YO/Prabhupada 0586 - Actually this Acceptance of Body Does Not Mean I Die: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0586 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1972 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 7: Line 7:
[[Category:YO-Quotes - in India, Hyderabad]]
[[Category:YO-Quotes - in India, Hyderabad]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0585 - A Vaiṣṇava is Unhappy by seeing Others Unhappy|0585|YO/Prabhupada 0587 - Every One of Us is Spiritually Hungry|0587}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 15: Line 18:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|7qb0UN7KhBo|Actually this Acceptance of Body Does Not Mean I Die - Prabhupāda 0586}}
{{youtube_right|s7PoEzNjTPk|Actually this Acceptance of Body Does Not Mean I Die<br />- Prabhupāda 0586}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/721125BG-HYD_clip03.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/721125BG-HYD_clip03.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 27: Line 30:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT (from DotSub) -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT (from DotSub) -->
Nitorina taba s'eto ninu aye yi, ara eda yi, ara eda yi ma paari, oma ku, sugbon eto timo ni yi ma wa ninu okan mi. nitoripe osi wa ninu okan mi, lati le paari ife okan yi mo gbodo gba ara eda imi. Ofin ipaaro ara fun emi leleyi. Emi yi as gba ara eda imi pelu eto yi lokan. pelu emi yi, emi to gaju, Eledumare wa pelu e. Sarvasya cāhaṁ hṛdi sanniviṣṭo mattaḥ smṛtir jñānam apohanaṁ ca ([[Vanisource:BG 15.15|BG 15.15]]). Beena, emi to gaju yi, Eledumara, lon fun logbon. " Nisin ofe s'eto yi. Nisin o ti ni ara lati fise. Beena ale riwipe enikan je oni sayensi giga tabi atokose to da. itumo re niwipe laye re to kehin atokose loje, osin seto bayi, ninu aye yi na, ife okan re yi ti tan. Asi sewaadi kan, lehin na adi olokiki, eyan pataki. Nitoripe awon karmi, nkan meta lonfe: lābha-pūjā-pratiṣṭhā. Wanfe ijeere aye yi, ati ki awon eyan teriba fun won, lābha-pūjā-pratiṣṭhā ati aye to dogba. Ile aye yi. Beena leyokan sikeji, awa sin gbiyanju lati ni ijeere aye yi die, awon igberaga, ati oruko rere. nitorina lasen gba ara eda orisiris. Nkan ton sele niyen. Looto pe mo gba ara eda yi konsepe moti ku. Mo wa nibe. Ninu ara teyin o le foju ri. Mowa nibe. Na jāyate na mriyate. Nitorina kosejo pe eyin ni ibimo tabi iku. Iyika ara eda yi leleyi. Vāsāṁsi jīrṇāni yathā vihāya ([[Vanisource:BG 2.22|BG 2.22]]), base ma salaye ninu ese-iwe to kan:
Nitorina taba s'eto ninu aye yi, ara eda yi, ara eda yi ma paari, oma ku, sugbon eto timo ni yi ma wa ninu okan mi. nitoripe osi wa ninu okan mi, lati le paari ife okan yi mo gbodo gba ara eda imi. Ofin ipaaro ara fun emi leleyi. Emi yi as gba ara eda imi pelu eto yi lokan. pelu emi yi, emi to gaju, Eledumare wa pelu e. Sarvasya cāhaṁ hṛdi sanniviṣṭo mattaḥ smṛtir jñānam apohanaṁ ca ([[Vanisource:BG 15.15 (1972)|BG 15.15]]). Beena, emi to gaju yi, Eledumara, lon fun logbon. " Nisin ofe s'eto yi. Nisin o ti ni ara lati fise. Beena ale riwipe enikan je oni sayensi giga tabi atokose to da. itumo re niwipe laye re to kehin atokose loje, osin seto bayi, ninu aye yi na, ife okan re yi ti tan. Asi sewaadi kan, lehin na adi olokiki, eyan pataki. Nitoripe awon karmi, nkan meta lonfe: lābha-pūjā-pratiṣṭhā. Wanfe ijeere aye yi, ati ki awon eyan teriba fun won, lābha-pūjā-pratiṣṭhā ati aye to dogba. Ile aye yi. Beena leyokan sikeji, awa sin gbiyanju lati ni ijeere aye yi die, awon igberaga, ati oruko rere. nitorina lasen gba ara eda orisiris. Nkan ton sele niyen. Looto pe mo gba ara eda yi konsepe moti ku. Mo wa nibe. Ninu ara teyin o le foju ri. Mowa nibe. Na jāyate na mriyate. Nitorina kosejo pe eyin ni ibimo tabi iku. Iyika ara eda yi leleyi. Vāsāṁsi jīrṇāni yathā vihāya ([[Vanisource:BG 2.22 (1972)|BG 2.22]]), base ma salaye ninu ese-iwe to kan:


