YO/Prabhupada 0499 - Vaisnava is very Kind-hearted, Merciful, Because He Feels for Others: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0499 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1972 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 7: Line 7:
[[Category:YO-Quotes - in India, Hyderabad]]
[[Category:YO-Quotes - in India, Hyderabad]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0498 - As Soon as I Give up this Body, all my Skyscraper Building, Business|0498|YO/Prabhupada 0500 - You Cannot Become Permanently Happy in this Material World|0500}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 19: Line 22:


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/721121BG.HYD_clip3.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/721121BG.HYD_clip3.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 27: Line 30:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Brahma-bhūtaḥ prasannātmā na śocati na kāṅkṣati ([[Vanisource:BG 18.54|BG 18.54]]). Lasiko yi, eyin na ma riwipe gbogbo awon eda daabi eyin na. kowulo t'eda na baje brahmana tabi aja, bibatiejepe candala loje, tabi erin.
Brahma-bhūtaḥ prasannātmā na śocati na kāṅkṣati ([[Vanisource:BG 18.54 (1972)|BG 18.54]]). Lasiko yi, eyin na ma riwipe gbogbo awon eda daabi eyin na. kowulo t'eda na baje brahmana tabi aja, bibatiejepe candala loje, tabi erin.


:vidyā-vinaya-sampanne
:vidyā-vinaya-sampanne
Line 33: Line 36:
:śuni caiva śva-pāke ca
:śuni caiva śva-pāke ca
:paṇḍitāḥ sama-darśinaḥ
:paṇḍitāḥ sama-darśinaḥ
:([[Vanisource:BG 5.18|BG 5.18]])
:([[Vanisource:BG 5.18 (1972)|BG 5.18]])


