YO/Prabhupada 1074 - Gbogbo iyan tan je ninu aye yi - nitori ara eda tani

Revision as of 14:09, 27 March 2015 by YamunaVani (talk | contribs) (Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0001 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Invalid source, must be from amazon or causelessmery.com

660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Ninu ibo mi ninu Bhagavada-gita wanti salaaye wipe

avyakto 'kṣara ity uktas
tam āhuḥ paramāṁ gatim
yaṁ prāpya na nivartante
tad dhāma paramaṁ mama
(BG 8.21)

Itumo Avyakta ni oun tio farahan. Beena oni awon apa ile aye yi tawa o le foju ri. Awon iye ara wa o daju to jepe awa o le ri awon irawo to wa, tabi awon isogbe towa ninu agbaye yi. Looto ninu aawon iwe mimo Veda a le ri awon iroyin nipa awon isogbe wanyi. Ale gba tabi rara, sugbon gbogbo awon isogbe wanyi tojepe awa ni asepo pelu, wanti juwe won ninu awoniwe mimo Veda, ninu Srimad-Bhagavtam ni pataki. Sugbon ni odo metalokan, to koja ile aye yi, paras tasmāt tu bhāvo 'nyo (BG 8.20), sugbon avyakta yi, toje odo metalokan tio farahan, oun ni paramam gatim, eyan gbodo gbiyanjulati de be. eyan gbodo summo odo metalokan yi, yaṁ prāpya, boya eyan ti de bee tai o fe de bee, na nivartante, eyan o gbodo pada si ile aye yi. Ibe to je odo metalokan Oluwa, lati be l'awa o ni lati pada wa.. (isinmi) Nisin eyan le beere, bawo lasele losi odo metalokan? Wanti salaay ena ninu Bhagavad-gita. Wanti salaaye ninu apa 8, ese-iwe 5,6,7,8, ilana lati le summo odo metalokan Oluwa won ti salaye nibe pe:

anta-kāle ca mām eva
smaran muktvā kalevaram
yaḥ prayāti sa mad-bhāvaṁ
yāti nāsty atra saṁśayaḥ
(BG 8.5)

Anta-kāle, t'aye ba ti pari, lasiko iku. Anta-kāle ca mām eva. Eni to ba ronu nipa Krsna, smaran, toba le ranti. Eni toba fe ku, lasiko iku, toba le ranti Krsna to fara eda yi sile bo sen ronu, Leyin na o daju pe a pada s'odo metalokan, mad-bhavam. Iwa mimo nitumo Bhavam. Yaḥ prayāti sa mad-bhāvaṁ yāti. Itumo Mad-bhavam ni gege bi iwa mimo t'Oluwa. gege base juwe tele, sac-cid-ānanda-vigraha (BS 5.1) l'Oluwa. O ni irisi re, sugbon irisi re wa taye raye, sat; o kun fun imoye, cit; ati idunnu, ananda. Nisin awa gan le yee wo fun ara wa boya ara eda tani yi boya sac-cid- ananda loje. Rara. asat l'ara eda yi. Dipo ko je sat, asat loje. Antavanta ime dehā (BG 2.18), Bhagavad-gītā sowipe, antavat, fun igba die l'ara eda yi ma wa fun. Ati.. Sac-cid-ananda. Dipo kodi sat, odi kedi loje. dipo koje cit, pelu imoye to po, aimokan re lo po. Awa o ni imoye kankan nipa odo metalokan, awa o de ni ogbon gidi kankan nipa ile aye yi. Beena aimoye nkan t'awa o mo, nitorina l'ara eda yi o mo nkankan. Dipo ko logbon, ko mo nkankan. Fun igba die lara eda yi ma wa, ko mo nkankan, ati nirananda. Dipo ko kun fun idunnuj, isoro re po gan. Gbogbo isoro tani ninu aye yi, nitori ara eda yi tani loje.