YO/Prabhupada 1075 - Awa sin seto ile aye wa to kan ninu aye yi: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0001 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 1: Line 1:
<!-- BEGIN CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN CATEGORY LIST -->
[[Category:1080 Yoruba Pages with Videos]]
[[Category:1080 Yoruba Pages with Videos]]
[[Category:Prabhupada 0001 - in all Languages]]
[[Category:Prabhupada 1075 - in all Languages]]
[[Category:YO-Quotes - 1966]]
[[Category:YO-Quotes - 1966]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]
Line 10: Line 10:
[[Category:Yoruba Language]]
[[Category:Yoruba Language]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 1074 - Gbogbo iyan tan je ninu aye yi - nitori ara eda tani|1074|YO/Prabhupada 1076 - lasiko iku ale wa nibi, tabi ka pada si odo metalokan|1076}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 18: Line 21:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|b7kt-tCjIvk|We are Preparing for Our Next Life by Our Activities of This Life - Prabhupāda 1075}}
{{youtube_right|b7kt-tCjIvk|Awa sin seto ile aye wa to kan ninu aye yi<br />- Prabhupāda 1075}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>File:660220BG-NEW_YORK_clip19.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/660220BG-NEW_YORK_clip19.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 30: Line 33:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Oluwa sowipe anta-kāle ca mām eva smaran muktvā kalevaram ([[Vanisource:BG 8.5|BG 8.5]]). Eni toba fi ara eda yi sile, pelu ironu nipa Oluwa Krsna, Eledumare, lesekese loma gba ara mimo toje sac-cid-ananda-vigraha (BS 5.1). Wanti salaaye dada Ilana lati f'ara eda yi sile ati basele gba ara imi ti wa Eda eyan ma ku leyin igba ton ba ti setoo iru ara eda wo loma ni ninu aye re to kan. Sugbon awon olori giga lon seto yi. gege ba sen ni ilosiwaju tabi ifaseyin ninu ise wa. Beena gege bi ise t'an se.. Awon iwa aye yi, lon setro iru aye ojio iwaju tale ni. Awa n'seto ara edato kan tafe ni pelu awon ise wa nisin. Beena taba le seto nisin ninu aye yi lati pada s'odo metalokan, beena o daju pe leyin igba taba f'ara eda yi sile... Oluwa sowipe yaḥ prayāti, eni to ba lo, sa mad-bhāvaṁ yāti ([[Vanisource:BG 8.5|BG 8.5]]), mad-bhāvam... Iru ara t'Oluwa ni loun na mani. Nisin, Orisirisi awon eda mimo lowa, base salaaye tele. Awon brahmavādī, paramātmavādī ati awon olufokansi. Ninu sanmo mimo tabi ninu brahma-jyotir awon isogbe mimo wa nibe, aimoye awon isogbe wanyi, ati salaaye teletele. iwonba awon isogbe wanyi si po ju gbogbo awon agbaye ninu ile aye yi. ekāṁśena sthito jagat ([[Vanisource:BG 10.42|BG 10.42]]) ni ile aye yi je. Ikan ninu apa merin gbogbo agbaye yi loje. odo metalokan ni meta lori merin to ku ninu apa kan lorin merin yi, aimoye awon agbaye na to wa bayi t'awa ti jeerisi nisin. ninu agbaye kan aimoye awon isogbe to wa. Beena aimoye awon orun ati irawo to wa ninu gbogbo agbaye yi, sugbon ikan ninu merin ni gbogbo agbayi yi ninu iseda aye. Odo metalokan ni meta lori merin to