Nkan tafe niyen. Iriri mimo. Paṇḍitāḥ sama-darśinaḥ. Nitorina awon elesin je pandita t'ipo kini. Nitoripe awon Olufokansi je sama-darśinaḥ. On ronu nipa awon eda iyoku nitumo Sama-darsinah. Eni toje Vaisnava... Para-duḥkha-duḥkhī, kṛpāmbudhir yaḥ. Awon Vaisnava ni okan rere nitoripe won ni ife fun awon elomi lokan On ronu nipa awon elomi nitoripe o mo eni toje. On ri gbogbo awon eda bi nkankana pelu Oluwa: " Nisin, nkankana leniyi je pelu Oluwa. Ogbodo pada si ile s'odo Metalakan, asi ba Oluwa jo, asi gbe nibe pelu re tayeraye, ni idunnu. Nisin aye re tin jeera bi elede, tabi eda eyan, tabi bi Oba. nkankana loje. FUn igba die nani." Beena awon olufokan sin gbiynaju lati mu won kuro ninu aimokan yi. Nitorina lnsen pe ni para-duhka-dukhi. Oto ni wipe o le mo nipa ibanuje awon eda toyato. kon se awon oniselu wanyi...kilonfe se? Won pa owo tiwon. Otan. Iru orire wo leleyi? Isoro wan niyen na. Teyan ban ronu wipe " Mo lowo gan. Orire mi po gan." Orire ko niyen. Awon eyan ton ni ilosiwaju gidi ninu imoye Krsna lon je awon eyan ton ni orire gidi. Oun lo ni orire. Bibeko, alaini orire nigbogbo wa. Beena gege bayi loseyeka wa sori ipo imoye mimo yi. aami ilosiwaju yi niwipe eni na o ni idamu kankan lati awon oun ile aye yi. Yaṁ hi na vyathayanty ete puruṣaṁ puruṣarṣabha, sama-duḥkha-sukham. sama-duḥkha ni aaami to wa... Nitoripe o mo wipe on laala. kasowipe eyin laala. Beena sowulo teyin ban sa fun ekun tabi eyin d'oba ninu alaa na? Nkankanna loje. Kosi iyato kankan. Lehin na, alaa loje. Nitorina sama-sukha- duhkha. Ti'nu mi ba dun nitoripe moti d'oba tabi eyan pataki kan, alaa na niyen. Tinba si rowipe " Talaka nimi, Oh mon jiya, mo l'aisan," nkankana loje. Nitorina ninu ese iwe to koja Krsna sowipe : tāṁs titikṣasva bhārata. " Ise adase die lati le faramo. E se ise yin, Imoye Krsna." Yudhyasva mām anusmara ([[Vanisource:BG 8.7|BG 8.7]]). Ise pataki wa niwipe, Krsna sowipe, man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru ([[Vanisource:BG 18.65|BG 18.65]]). " E ronu nipa nigbogbo'gba." Ise adase yi gbodo tesiwaju. Ema foju si awon eto ibanuje tabi idunnu. Nibi...ninu Caitanya-caritamrta won ti salaaye wipe, 'dvaite' bhadrābhadra-jñāna saba 'manodharma', 'ei bhāla ei manda' ei saba 'bhrama'. Dvaite, ninu aye yi, aye apa meji nkan lowa, ninu aye yi, " Nkan bayi da, nkan bayi o da," Nkan afori ro niyen je. Gbogbo nkan ni o da. Kosi nkankan to da. Beena awa lan ronu pe " Eleyi da, eleyi o da." Nkan tan se niyen. Gege bi ise oselu. " Apa yi da. Ikeji o da." Sugbon eyikeyi ninu won toba gba ijoba nkankan loma je. Iye #awon nkan ti won . Kole dinku, teyin ba gba apa kan tabo keji, beena nkan irori wo ni gbogbo e .
Nkan tafe niyen. Iriri mimo. Paṇḍitāḥ sama-darśinaḥ. Nitorina awon elesin je pandita t'ipo kini. Nitoripe awon Olufokansi je sama-darśinaḥ. On ronu nipa awon eda iyoku nitumo Sama-darsinah. Eni toje Vaisnava... Para-duḥkha-duḥkhī, kṛpāmbudhir yaḥ. Awon Vaisnava ni okan rere nitoripe won ni ife fun awon elomi lokan On ronu nipa awon elomi nitoripe o mo eni toje. On ri gbogbo awon eda bi nkankana pelu Oluwa: " Nisin, nkankana leniyi je pelu Oluwa. Ogbodo pada si ile s'odo Metalakan, asi ba Oluwa jo, asi gbe nibe pelu re tayeraye, ni idunnu. Nisin aye re tin jeera bi elede, tabi eda eyan, tabi bi Oba. nkankana loje. FUn igba die nani." Beena awon olufokan sin gbiynaju lati mu won kuro ninu aimokan yi. Nitorina lnsen pe ni para-duhka-dukhi. Oto ni wipe o le mo nipa ibanuje awon eda toyato. kon se awon oniselu wanyi...kilonfe se? Won pa owo tiwon. Otan. Iru orire wo leleyi? Isoro wan niyen na. Teyan ban ronu wipe " Mo lowo gan. Orire mi po gan." Orire ko niyen. Awon eyan ton ni ilosiwaju gidi ninu imoye Krsna lon je awon eyan ton ni orire gidi. Oun lo ni orire. Bibeko, alaini orire nigbogbo wa. Beena gege bayi loseyeka wa sori ipo imoye mimo yi. aami ilosiwaju yi niwipe eni na o ni idamu kankan lati awon oun ile aye yi. Yaṁ hi na vyathayanty ete puruṣaṁ puruṣarṣabha, sama-duḥkha-sukham. sama-duḥkha ni aaami to wa... Nitoripe o mo wipe on laala. kasowipe eyin laala. Beena sowulo teyin ban sa fun ekun tabi eyin d'oba ninu alaa na? Nkankanna loje. Kosi iyato kankan. Lehin na, alaa loje. Nitorina sama-sukha- duhkha. Ti'nu mi ba dun nitoripe moti d'oba tabi eyan pataki kan, alaa na niyen. Tinba si rowipe " Talaka nimi, Oh mon jiya, mo l'aisan," nkankana loje. Nitorina ninu ese iwe to koja Krsna sowipe : tāṁs titikṣasva bhārata. " Ise adase die lati le faramo. E se ise yin, Imoye Krsna." Yudhyasva mām anusmara ([[Vanisource:BG 8.7 (1972)|BG 8.7]]). Ise pataki wa niwipe, Krsna sowipe, man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru ([[Vanisource:BG 18.65 (1972)|BG 18.65]]). " E ronu nipa nigbogbo'gba." Ise adase yi gbodo tesiwaju. Ema foju si awon eto ibanuje tabi idunnu. Nibi...ninu Caitanya-caritamrta won ti salaaye wipe, 'dvaite' bhadrābhadra-jñāna saba 'manodharma', 'ei bhāla ei manda' ei saba 'bhrama'. Dvaite, ninu aye yi, aye apa meji nkan lowa, ninu aye yi, " Nkan bayi da, nkan bayi o da," Nkan afori ro niyen je. Gbogbo nkan ni o da. Kosi nkankan to da. Beena awa lan ronu pe " Eleyi da, eleyi o da." Nkan tan se niyen. Gege bi ise oselu. " Apa yi da. Ikeji o da." Sugbon eyikeyi ninu won toba gba ijoba nkankan loma je. Iye #awon nkan ti won . Kole dinku, teyin ba gba apa kan tabo keji, beena nkan irori wo ni gbogbo e .
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:05, 14 June 2018



