YO/Prabhupada 0322 - The Body is Awarded by God According to Your Karma: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0322 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1973 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 7: Line 7:
[[Category:YO-Quotes - in USA, Los Angeles]]
[[Category:YO-Quotes - in USA, Los Angeles]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0321 - Always Connected with the Original Powerhouse|0321|YO/Prabhupada 0323 - Creating a Society of Swans, Not of Crows|0323}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 19: Line 22:

<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/731218SB.LA_clip.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/731218SB.LA_clip.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->

Line 35: Line 38:
:sa gunan samatityaitan
:sa gunan samatityaitan
:brahma-bhuyaya kalpate
:brahma-bhuyaya kalpate
:([[Vanisource:BG 14.26|BG 14.26]])
:([[Vanisource:BG 14.26 (1972)|BG 14.26]])

Idimu to wa ni gunamayi maya, pe awon ipo aye yi ti di wa mu. Idinmu to wa niyen. Sugbon teyan ba wa ninu ise ifarasi Olorun, Kole si ninu idimu nitoripe wan bi awon nkan se je. Gege bi mose je alejo ninu Ilu yi.. moti wa si'lu yi. Gege na ti man sowipe " Emi ni moni ilu yi," Isoro ma wa niyen. Sugobn tin ba mo wipe alejo nimi pe mo wa sibi, koni wahala kankan. Mole rin bi mose fe. Mole gba gbogbo iranlowo ti'lu Ameriaca. koni si wahala kankan. Gege na, awa ti wa sinnu ule aye bi awon alejo, sugbon tawa ba rowipe " Emi ni mo ni ile-aye aye, tabi awujo awon okurin, tabi awon rile-ede, aimokan niyen je.

Itunmo imoye Krsna yi niwipe afe fi ipaari si aimokan wanyi, lati je ki awon eyan logbon pe " KOn si nkan ninu aye yi to je temi. Olorun loni gbogbo nkan aye yi." Gege na, ilan ti Maharaja Yudisthira fe salaye ni yen Moti slaaye tele pe nitoripe awa ti wa ninu eto ahankara yi, " Ara mi nimo je, arti gbogbo nkan toni asepo pelu ara yi temi nani." Itanra eni niyen je, moha. Moha leleyi, aimokan. Janasya moho 'yam. Aimokan nitumo Moha. Aimokan niyen. Kini aimokan yi? Aham mameti: ([[Vanisource:SB 5.5.8|SB 5.5.8]]) " Emi lara mi, ati gbogbo nkna to ni asepo pelu are mi, temi nani." Moha niyen, aimokan. Oun loko lo ni ni ara yi, nitoripe Olorun lo fun l'ara to ni gege bi karma re seje. gege bi, oni-ile ase fun yin ni ile gege bese ma sonwo si. Eyin ko leni ile na. Oto oro niyen. teba son $500 ni osu kan, wan funyin ni ile to da. teba son $25 imi lema ri gba. gege na, awon ara orisiri tani Onikaluku ni ara to yato sokeji. Bi ile seji niyen. Gege na, ile loje nitoripa mon gbe ninu. Ara mi ko ni moje. Ilana Bhagavad-gita niyen. Dehino 'smin yatha dehe ([[Vanisource:BG 2.13|BG 2.13]]). Asmin dehe, dehi ni, oni-ile. Oni-ile. Eyan ni onile na je, eyan na ni eniton sowon fun ile na je. gege na, ile ni ara wa yi je. Emi mi lon gbe ninu e. Moti ya lo gege bi karma mi seje.
Itunmo imoye Krsna yi niwipe afe fi ipaari si aimokan wanyi, lati je ki awon eyan logbon pe " KOn si nkan ninu aye yi to je temi. Olorun loni gbogbo nkan aye yi." Gege na, ilan ti Maharaja Yudisthira fe salaye ni yen Moti slaaye tele pe nitoripe awa ti wa ninu eto ahankara yi, " Ara mi nimo je, arti gbogbo nkan toni asepo pelu ara yi temi nani." Itanra eni niyen je, moha. Moha leleyi, aimokan. Janasya moho 'yam. Aimokan nitumo Moha. Aimokan niyen. Kini aimokan yi? Aham mameti: ([[Vanisource:SB 5.5.8|SB 5.5.8]]) " Emi lara mi, ati gbogbo nkna to ni asepo pelu are mi, temi nani." Moha niyen, aimokan. Oun loko lo ni ni ara yi, nitoripe Olorun lo fun l'ara to ni gege bi karma re seje. gege bi, oni-ile ase fun yin ni ile gege bese ma sonwo si. Eyin ko leni ile na. Oto oro niyen. teba son $500 ni osu kan, wan funyin ni ile to da. teba son $25 imi lema ri gba. gege na, awon ara orisiri tani Onikaluku ni ara to yato sokeji. Bi ile seji niyen. Gege na, ile loje nitoripa mon gbe ninu. Ara mi ko ni moje. Ilana Bhagavad-gita niyen. Dehino 'smin yatha dehe ([[Vanisource:BG 2.13 (1972)|BG 2.13]]). Asmin dehe, dehi ni, oni-ile. Oni-ile. Eyan ni onile na je, eyan na ni eniton sowon fun ile na je. gege na, ile ni ara wa yi je. Emi mi lon gbe ninu e. Moti ya lo gege bi karma mi seje.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 23:49, 13 June 2018