:vāsāṁsi jīrṇāni yathā vihāya
:vāsāṁsi jīrṇāni yathā vihāya
Line 33: Line 36:
:tathā śarīrāṇi vihāya jīrṇāny
:tathā śarīrāṇi vihāya jīrṇāny
:anyāni saṁyāti navāni dehī
:anyāni saṁyāti navāni dehī
:([[Vanisource:BG 2.22|BG 2.22]])
:([[Vanisource:BG 2.22 (1972)|BG 2.22]])


Dehī, eda yi, o kan paaro aso re. bi aso ni ara eda yi se ri. gege base soro tele,awon eyan sowipe emi wa o le ni irisi. Bawo niyen se je? Ti ara eda yi ba dabi aso funmi, bawo lose jewipe emi o ni irisi kankan? bawo laso na se ni irisi? Aso tabi ewu mi ni irisi yi nitoripe ara mi ni irisi na. Moni owo meji. Nitorina aso mi, ewu mi na sini owo meji. Aso mi ni apa meji. Beena ti aso na, ara eda yi bonse juwe re ninu Bhagavad-gita - vāsāṁsi jīrṇāni yathā vihāya ([[Vanisource:BG 2.22|BG 2.22]]) - beena toba je aso, mogbodo ni irisi temi. Bibeeko bawo lonse se aso na? Ipaari oro to daju leleyi asi rorun lati ni oye re. Afi temi ba ni ara eda mi bawo ni aso me seni irisi re? Kini idaaun na? Seni kan fe daaun? Bi eda talakoko o se lese at'owo? Gege bi eyin sen losi odo aronso. Asi won owo yin, ese yin, aya yin. Lehin won ma se aso ati ewu yin. Beena, teyin ba ni aso teba fe, oye ke mo wipe moni ara, ara mimo. Koseni tole jiyan. lehin gbogbo ijiyan wa, oyeka gba oro Krsna. Nitoripe oun l'Olori.
Dehī, eda yi, o kan paaro aso re. bi aso ni ara eda yi se ri. gege base soro tele,awon eyan sowipe emi wa o le ni irisi. Bawo niyen se je? Ti ara eda yi ba dabi aso funmi, bawo lose jewipe emi o ni irisi kankan? bawo laso na se ni irisi? Aso tabi ewu mi ni irisi yi nitoripe ara mi ni irisi na. Moni owo meji. Nitorina aso mi, ewu mi na sini owo meji. Aso mi ni apa meji. Beena ti aso na, ara eda yi bonse juwe re ninu Bhagavad-gita - vāsāṁsi jīrṇāni yathā vihāya ([[Vanisource:BG 2.22 (1972)|BG 2.22]]) - beena toba je aso, mogbodo ni irisi temi. Bibeeko bawo lonse se aso na? Ipaari oro to daju leleyi asi rorun lati ni oye re. Afi temi ba ni ara eda mi bawo ni aso me seni irisi re? Kini idaaun na? Seni kan fe daaun? Bi eda talakoko o se lese at'owo? Gege bi eyin sen losi odo aronso. Asi won owo yin, ese yin, aya yin. Lehin won ma se aso ati ewu yin. Beena, teyin ba ni aso teba fe, oye ke mo wipe moni ara, ara mimo. Koseni tole jiyan. lehin gbogbo ijiyan wa, oyeka gba oro Krsna. Nitoripe oun l'Olori.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:13, 14 June 2018