Lecture on BG 2.15 -- Hyderabad, November 21, 1972

Brahma-bhūtaḥ prasannātmā na śocati na kāṅkṣati (BG 18.54). Lasiko yi, eyin na ma riwipe gbogbo awon eda daabi eyin na. kowulo t'eda na baje brahmana tabi aja, bibatiejepe candala loje, tabi erin.

vidyā-vinaya-sampanne
brāhmaṇe gavi hastini
śuni caiva śva-pāke ca
paṇḍitāḥ sama-darśinaḥ
(BG 5.18)

Nkan tafe niyen. Iriri mimo. Paṇḍitāḥ sama-darśinaḥ. Nitorina awon elesin je pandita t'ipo kini. Nitoripe awon Olufokansi je sama-darśinaḥ. On ronu nipa awon eda iyoku nitumo Sama-darsinah. Eni toje Vaisnava... Para-duḥkha-duḥkhī, kṛpāmbudhir yaḥ. Awon Vaisnava ni okan rere nitoripe won ni ife fun awon elomi lokan On ronu nipa awon elomi nitoripe o mo eni toje. On ri gbogbo awon eda bi nkankana pelu Oluwa: " Nisin, nkankana leniyi je pelu Oluwa. Ogbodo pada si ile s'odo Metalakan, asi ba Oluwa jo, asi gbe nibe pelu re tayeraye, ni idunnu. Nisin aye re tin jeera bi elede, tabi eda eyan, tabi bi Oba. nkankana loje. FUn igba die nani." Beena awon olufokan sin gbiynaju lati mu won kuro ninu aimokan yi. Nitorina lnsen pe ni para-duhka-dukhi. Oto ni wipe o le mo nipa ibanuje awon eda toyato. kon se awon oniselu wanyi...kilonfe se? Won pa owo tiwon. Otan. Iru orire wo leleyi? Isoro wan niyen na. Teyan ban ronu wipe " Mo lowo gan. Orire mi po gan." Orire ko niyen. Awon eyan ton ni ilosiwaju gidi ninu imoye Krsna lon je awon eyan ton ni orire gidi. Oun lo ni orire. Bibeko, alaini orire nigbogbo wa. Beena gege bayi loseyeka wa sori ipo imoye mimo yi. aami ilosiwaju yi niwipe eni na o ni idamu kankan lati awon oun ile aye yi. Yaṁ hi na vyathayanty ete puruṣaṁ puruṣarṣabha, sama-duḥkha-sukham. sama-duḥkha ni aaami to wa... Nitoripe o mo wipe on laala. kasowipe eyin laala. Beena sowulo teyin ban sa fun ekun tabi eyin d'oba ninu alaa na? Nkankanna loje. Kosi iyato kankan. Lehin na, alaa loje. Nitorina sama-sukha- duhkha. Ti'nu mi ba dun nitoripe moti d'oba tabi eyan pataki kan, alaa na niyen. Tinba si rowipe " Talaka nimi, Oh mon jiya, mo l'aisan," nkankana loje. Nitorina ninu ese iwe to koja Krsna sowipe : tāṁs titikṣasva bhārata. " Ise adase die lati le faramo. E se ise yin, Imoye Krsna." Yudhyasva mām anusmara (BG 8.7). Ise pataki wa niwipe, Krsna sowipe, man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru (BG 18.65). " E ronu nipa nigbogbo'gba." Ise adase yi gbodo tesiwaju. Ema foju si awon eto ibanuje tabi idunnu. Nibi...ninu Caitanya-caritamrta won ti salaaye wipe, 'dvaite' bhadrābhadra-jñāna saba 'manodharma', 'ei bhāla ei manda' ei saba 'bhrama'. Dvaite, ninu aye yi, aye apa meji nkan lowa, ninu aye yi, " Nkan bayi da, nkan bayi o da," Nkan afori ro niyen je. Gbogbo nkan ni o da. Kosi nkankan to da. Beena awa lan ronu pe " Eleyi da, eleyi o da." Nkan tan se niyen. Gege bi ise oselu. " Apa yi da. Ikeji o da." Sugbon eyikeyi ninu won toba gba ijoba nkankan loma je. Iye #awon nkan ti won . Kole dinku, teyin ba gba apa kan tabo keji, beena nkan irori wo ni gbogbo e .