi na bhaved ([[Vanisource:CC Madhya 17.136|CC Madhya 17.136]]). Na bhaved grāhyam indriyaiḥ. pelu ogbon lasan ko le ye wa.. awan sin gbo pelu eti wa oruko krsna sugbon ti awa o ba so eti wa di mimo ba sen gbo si eti wa ma di mimo. agbudo se iranlowo Agbudo yago fun awọn ẹṣẹ itumo iranlowo ni yen,awọn ẹṣẹ mewa gege awa o si se iranlowo fun eto yiya si mimo tin ma fe tan ina, o se dandan pe kin mu igi to gbe gan ko si ni pe to ma gbin na gege na, ti awa ba korin oma ranwa lowo sugbon taba yago fun awon ese na, ale ya si mimo kiakia.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 23:40, 13 June 2018



Lecture on BG 2.3 -- London, August 4, 1973

Pradyumna: Itumo - ọmọ Pṛthā, ma si se iranu, ewo ju bayi lo dide ko si ni ìgboyà. Ewo to je eyan to le ba awon Ota re wi.

Prabhupāda: Gege na Bhagavān, Kṛṣṇa, si ba Arjuna soro. kśūdraṁ hṛdaya-daurbalyam. Ti eyan to je Ksatriya ko le so wipe " Mi o le pa awon ebi mi, mo fe gbe ohun ijagun mi si le ailera ni yen je. Ki lo de to fin se gbogbo iranu yi?" Kśūdraṁ hṛdaya-daurbalyam. ti eyan ba fi ise re lle gege bi ksatriya ailera okan lon daamu eyan na. Iru oro bayi ko ni itumo Klaibyaṁ ma sma gamaḥ pārtha naitat tvayy upapadyate. kini awon eyan ma so? gege bo se je ore si mi. fi gbogbo ailera okan re sile ko si ni ìgboyà, dide. uttiṣṭha, se ri bi Krsna sen ti aja lati ja awon eyan o si ni opolo, wan si bu Krsna pe " kilode ton ti Arjuna ati Ja" okunrin jeje ni Arjuan, kilode ti krsna fe ko ja nkan ti awn pe ni jaḍa-darśana ni yen. itumo jaḍa-darśana ni iwoye t'aye Nitorina iwe sastra so wi pe ataḥ śrī-kṛṣṇa-nāmādi na bhaved grāhyam indriyaiḥ (CC Madhya 17.136). Śrī-kṛṣṇa-nāmādi. ti eyan ba korin oruko Krsna oma sumo ibẹrẹ asopọ wa pelu Krsna ni yen. Namadi sastra so wi pe, ataḥ śrī-kṛṣṇa-nāmādi. ibere ni itumo Ādi.

Awa ooni asopo pelu Krsna Sugbon ta be beere sini korin Hare Krsna, lesekese lama ni aye lati ni asepo pelu Krsna lesekese ko lo ma de, eyan gbudo gba eko na sugbon awon eyan ton ti ni ilosiwaju ninu eto yi, wan le ni asepo pelu Krsna lesekese Oruko ni itumo Nāma Oruko lasan ko ni Krsna je. gege bi śravanaṁ kīrtanam (SB 7.5.23). śravanaṁ kīrtanam, ayin krsna logo O de ni irisi oruko ni itumo nama, irisi ni itumo form Nāma, rūpa... akoko idaraya ni itumo Līlā; guṇa je àmúyẹ; awon elesin re... Ataḥ śrī-kṛṣṇa-nāmādi na bhaved (CC Madhya 17.136). Na bhaved grāhyam indriyaiḥ. pelu ogbon lasan ko le ye wa.. awan sin gbo pelu eti wa oruko krsna sugbon ti awa o ba so eti wa di mimo ba sen gbo si eti wa ma di mimo. agbudo se iranlowo Agbudo yago fun awọn ẹṣẹ itumo iranlowo ni yen,awọn ẹṣẹ mewa gege awa o si se iranlowo fun eto yiya si mimo tin ma fe tan ina, o se dandan pe kin mu igi to gbe gan ko si ni pe to ma gbin na gege na, ti awa ba korin oma ranwa lowo sugbon taba yago fun awon ese na, ale ya si mimo kiakia.