YO/Prabhupada 0482 - Mind is the vehicle for being attached: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0482 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1968 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0005 edit: add new navigation bars (prev/next))
 
Line 7: Line 7:
[[Category:YO-Quotes - in USA, Seattle]]
[[Category:YO-Quotes - in USA, Seattle]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0481 - Krishna is All-attractive, Krishna is Beautiful|0481|YO/Prabhupada 0483 - How You Can Think of Krishna Unless You Develop Love for Krishna?|0483}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 19: Line 22:


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/681018LE.SEA_clip5.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/681018LE.SEA_clip5.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->



Latest revision as of 12:31, 21 September 2017



Lecture -- Seattle, October 18, 1968

okan wa lon di wa mu. Teyin ba nife fun okurin kan , tab'obirin ka, fun enikeni.. Nigbakugba, ama bere sini somo onitoun. Nkan iranu ni anfaani lati somo awon eyan bayi. teyin ba fe somo enikeni, ogbodo je nkan t'ara eni. Se oto or ko niyen? Eyin o le nife fun sanma, sugbon ele nife fun orun, ele nife fun osupa, tabi awon irawo, nitoripe awon eda l'ototo lonje. teyin bafe nife fun sanma, a le gan fun yin. Egbodo pada s'orun yi. Beena ilana yoga yi, tope si ipo to gaju, ninu ife... Beena teyin bafe nife enikan. Krsna loye koje. Gege bi iworan yi se wa nibi. Rādhārāṇī nife fun Kṛṣṇa, o sin fun Krsna ni awon idodo, Krsna sin fun fere re. Bena ele wo aworan yi nigbogbo'gba. Lehin na eyin ma wa ninu yoga, samadhi. Kilode teyin se feran awon nkan tio seyan. teyin ban ronu nipa awon nkan tio kin seyan, ema ri ina, awon oda , orisirisi nkan leyi ma ri. Sugbon irisi na niyen je. Bawo lese fe fi awon irisi segbe? Kolese se. Nitorina kilode teyin o se fokan yin sori irisi gidi, īśvaraḥ paramaḥ kṛṣṇaḥ sac-cid-ānanda-vigrahaḥ (Bs. 5.1), Eledumare, oludari gbogbo agbaye, Oludari to gaju, tol'ara? Bawo? Ara nitumo igrahaḥ, vigrahaḥ Iru ara wo loni? Sac-cid-ānanda, aye t'aye raye, to kun fun idunnu, kun fun imoye. Iru ara bayi. Kon se iru ara bi t'awa bayi. Ara yi kun fun aimokan, ati isoro, fun igba die na lowa. odi keji loje. Ara re wa fun tayeraye; ara mi wa fun igba die. Ara re kun fun idunnu, ara temi kun fun isoro, gbogbo'gba ki nkan fun mi nidamu - orififo, eyin riro, inira, Awon eyan ton funmi ni isoro. Adhyātmic, adhibhautic, oru ton mu, otutu to po, ati awon nkan bayi to po. Ara yi wa ninu isoro meta, ara eda yi.