Lecture on SB 1.15.40 -- Los Angeles, December 18, 1973

baba wa to gaju ti funwa, " America yin leleyi, India yin leleyi." Sugbon kosi nkan to je ti awon omo-ilu Anerica tabi India, Baba wa loke loni gbogbo e. Afi ton ba wa sori ironu bayi pe " Baba mi loke lo funmi lati gbadu, pe, baba mi loke loni.." Imoye Krsa niyen. Imoye Krsna niyen.

Awon ton ni imoye Krsna yi, wan mowipe "konsi nkankan to je temi. Isavasyam idam sarvam yat kinca (Iso mantra 1). loni gbogbo nkan. " Awon kokoro ganm Olorun lo niwan. Emi ko nimo niwan." Teyin b ale ronu bayi, eti ni ominiran niyen. Nkan ti Bhagavad-gita so niyen,

mam ca yo 'vyabhicarena
bhakti-yogena sevate
sa gunan samatityaitan
brahma-bhuyaya kalpate
(BG 14.26)

Idimu to wa ni gunamayi maya, pe awon ipo aye yi ti di wa mu. Idinmu to wa niyen. Sugbon teyan ba wa ninu ise ifarasi Olorun, Kole si ninu idimu nitoripe wan bi awon nkan se je. Gege bi mose je alejo ninu Ilu yi.. moti wa si'lu yi. Gege na ti man sowipe " Emi ni moni ilu yi," Isoro ma wa niyen. Sugobn tin ba mo wipe alejo nimi pe mo wa sibi, koni wahala kankan. Mole rin bi mose fe. Mole gba gbogbo iranlowo ti'lu Ameriaca. koni si wahala kankan. Gege na, awa ti wa sinnu ule aye bi awon alejo, sugbon tawa ba rowipe " Emi ni mo ni ile-aye aye, tabi awujo awon okurin, tabi awon rile-ede, aimokan niyen je.

Itunmo imoye Krsna yi niwipe afe fi ipaari si aimokan wanyi, lati je ki awon eyan logbon pe " KOn si nkan ninu aye yi to je temi. Olorun loni gbogbo nkan aye yi." Gege na, ilan ti Maharaja Yudisthira fe salaye ni yen Moti slaaye tele pe nitoripe awa ti wa ninu eto ahankara yi, " Ara mi nimo je, arti gbogbo nkan toni asepo pelu ara yi temi nani." Itanra eni niyen je, moha. Moha leleyi, aimokan. Janasya moho 'yam. Aimokan nitumo Moha. Aimokan niyen. Kini aimokan yi? Aham mameti: (SB 5.5.8) " Emi lara mi, ati gbogbo nkna to ni asepo pelu are mi, temi nani." Moha niyen, aimokan. Oun loko lo ni ni ara yi, nitoripe Olorun lo fun l'ara to ni gege bi karma re seje. gege bi, oni-ile ase fun yin ni ile gege bese ma sonwo si. Eyin ko leni ile na. Oto oro niyen. teba son $500 ni osu kan, wan funyin ni ile to da. teba son $25 imi lema ri gba. gege na, awon ara orisiri tani Onikaluku ni ara to yato sokeji. Bi ile seji niyen. Gege na, ile loje nitoripa mon gbe ninu. Ara mi ko ni moje. Ilana Bhagavad-gita niyen. Dehino 'smin yatha dehe (BG 2.13). Asmin dehe, dehi ni, oni-ile. Oni-ile. Eyan ni onile na je, eyan na ni eniton sowon fun ile na je. gege na, ile ni ara wa yi je. Emi mi lon gbe ninu e. Moti ya lo gege bi karma mi seje.