YO/Prabhupada 0344 - Srimad-Bhagavatam, Simply Dealing with Bhakti: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0344 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1974 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0005 edit: add new navigation bars (prev/next))
 
Line 7: Line 7:
[[Category:YO-Quotes - in India, Bombay]]
[[Category:YO-Quotes - in India, Bombay]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0343 - We are Trying to Educate the Mudhas|0343|YO/Prabhupada 0345 - Krishna is Sitting in Everyone's Heart|0345}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 19: Line 22:


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/741223SB.BOM_clip.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/741223SB.BOM_clip.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->



Latest revision as of 12:08, 21 September 2017



Lecture on SB 3.26.11-14 -- Bombay, December 23, 1974

Lehin igbati Vyasadeva ko awon iwe Vedam inu re o dun. O ko awon Veda merin, lehin na awon Purana - Itumo awon Purana ni awon iwe ton tele awon Vedas ati Vedanta-sutra, oro to kehin ninu imoye Veda, Vedanta-sutra. sugbon koni itelorun. Gege Oluko re Narada Muni si beere lowo re pe: Kilode to jepe inu re o dun lehin igba toti ko gbogbo awon iwe wanyi fun aawon eyan?" O sowipe, "Beeni Sa, nio mo nkan ti mo ko... Inu mi o dun. mio mo di na." Nigbana ni Nārada Muni si wipe," The dissatisfaction jẹ nitori rẹ ko apejuwe awọn akitiyan ti awọn adajọ ile- Oluwa. Nitorina ni inu re ose dun, o ti soro nipa awon nkan lasan, sugbon awon nkan gidi, oti salaaye. Nitorina ni ibanuje semu e. Nisin ya tun ko." pelu ilaa Oluko re Narada Muni, Vyasadeva, si fi awon oro gidi si Srimad- Bhagavatam. Śrīmad-bhāgavatam amalaṁ purāṇaṁ yad vaiṣṇavānāṁ priyam. Nitorina awon Vaisnava, wan pe Śrīmad-Bhāgavatam ni amalaṁ purāṇam. Itumo Amalaṁ purāṇam.... . Itumo Amala ni nkan tio ni alebu kankan. awon purana imi si wa ton soro nipa karma, jnana, yoga. Nitorina samalam lon je, pelu alebu ile- aye yi. Śrīmad-Bhāgavatam, ton soro nipa bhakti, amalam niyen. toni asepo pelu Olorun nitumo Bhakti, bhakta ati Bhagavan, bhakti ni ise na. Bhagavan ati bhakta wa, gege bi oga ati iranse. Ise ni ibasepo to wa laarin oga ati irasse.

Iwa tani niyen, Lati sise. sugbon nitoripe awa ti ni asepo pelu nkan aye yi, awa sin sise bi se ye. awon eyna wa ton fe sise fun ebi wa, awujo wa, orile-ede wa, fun agbaye, sugbon gbogbo ise yi ni alebu. Sugbon teba bereise yin ninu imoye Krsna, ise to gaju niyen. Gege na egbe imoye Krsna yi fe mu awon eyan wa sori ipo lati le sise.

Ese pupo.