YO/Prabhupada 0634 - Krishna is Never Affected by the Illusory Energy: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0634 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1973 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 6: Line 6:
[[Category:YO-Quotes - in United Kingdom]]
[[Category:YO-Quotes - in United Kingdom]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0633 - We are just like the Shining Sparks of Krsna|0633|YO/Prabhupada 0635 - The Soul is there in Every Living Entities, even within the Ant|0635}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 18: Line 21:


<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/730830BG-LON_clip_05.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/730830BG-LON_clip_05.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 26: Line 29:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT (from DotSub) -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT (from DotSub) -->
Nitorina ni Vyāsadeva se ri, apaśyat puruṣaṁ pūrṇam ([[Vanisource:SB 1.7.4|SB 1.7.4]]). Gege bi oko afefe, e le fo lori awon sanmo. Awon sanmo o le bo ina orun. Botilejepe labe oko ofurufu yi, sanmo nikan leyin ma ri. Beena kosi bi maya sele se nkankan si Krsna., Nitorina, Bhagavad-gita sowipe daivī hy eṣā guṇamayī mama māyā. Mama māyā ([[Vanisource:BG 7.14|BG 7.14]]), Kṛṣṇa sowipe, " Agbara aimokan mi." Agbara aimokan yi kole se nkankan si Krsna. Gege bi awon sanmo. Sugbon awon alakowe Mayavadi, wan sowipe nigbati otito to gaju yio ba wa, awon na sini igbagbo ninu aye atunwa, sugbon imoye toni niwipe otito too gaju kole jeyan. Nigbat'oba farahan, asi gba ara maya. Mayadeva leleyi. Oluwa ni Krsna sugbon oti gba ara eda lasan. Beena won fe fi awon eda lasan fiwe Krsna, beena wonle fenu ba Bhagavad-gita je. Wan sowipe avajānanti māṁ mūḍhā mānuṣīṁ tanum āśritam ([[Vanisource:BG 9.11|BG 9.11]]). Nitoripe Krsna ti wa ninu ara eda lasan.. Irisi re talakoko pel'apa meji. Wan si gbabee na ninu bibeli: Oluwa si da okunrin lati irisi re." Beena apa meji l'Oluwa ni. Irisi re pel'apa merin ti Visnu, irisi t'alakoko ko niyen. Irisi keji lati Sankarsana ni irisi Visnu je. Beena maya o le fowokan Krsna. Nkan to wa niyen.
Nitorina ni Vyāsadeva se ri, apaśyat puruṣaṁ pūrṇam ([[Vanisource:SB 1.7.4|SB 1.7.4]]). Gege bi oko afefe, e le fo lori awon sanmo. Awon sanmo o le bo ina orun. Botilejepe labe oko ofurufu yi, sanmo nikan leyin ma ri. Beena kosi bi maya sele se nkankan si Krsna., Nitorina, Bhagavad-gita sowipe daivī hy eṣā guṇamayī mama māyā. Mama māyā ([[Vanisource:BG 7.14 (1972)|BG 7.14]]), Kṛṣṇa sowipe, " Agbara aimokan mi." Agbara aimokan yi kole se nkankan si Krsna. Gege bi awon sanmo. Sugbon awon alakowe Mayavadi, wan sowipe nigbati otito to gaju yio ba wa, awon na sini igbagbo ninu aye atunwa, sugbon imoye toni niwipe otito too gaju kole jeyan. Nigbat'oba farahan, asi gba ara maya. Mayadeva leleyi. Oluwa ni Krsna sugbon oti gba ara eda lasan. Beena won fe fi awon eda lasan fiwe Krsna, beena wonle fenu ba Bhagavad-gita je. Wan sowipe avajānanti māṁ mūḍhā mānuṣīṁ tanum āśritam ([[Vanisource:BG 9.11 (1972)|BG 9.11]]). Nitoripe Krsna ti wa ninu ara eda lasan.. Irisi re talakoko pel'apa meji. Wan si gbabee na ninu bibeli: Oluwa si da okunrin lati irisi re." Beena apa meji l'Oluwa ni. Irisi re pel'apa merin ti Visnu, irisi t'alakoko ko niyen. Irisi keji lati Sankarsana ni irisi Visnu je. Beena maya o le fowokan Krsna. Nkan to wa niyen.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:19, 14 June 2018



Lecture on BG 2.28 -- London, August 30, 1973

Nitorina ni Vyāsadeva se ri, apaśyat puruṣaṁ pūrṇam (SB 1.7.4). Gege bi oko afefe, e le fo lori awon sanmo. Awon sanmo o le bo ina orun. Botilejepe labe oko ofurufu yi, sanmo nikan leyin ma ri. Beena kosi bi maya sele se nkankan si Krsna., Nitorina, Bhagavad-gita sowipe daivī hy eṣā guṇamayī mama māyā. Mama māyā (BG 7.14), Kṛṣṇa sowipe, " Agbara aimokan mi." Agbara aimokan yi kole se nkankan si Krsna. Gege bi awon sanmo. Sugbon awon alakowe Mayavadi, wan sowipe nigbati otito to gaju yio ba wa, awon na sini igbagbo ninu aye atunwa, sugbon imoye toni niwipe otito too gaju kole jeyan. Nigbat'oba farahan, asi gba ara maya. Mayadeva leleyi. Oluwa ni Krsna sugbon oti gba ara eda lasan. Beena won fe fi awon eda lasan fiwe Krsna, beena wonle fenu ba Bhagavad-gita je. Wan sowipe avajānanti māṁ mūḍhā mānuṣīṁ tanum āśritam (BG 9.11). Nitoripe Krsna ti wa ninu ara eda lasan.. Irisi re talakoko pel'apa meji. Wan si gbabee na ninu bibeli: Oluwa si da okunrin lati irisi re." Beena apa meji l'Oluwa ni. Irisi re pel'apa merin ti Visnu, irisi t'alakoko ko niyen. Irisi keji lati Sankarsana ni irisi Visnu je. Beena maya o le fowokan Krsna. Nkan to wa niyen.