YO/Prabhupada 0343 - We are Trying to Educate the Mudhas



Lecture on BG 3.27 -- Madras, January 1, 1976

Nigbai Krsna wa layeyi ofi han wa, pe ole ni idari logbogbo eyan, kode seni toni idari lori e. Isvara niyen. paramesvara. gbogbo wa le di isvara, gbogbo wa ledi Olorun. Sugbon Krsna ni Eledumare. Nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām (Kaṭha Upaniṣad 2.2.13) . Oyeka gbiyanju lati ni oye na, ko le a rara. Oludari kanna loti wa si wa ju bayi beeyan lasan. Sugbon awa o fe gba. Isoro to wa niyen. Avajānanti māṁ mūḍhā mānuṣīṁ tanum āśritam (BG 9.11). Ibanuje to wa niyen. Krsna sowipe " Mofe wa fi han eni to je Oludari to gaju, mosin huwa bi eyan lasan, ki gbogbo eyan ba le mo. mosi ti funn yin ni awon ilana ninu Bhagavad-gita, awon ode wanyi, kosi ye wan." Olorun wa n'be, awa ti funyin ni Oruko Olorun, Krsna, ile Olorun, Vrndavana, Oruko baba ati iya Olorun. Kilode lati wa Olorun na? Sugbon wa n o ni gba. awon ode wanyi o ni gba. Mudha. Wanti salaaye nipa wan pe mudha lonje. laaro yi awon oniroyin wa bami pe " Kini ide fun egbe yin?" Mosowipe , " lati fun awon mudha leeko, otan." ipinnu egbe imolye Krsna yi niwipe awa fe ko awon mudha wanyi. tani mudha na? Krsna ti salaaye. Na māṁ duṣkṛtino mūḍhāḥ prapadyante narādhamāḥ (BG 7.15). Kilode? Māyayāpahṛta-jñānāḥ. Maya ti yo opolo orire kuro? Āsuraṁ bhāvam āśritāḥ. Awa si ni idanwo kekere, gege bi awon onisayensi sele da awon nkan mo. Awa na o fi be logbon. Awa je ikan ninu awon mudha wanyi, sugbon a mo basele sedanwo yi.. Awa fe wa bi mudha kaba le gba ilana lowo Krsna. Imoye Krsna niyen. Awa o si sowipe awa la moju.

Rara. Caitnaya Mahaprabhu gan, si se bi mudha. Nigbato ba Prakāśānanda Sarasvatī soro...Māyāvādī sannyāsī loje. Caitanya Mahaprabhu sin korin ton jo. Awon sannyasi Mayavadi wanyi bere sini bu pe " sannyasi loje, kilode ton ba awon jo loju titi. Kile leyi?" Wansi seto ipade laarin Prakāśānanda Sarasvatī ati Caitanya Mahāprabhu. ninu ipade yo Caitanya Mahāprabhu si wa bi sannyasi to resile gan. gege na Prakāśānanda Sarasvatī si bere lowo re, " Edakun sa, sannyasi niyin. Lati ka awon iwe Vedanta ni ise teni, kilode teyin sen jo kakiri ten korin? Eyin o ka Vedanta." Caitanya Mahaprabhu sowipe, " Beeni Sa, otooro leso. Mon se bayi nitoripe Gurur Maharaja mi soswipe, mudha, ode nimi." Bawo? O sowipe guru more mūrkha dekhi' karila śāsana (CC Adi 7.71). Guru Maharaja ri pe ode nimi, osi kilo funmi." "Bawo lose kilo fun e? O sowipe " E wo yi ]kosi bosele ka Vedanta. Kolese se fun e. Mudha loje. Korin Hare Krsna."

Kini idi fun? Fun asiko ta wa yi nani, bawo ni awon mudha yi se fe ni oye nipa Vedanta? Ekorin Hare Krsna. Lehin na ema ni imoye>

harer nāma harer nāma harer nāmaiva kevalam
kalau nāsty eva nāsty eva nāsty eva gatir anyathā
(CC Adi 17.21)

Ninu asiko tawwayi awon eyan o le ka Vedanta, tolo tie ni asiko lati ka Vedanta? Gege na o da ka gba Vedanta gege bo Krsna se so, vedaiś ca sarvair aham eva vedyaḥ (BG 15.15).

śabdād anāvṛtti ni imoye Vedanta. Teyan ban korin śabda-brahma o le ni igbala. nkan ti awon sastra soniyen:

harer nāma harer nāma harer nāmaiva kevalam
kalau nāsty eva nāsty eva nāsty eva gatir anyathā
(CC Adi 17.21)

gege na teyan ba fe jade kuro ninu awon idinmu aye yi, janma-mṛtyu-jarā-vyādhi (BG 13.9) - awon isoro to wa niyen, gege bi sastra se so, gege bi awon mahajan se so, agbudo korin Hare Krsna maha mantra. Ise wa niyen.