YO/Prabhupada 0427 - Soul is Different from the Gross Body and the Subtle Body: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0427 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1972 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 6: Line 6:
[[Category:YO-Quotes - in United Kingdom]]

<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0426 - One Who is Learned, He Does Not Lament Either for the Living or for the Dead Body|0426|YO/Prabhupada 0428 - The Special Prerogative of the Human Being is to Understand - What I Am|0428}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->

<div class="center">
<div class="center">
Line 18: Line 21:

<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/720716BG.EDI_clip2.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/720716BG.EDI_clip2.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->

Line 26: Line 29:

<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
gege bi ilana Veda, apa eda merin lowa ninu awujo eyan. Cātur-varṇyaṁ mayā sṛṣṭaṁ guṇa-karma-vibhāgaśaḥ ([[Vanisource:BG 4.13|BG 4.13]]). Agbodo pin awujo eda eyan si apa merin wanyi. gege bi ara eda, apa merin lowa: Apa opolo, apa owo, apa ikun ati apa ese. Gbogbo e lo wulo. teba sife toju ara na, egbodo toju oriyin, owo yin, ikun yin at'ese na. Asepo. Eti gbo aimoye igba nipa awon isasoto ni orile-ede India: brāhmaṇa, kṣatriya, vaiśya, śūdra. Kon se nkan eke. Nkan adayeba loje. Ninu gbogbo awujo laye yi, India nikan ko, ninu awon orile-ede iimi, awon apa-okurn wanyi wa. Awon alakowe, awon onijoba, awon ton da nkan sile, awon ton sise. Ele pe ni oruko to yato, sugbon isasoto yi gbodo wa. Gege bi mose so fun yin, isasoto wa ninu ara mi - apa opolo, apa owo, apa ikun, apa ese. Gbogbo awon oba wa ninu apa owo lati le fun awon eyan ni idaabo. Beena teletele awon ksatriyas.. Eni ton toju awon olugbe lati alebu awon ota nitumo Ksatriya. Nkan ton pe ni ksatriya niyen. Beena koko ror wa niwipe Krsna ti sofun Arjuna wipe " Kilode tofe fi ise re sile? So rowipe awon aburo re, tabi baba agba l'apa keji ma ku leyin ogun na? Rara. Oto oror koniyen." Koko oror niwipe Krsna fe ko Arjuna wipe ayato si ara wa. gege bi gbogbo wa, ani aso to yato. Beena, awon emi ninu ara wa si yato si ara wa. Imoye Bhagavad-gita niyen. Koye awon eyan. Awon man rowipe ara won lonje. Sastra o feran iru ironu bayi.
gege bi ilana Veda, apa eda merin lowa ninu awujo eyan. Cātur-varṇyaṁ mayā sṛṣṭaṁ guṇa-karma-vibhāgaśaḥ ([[Vanisource:BG 4.13 (1972)|BG 4.13]]). Agbodo pin awujo eda eyan si apa merin wanyi. gege bi ara eda, apa merin lowa: Apa opolo, apa owo, apa ikun ati apa ese. Gbogbo e lo wulo. teba sife toju ara na, egbodo toju oriyin, owo yin, ikun yin at'ese na. Asepo. Eti gbo aimoye igba nipa awon isasoto ni orile-ede India: brāhmaṇa, kṣatriya, vaiśya, śūdra. Kon se nkan eke. Nkan adayeba loje. Ninu gbogbo awujo laye yi, India nikan ko, ninu awon orile-ede iimi, awon apa-okurn wanyi wa. Awon alakowe, awon onijoba, awon ton da nkan sile, awon ton sise. Ele pe ni oruko to yato, sugbon isasoto yi gbodo wa. Gege bi mose so fun yin, isasoto wa ninu ara mi - apa opolo, apa owo, apa ikun, apa ese. Gbogbo awon oba wa ninu apa owo lati le fun awon eyan ni idaabo. Beena teletele awon ksatriyas.. Eni ton toju awon olugbe lati alebu awon ota nitumo Ksatriya. Nkan ton pe ni ksatriya niyen. Beena koko ror wa niwipe Krsna ti sofun Arjuna wipe " Kilode tofe fi ise re sile? So rowipe awon aburo re, tabi baba agba l'apa keji ma ku leyin ogun na? Rara. Oto oror koniyen." Koko oror niwipe Krsna fe ko Arjuna wipe ayato si ara wa. gege bi gbogbo wa, ani aso to yato. Beena, awon emi ninu ara wa si yato si ara wa. Imoye Bhagavad-gita niyen. Koye awon eyan. Awon man rowipe ara won lonje. Sastra o feran iru ironu bayi.

:yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke
:yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke
Line 40: Line 43:
:tathā dehāntara-prāptir
:tathā dehāntara-prāptir
:dhīras tatra na muhyati
:dhīras tatra na muhyati
:([[Vanisource:BG 2.13|BG 2.13]])
:([[Vanisource:BG 2.13 (1972)|BG 2.13]])

Dehinaḥ... Asmin dehe, ninu ara yi, bi emi sewa, dehi... eni toje onile ninu ara na nitumo Dehi. Ara mi ko nimi. teba bere lowo mi, " Gege bi omode sen bere nigbami, " Kileleyi? A sowipe, " Ori mi leleyi." Beena teba bere lowo mi "ki leleyi?" Gbogbo eyan ma daun " Ori mi leleyi." Koseni toma sowipe, "Ori." Beena teba si bere nipa gbogbo apa ara, ema sowipe, " Ori mi, owo mi, ika mi, ese mi," sugbon nibo ni "emi" yi wa? "Temi" wa nitoripe "Emi" wa. Sugbon awa o mo nipa "emi". Amo nipa "temi". Aimokan leleyi. Beena gbogbo agbaye si rowipe ara wa laje. Apeer imi tele fun ni wipe, kasowipe baba mi ti ku. Nisin mon sukun, "Oh baba mi ti lo, baba mi ti lo." Sugbon teyan ba bere, " kilode ton sen sowipe baba re tilo? O wa nibi. Kilode ton sen sukun?" "Rara, rara, rara, ara rw leleyi. Ara re leleyi. Baba mi ti lo." Nitorina pelu isiro wa nisin, ara yin nikan ni mon ri, Ara mi leyin na ri, koseni to ri eda to wa ninu e. Lehin igba ti iku ba de " Oh baba mi ko, ara baba mi leleyi." Se ri bayi? Lehin iku lan man logbon. Taba wa laaye, aimokan lo diwa mu. Awujo aiye isin leleyi. gege bi awon eyan ton gba iwe aseduro lati gb'owo. Beena won gba owo yi lehin ton ba ku, eyin o le ri gba ninu aye yi. Nigbami ninu aye yi na. Beena nkan tin mon so niwipe fun asiko tawa laaye, awa o mo nkankan. Awa o mo "eni ti baba wa je, eni t'aburo wa je, eni timo je." Sugbon gbogbo wa lan rowipe, " Ara timon wo yi ni baba mi, ara yi ni omo mi, ara yi ni iyawo mi. Aimokan leleyi. Teba wo gbogbo agbaye yi, nigbaton ba wa laaye gbogbo won lon ma sowipe " Okurin geesi nimi," " Okuirn India nimi", "hindu nimi", "Musluman nimi." Sugbon teba bere, "niotoro se nkan to je niyen?" Nitoripe ara yi je Hindu, Musluman, tabi Onigbagbo, nitoripe won bi ara na sinu, awujo awon Hindu, Musluman, tabi won bi sinu orile-ede nitorina lasen sowwipe, "Olugbe India nimi," " Olugbe Europu nimi", "bayi bayi nimi ". sugbon t'ara na ba ku, nigbana a ma sowipe, " Rara, rara, eni to wa ninu ara na ti lo. Nkan to yato leleyi."

<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 23:57, 13 June 2018

Lecture on BG 2.11 -- Edinburgh, July 16, 1972

gege bi ilana Veda, apa eda merin lowa ninu awujo eyan. Cātur-varṇyaṁ mayā sṛṣṭaṁ guṇa-karma-vibhāgaśaḥ (BG 4.13). Agbodo pin awujo eda eyan si apa merin wanyi. gege bi ara eda, apa merin lowa: Apa opolo, apa owo, apa ikun ati apa ese. Gbogbo e lo wulo. teba sife toju ara na, egbodo toju oriyin, owo yin, ikun yin at'ese na. Asepo. Eti gbo aimoye igba nipa awon isasoto ni orile-ede India: brāhmaṇa, kṣatriya, vaiśya, śūdra. Kon se nkan eke. Nkan adayeba loje. Ninu gbogbo awujo laye yi, India nikan ko, ninu awon orile-ede iimi, awon apa-okurn wanyi wa. Awon alakowe, awon onijoba, awon ton da nkan sile, awon ton sise. Ele pe ni oruko to yato, sugbon isasoto yi gbodo wa. Gege bi mose so fun yin, isasoto wa ninu ara mi - apa opolo, apa owo, apa ikun, apa ese. Gbogbo awon oba wa ninu apa owo lati le fun awon eyan ni idaabo. Beena teletele awon ksatriyas.. Eni ton toju awon olugbe lati alebu awon ota nitumo Ksatriya. Nkan ton pe ni ksatriya niyen. Beena koko ror wa niwipe Krsna ti sofun Arjuna wipe " Kilode tofe fi ise re sile? So rowipe awon aburo re, tabi baba agba l'apa keji ma ku leyin ogun na? Rara. Oto oror koniyen." Koko oror niwipe Krsna fe ko Arjuna wipe ayato si ara wa. gege bi gbogbo wa, ani aso to yato. Beena, awon emi ninu ara wa si yato si ara wa. Imoye Bhagavad-gita niyen. Koye awon eyan. Awon man rowipe ara won lonje. Sastra o feran iru ironu bayi.

yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke
sva-dhīḥ kalatrādiṣu bhauma ijya-dhīḥ
yat-tīrtha-buddhiḥ salile na karhicij
janeṣv abhijñeṣu sa eva go-kharaḥ
(SB 10.84.13)

Maalu nitumo Go, ketekete nitumo khara. Enikeni to ban gbe biwipe ara re loje, yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke... Fun awon eranko ni iru ironu yi wa fun. Aja o mowipe o yato si ara to ni, pe emi mimo loje. Sugbon okunrin, o le ye pe oyato si ara re, ara re ko loje. Bawo lasele mowipe ayato si ara wa? Ilana to rorun wa lati mo. Nibi eleri ninu Bhagavad-gita, wan sowipe,

dehino 'smin yathā dehe
kaumāraṁ yauvanaṁ jarā
tathā dehāntara-prāptir
dhīras tatra na muhyati
(BG 2.13)