YO/Prabhupada 1073 - Beena botilejepe awa o le ye ironu lati d'oga iseda aye yi kuro l'okan

Revision as of 13:58, 27 March 2015 by YamunaVani (talk | contribs) (Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba) Pages with Videos Category:Prabhupada 0001 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - L...")
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Invalid source, must be from amazon or causelessmery.com

660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Nisin ninu apa 15 ti Bhagavad-gita, wanti ti juwe gege bi ile aye yi se ri. Wan sowipe

ūrdhva-mūlam adhaḥ-śākham
aśvatthaṁ prāhur avyayam
chandāṁsi yasya parṇāni
yas taṁ veda sa veda-vit
(BG 15.1)

Nisin, wanti juwe ile aye yi ninu apa meedogun iwe Bhagavad-gita pe bi igi toni awon gbongbo re soke, urdhva-mulam. Seyin ti ri igi toni awon gbongbo re soke? Awa ti jerisi pe igi toni gbongbo re soke , Taba duro s'eti omi odo, a le ri wipe igi tow leti omi odo na le farahan lori omi pelu awon gbongboo re soke ati awon igi re loke. Beena bi itan ojiji odo metalokan ni ile aye yi je. Gege bi itan ojiji t'igi leti omi odo se dorikodo ninu omi, beena, ile aye , ojiji loje. Ojiji. Ninu ojiji kosi nkankam gidi ninu re, sugobn lasiko kanna, lat'ojiji yi o le ye wa wipe nkan gidi n'be. Fun apeere, ojiji omi to wa ninu ile gbigbe, o fi yewa wipe ni ile gbigbe ko s'omi, sugbon omi wa. Beena, ninu ojiji odo metalokna, tabi ile aye yi, kosi idunnu kankan, kos'omi kankan. Sugbon idunnu at'oimi gidi wa ninu odo metalok Oluwa ti fi ye wa wipe eyan gbodo wa si odo metalokan pel'ona toti da sile, nirmāna-mohā.

nirmāna-mohā jita-saṅga-doṣā
adhyātma-nityā vinivṛtta-kāmāḥ
dvandvair vimuktāḥ sukha-duḥkha-saṁjñair
gacchanty amūḍhāḥ padam avyayaṁ tat
(BG 15.5).

padam avyayam yi, odo metalokan yi , eni toje nimana-moha lole dee be. Nirmāna-mohā. Awon ton feran ipo nitumo Nirmāna. Awon eyan feran yiyan. Awon fe d'oga, awon imi fe d'Oluwa, awon imi fe di Olori ijoba, tabi elomi fe d'olowo, elomi fe di nkan bayi bayi, Oba. Gbogbo awon yiyan wanyi, botijepe ani awon ife okan si won.. Nitoripe leyin gbogbo awon yiyan wanyi fun ara wa, ayato si ara eda yi. Imoye t'alakoko ninu imo mimo. Beena awa o gbodo ni ifarasi iru awon yiyan wanyi. Ati jita-saṅga-doṣā, saṅga-doṣā. Nisin ati ni asepo pelu awon ipo meta ile aye yi, taba si yo ara wa kuro pelu ise ifarasi Oluwa... Boti jepe awa o ni ifarasi fun ise Oluwa, awa o le yo ara wa kuro ninu awon ipo meta aye yi. Nitorina Olyuwa sowipe, vinivṛtta-kāmāḥ, awon ipo wanyi tabi awon idimu aye yi nitotri ifekufe lonti wa, ife okan. Afe d'oga ile aye yi. Titi d'igba t'aba fi iwa yi sile lati d'oga ninu aye yi, titi digba na kole si basele pada si ijoba Oluwa, sanatana-dhama. Dvandvair vimuktāḥ sukha-duḥkha-saṁjñair gacchanty amūḍhāḥ, amūḍhāḥ padam avyayaṁ tat (BG 15.5). Odo metalokan tayeraye, tio le paare bi ile aye yi, afi taba di amūḍhāḥ. Itumo Amūḍhāḥ l'eni tio ni idamu kankan, Eni tio ni idamu kankan lati awon ifarasi fu igbadun aye yi. Eni toba de wa ninu ise fun Oluwa, Oun leni to daju lati wole sinu odo metalokan. orun o wulo ninu odo metalokan yi, osupa tabi ina monamona. Iwo ni soki nipa odo metalokan niyen.