Lecture on BG 2.20 -- Hyderabad, November 25, 1972

Nitorina taba s'eto ninu aye yi, ara eda yi, ara eda yi ma paari, oma ku, sugbon eto timo ni yi ma wa ninu okan mi. nitoripe osi wa ninu okan mi, lati le paari ife okan yi mo gbodo gba ara eda imi. Ofin ipaaro ara fun emi leleyi. Emi yi as gba ara eda imi pelu eto yi lokan. pelu emi yi, emi to gaju, Eledumare wa pelu e. Sarvasya cāhaṁ hṛdi sanniviṣṭo mattaḥ smṛtir jñānam apohanaṁ ca (BG 15.15). Beena, emi to gaju yi, Eledumara, lon fun logbon. " Nisin ofe s'eto yi. Nisin o ti ni ara lati fise. Beena ale riwipe enikan je oni sayensi giga tabi atokose to da. itumo re niwipe laye re to kehin atokose loje, osin seto bayi, ninu aye yi na, ife okan re yi ti tan. Asi sewaadi kan, lehin na adi olokiki, eyan pataki. Nitoripe awon karmi, nkan meta lonfe: lābha-pūjā-pratiṣṭhā. Wanfe ijeere aye yi, ati ki awon eyan teriba fun won, lābha-pūjā-pratiṣṭhā ati aye to dogba. Ile aye yi. Beena leyokan sikeji, awa sin gbiyanju lati ni ijeere aye yi die, awon igberaga, ati oruko rere. nitorina lasen gba ara eda orisiris. Nkan ton sele niyen. Looto pe mo gba ara eda yi konsepe moti ku. Mo wa nibe. Ninu ara teyin o le foju ri. Mowa nibe. Na jāyate na mriyate. Nitorina kosejo pe eyin ni ibimo tabi iku. Iyika ara eda yi leleyi. Vāsāṁsi jīrṇāni yathā vihāya (BG 2.22), base ma salaye ninu ese-iwe to kan:

vāsāṁsi jīrṇāni yathā vihāya
navāni gṛhṇāti naro 'parāṇi
tathā śarīrāṇi vihāya jīrṇāny
anyāni saṁyāti navāni dehī
(BG 2.22)

Dehī, eda yi, o kan paaro aso re. bi aso ni ara eda yi se ri. gege base soro tele,awon eyan sowipe emi wa o le ni irisi. Bawo niyen se je? Ti ara eda yi ba dabi aso funmi, bawo lose jewipe emi o ni irisi kankan? bawo laso na se ni irisi? Aso tabi ewu mi ni irisi yi nitoripe ara mi ni irisi na. Moni owo meji. Nitorina aso mi, ewu mi na sini owo meji. Aso mi ni apa meji. Beena ti aso na, ara eda yi bonse juwe re ninu Bhagavad-gita - vāsāṁsi jīrṇāni yathā vihāya (BG 2.22) - beena toba je aso, mogbodo ni irisi temi. Bibeeko bawo lonse se aso na? Ipaari oro to daju leleyi asi rorun lati ni oye re. Afi temi ba ni ara eda mi bawo ni aso me seni irisi re? Kini idaaun na? Seni kan fe daaun? Bi eda talakoko o se lese at'owo? Gege bi eyin sen losi odo aronso. Asi won owo yin, ese yin, aya yin. Lehin won ma se aso ati ewu yin. Beena, teyin ba ni aso teba fe, oye ke mo wipe moni ara, ara mimo. Koseni tole jiyan. lehin gbogbo ijiyan wa, oyeka gba oro Krsna. Nitoripe oun l'Olori.