YO/Prabhupada 0651 - The Whole Yoga System Means to Make the Mind Our Friend: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0651 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1969 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 8: Line 8:
[[Category:Yoruba Pages - Yoga System]]
[[Category:Yoruba Pages - Yoga System]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0650 - Get Out from this Entanglement by this Perfect Yoga of Krishna Consciousness|0650|YO/Prabhupada 0652 - Padma Purana is Meant for the Persons Who Are in the Modes of Goodness|0652}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 20: Line 23:

<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/690215BG-LA_Clip1.MP3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/690215BG-LA_Clip1.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->

Line 36: Line 39:
Olufokansi: Ese kefa.
Olufokansi: Ese kefa.

Olufokansi: " Fun eni toti ni idaari lori okan re, ore re loje. sugbon fun eni tio le se, ota re l'okan re je ([[Vanisource:BG 6.6|BG 6.6]])"
Olufokansi: " Fun eni toti ni idaari lori okan re, ore re loje. sugbon fun eni tio le se, ota re l'okan re je ([[Vanisource:BG 6.6 (1972)|BG 6.6]])"

Prabhupada: Beeni. Wan soro nipa okan. Gbogbo ilana yoga wa lati so okan wa d'ore wa. Okan wa, ninu ile aye yi... Gege bi amoti, ota l'okan re jesi. Oni ese iwe kan to da gan ninu Caitanya-caritāmṛta.

Line 46: Line 49:
Okan... Emi nimi, nkankana pelu Eledumare. Lesekese ti okan wa ba ni idoti, ma bere sini huwakuwa, nitoripe moti ni ominiran die. "kilode timo fe sise fun Krsna tabi Oluwa? Oluwa nimi." Okan wa lonsofun wa. Gbogbo nkan wanyi ti yika. Owa labe itanra yi, aimokan, gbogbo ile aye re ti baje niyen. T'awa o ba le ni idari lorio okan wa, tafe ni idari lori awon ijoba nla nla, sugbon tawa o ba le ni idari lori okan wa, lehin na teyin ba tie niidari lori ijoba na, ipadaanu loje. Okan yin l'ota to gaju teyin ni. Tesiwaju.

Olufokansi: Fun eni toti ni idari lori okan re, eyan bayi ti padi emi mimolokan, nitoripe oti ni ifokanbale. Fun irun eyan bayi, idunnu ati ibanuje, oru at'otuttu, ogo ati eebu nkankana nigbogbo e ([[Vanisource:BG 6.7|BG 6.7]])."
Olufokansi: Fun eni toti ni idari lori okan re, eyan bayi ti padi emi mimolokan, nitoripe oti ni ifokanbale. Fun irun eyan bayi, idunnu ati ibanuje, oru at'otuttu, ogo ati eebu nkankana nigbogbo e ([[Vanisource:BG 6.7 (1972)|BG 6.7]])."

Prabhupada: Tesiwaju.
Prabhupada: Tesiwaju.

Olufokansi: Ale sowipe eyan tini agbara idan tabi odi yogi tabi otini imo nipa ara-eni, nigbato ba ni itelorun ninu imoye ati imo ara-eni. Iru eyan bayi wa lori ipo to gaju, ara re si bale. O le ri gbogbo nkan, boya okuta, tabi wura bi nkankana ([[Vanisource:BG 6.8|BG 6.8]])."
Olufokansi: Ale sowipe eyan tini agbara idan tabi odi yogi tabi otini imo nipa ara-eni, nigbato ba ni itelorun ninu imoye ati imo ara-eni. Iru eyan bayi wa lori ipo to gaju, ara re si bale. O le ri gbogbo nkan, boya okuta, tabi wura bi nkankana ([[Vanisource:BG 6.8 (1972)|BG 6.8]])."

Prabhupada: Beeni. Nigbat'okan re ba bale, lehin nani ipo yi ma wa. Okuta, tabi wura, iye kanna.
Prabhupada: Beeni. Nigbat'okan re ba bale, lehin nani ipo yi ma wa. Okuta, tabi wura, iye kanna.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:21, 14 June 2018

Lecture on BG 6.6-12 -- Los Angeles, February 15, 1969

Prabhupada: Gbogbo ogo fun awon olufokansi.

Olufokansi: Gbogbo ogo funyin si Prabhupada.

Prabhupada: Apa iwe?

Olufokansi: Ese kefa.

Olufokansi: " Fun eni toti ni idaari lori okan re, ore re loje. sugbon fun eni tio le se, ota re l'okan re je (BG 6.6)"

Prabhupada: Beeni. Wan soro nipa okan. Gbogbo ilana yoga wa lati so okan wa d'ore wa. Okan wa, ninu ile aye yi... Gege bi amoti, ota l'okan re jesi. Oni ese iwe kan to da gan ninu Caitanya-caritāmṛta.

kṛṣṇa bhuliya jīva bhoga vāñchā kare
pāśatemāyā tāre jāpaṭiyā dhare
(Prema-vivarta)

Okan... Emi nimi, nkankana pelu Eledumare. Lesekese ti okan wa ba ni idoti, ma bere sini huwakuwa, nitoripe moti ni ominiran die. "kilode timo fe sise fun Krsna tabi Oluwa? Oluwa nimi." Okan wa lonsofun wa. Gbogbo nkan wanyi ti yika. Owa labe itanra yi, aimokan, gbogbo ile aye re ti baje niyen. T'awa o ba le ni idari lorio okan wa, tafe ni idari lori awon ijoba nla nla, sugbon tawa o ba le ni idari lori okan wa, lehin na teyin ba tie niidari lori ijoba na, ipadaanu loje. Okan yin l'ota to gaju teyin ni. Tesiwaju.

Olufokansi: Fun eni toti ni idari lori okan re, eyan bayi ti padi emi mimolokan, nitoripe oti ni ifokanbale. Fun irun eyan bayi, idunnu ati ibanuje, oru at'otuttu, ogo ati eebu nkankana nigbogbo e (BG 6.7)."

Prabhupada: Tesiwaju.

Olufokansi: Ale sowipe eyan tini agbara idan tabi odi yogi tabi otini imo nipa ara-eni, nigbato ba ni itelorun ninu imoye ati imo ara-eni. Iru eyan bayi wa lori ipo to gaju, ara re si bale. O le ri gbogbo nkan, boya okuta, tabi wura bi nkankana (BG 6.8)."

Prabhupada: Beeni. Nigbat'okan re ba bale, lehin nani ipo yi ma wa. Okuta, tabi wura, iye kanna.