ku. Nisin, mad-bavam yi, eni to bafe wole sinu Brahman to gaju, won ma wole sinu brahma-jyotie Oluwa. brahma-jyotir ati awon isogbe mimo iyoku ninu brahma-jyotir nitumo Mad-bhāvam awon olufokansi, ton fe gbadun ninu asepo pel'Oluwa, won ma wole sinu awon isiogbe wanyi, isogbe Vainkuntha. Aimoye awon isogbe Vaikuntha to wa, at'Oluwa, Sri Krsna, pelu irisi re bi Narayana pel'owo merin at'oruko orisirisi, Pradyumna, Aniruddha, ati Mādhava, Govinda... Aimoye opruko towa fun irisi owo merin ti Narayana yi. Beena ikan ninu awon isogbe wanyi, mad-bhavam na niyen, iyen na wa ninu iseda mimo. Beena enikeni toba je onigbago, lasiko to ba fe ku, toba ronu nipa brahma-jyotir tabi toba ronu nipa Paramatma tabi toba ronu nipa Eledumare Sri Krsna, ikan ninu meta wanyi, asi wole sinu sanmo mimo. Sugbon awon olufokansi nikan ton ti ni asepo pel'Oluwa, awon lon le wole sinu isogbe Vaikuntha tabi Goloka Vrndavana. Oluwa sowipe, yaḥ prayāti sa mad-bhāvaṁ yāti nāsty atra saṁśayaḥ ([[Vanisource:BG 8.5|BG 8.5]]). Kosi isiyemeji kankan. Eyan o gbodo ni iseyemeji. Ibeere to wa niyen. Beena eyin tin Bhagavad-gita ninu gbogbo aye re, sugbon t'Oluwa ba so nkan tio jo nkan to wa lori wa, ama ti segbe kan. Ilana to wa ko niyen fun kika iwe Bhagavad-gita. Gege bi Arjuna to sowipe sarvam etaṁ ṛtam manye, " Mo ni gbagbo ninu ounkoun teba so." Beena, igboran. Oluwa sowipe lasiko iku, enikeni toba ronu nipa re, boya bi Brahman tabi Paramatma tabi Eledumare, eni na ma wole sinu sanmo mimo, kosejo kankan nibe. Eyan o gbodo ni isiyemeji kankan. ilana to wa yi, wanti salaaye ofin yi ninu Bhagavad-gita, basele wole sinu odo metalokan t'aban ronu nipa Eledumare lasiko iku wa. Nitoripe wan ti salaaye wipe:  
Igbesi aye yi jẹ igbaradi fun aye atunwa. Oluwa so wipe anta-kāle ca mām eva smaran muktvā kalevaram ([[Vanisource:BG 8.5 (1972)|BG 8.5]]). "Ẹnikẹni ti o se ìrántí Oluwa Eledumare nigbati o ba nfi ara rẹ silẹ, ni anfaani lẹsẹkanna la ti ni ara ẹmi ti sac-cid-ananda-vigraha (BS 5.1). Ilana bi a se nfi ara yi silẹ ati gbigba ara miran ninu ile aye na tun ti s’eto fun. Eniyan pade ikú lẹhin ti iru ara ti yio gbe wọ ni aye atunwa ti ni ipinnu. Sugbọn awọn alasẹ giga ni wọn ṣe ipinnu yi. gege ba sen ni ilosiwaju tabi ifaseyin ninu ise wa. Bakanna ni ibamu pẹlu awọn akitiyan wa... Igbesi aye yi jẹ igbaradi fun aye atunwa. A nse igbaradi fun aye atunwa nipa awon akitiyan ti ile aye yi. Nitorina, ti a ba le mura, ninu aye yi lati ni igbega si ijọba Ọlọrun, o ti daju nigbana, lẹhin ti a ba fi ara yi silẹ... Oluwa so wipe yaḥ prayāti, eni to ba lo, sa mad-bhāvaṁ yāti ([[Vanisource:BG 8.5 (1972)|BG 8.5]]), mad-bhāvam... Oluwarẹ yio ni anfaani ara ẹmí kanna bi ti Oluwa. Bi a ti salaye ṣaaju tẹlẹ, awọn orisirisi eniyan mimọ ni wọn wa Awọn brahma-vādī, paramātma-vādī ati awọn olufọkansin.. Ninu Brahma-jyotir (ọrun imọlẹ) awọn ibugbe ọrun ni wọn wa nibẹ. bi a ti wi tẹlẹ, awọn aimoye ibugbe ọrun ni wọn wa nibẹ. Iye awọn ibugbe ọrun wọnyi tobi ju gbogbo awọn aye ti wọn wa ninu agbaye yi jina, jina. ekāṁśena sthito jagat ([[Vanisource:BG 10.42 (1972)|BG 10.42]]) ni ile aye yi jẹ. Ikan ninu awọn afa mẹrin gbogbo agbaye yi lo jẹ. afa mẹta lori mẹrin to ku jẹ isalu ọrun ninu apa kan lorin merin yi, ninu afa ilẹ yi awọn ọkẹ ati awọn ọkẹ aimoye agbaye bi eleyi t'awa ti jeerisi nisin. ninu agbaye kan aimoye awon isogbe to wa. awọn ọkẹ aimoye agbaye ati awọn aye ọrun pẹlu awọn oorun, awọn irawọ ati awọn osupa ti wọn o lonka ni wọn wa nibẹ. sugbon ikan ninu merin ni gbogbo agbayi yi ninu iseda aye. afa mẹta lori mẹrin to ku jẹ isalu ọrun. Nisin, mad-bavam yi, Ẹni ti o ba fẹ darapọ mọ aye ti Brahman to ga julọ, wọn a si darapọ mọ Brahma-jyotir ti Oluwa Atobiju. brahma-jyotir ati awon isogbe mimo iyoku ninu brahma-jyotir nitumo Mad-bhāvam awon ẹlẹsin, ti o fẹ ni irẹpọdun pẹlu Oluwa, wọn ma wọ inu aye ọrun Vaikuṇṭha. Awọn aye ọrun Vaikuṇṭha wa ni aimoye, ati Oluwa, Ọlọrun Eledumare nipa apero awọn ilọpo Rẹ bi Narayana ọlọwọ mẹrin pẹlu orisirisi orukọ, bi Pradyumna, Aniruddha ati Govinda... ọpọlọpọ awọn ainiye awọn orukọ ni o wa fun Narayana ọlọwọ merin yi. Beena ikan ninu awon isogbe wanyi, mad-bhavam na niyen, iyen na wa ninu iseda mimo. Nitorina ti aye ba de opin eyikeyi ninu awọn eniyan mimọ le fi boya Brahma-jyotir, Paramātmā tabi Śrī Krishna Eledumare gbiro, ni ọnakọna, gbogbo wọn ni wọn o wọ inu isalu ọrun. sugbọn olufọkansin nikan, tabi ẹniti o ni asepọ timọtimọ pẹlu Oluwa Ọba, ni o ma wọ inu ajule ọrun Vaikuṇṭha tabi ajule ọrun Goloka Vrndavana. Oluwa so wipe, yaḥ prayāti sa mad-bhāvaṁ yāti nāsty atra saṁśayaḥ ([[Vanisource:BG 8.5 (1972)|BG 8.5]]). "ko si iyemeji nibẹ." Igbagbọ wa gbọdọ duro sinsin lori eyi. Ẹ ti nfi gbogbo aye yin nka Bhagavad-gita, sugbọn ti Oluwa ba sọ nkan ti ko ni ibamu pẹlu ero wa, a kọ ọ Ki ise ọna kika iwe mimọ Bhagavad-gita niyi. o yẹ ki iwa wa jẹ bi ti Arjuna: sarvam etaṁ ṛtam manye, "Mo gba gbogbo ohun ti iwọ ti sọ gbọ." Bakanna, igboran. Nitorina nigbati Oluwa wi pe ni akoko iku ẹnikẹni ti o ba ronu Rẹ bi, Brahman tabi Paramātmā tabi bi Ọlọrun Eledumare, dajudaju yio lọ sinu sàkaani ọrun, ko si iyemeji nipa eyi. Ko si ọrọ pe a ko le gbà gbọ. ipilẹsẹ ti gbogboogbo na tun ti ni alaye ninu Bhagavad-gītā bi o se le ṣee ṣe lati wọ ijọba ọrun nipa fifi Ọlọrun nìkan gbiro ni akoko iku. Nitoripe ipilẹsẹ ti gbogboogbo na ti ni imẹnuba:  


:yaṁ yaṁ vāpi smaran bhāvaṁ
:yaṁ yaṁ vāpi smaran bhāvaṁ
Line 36: Line 39:
:taṁ tam evaiti kaunteya
:taṁ tam evaiti kaunteya
:sadā tad-bhāva-bhāvitaḥ
:sadā tad-bhāva-bhāvitaḥ
:([[Vanisource:BG 8.6|BG 8.6]])
:([[Vanisource:BG 8.6 (1972)|BG 8.6]])
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:31, 14 June 2018



660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Igbesi aye yi jẹ igbaradi fun aye atunwa. Oluwa so wipe anta-kāle ca mām eva smaran muktvā kalevaram (BG 8.5). "Ẹnikẹni ti o se ìrántí Oluwa Eledumare nigbati o ba nfi ara rẹ silẹ, ni anfaani lẹsẹkanna la ti ni ara ẹmi ti sac-cid-ananda-vigraha (BS 5.1). Ilana bi a se nfi ara yi silẹ ati gbigba ara miran ninu ile aye na tun ti s’eto fun. Eniyan pade ikú lẹhin ti iru ara ti yio gbe wọ ni aye atunwa ti ni ipinnu. Sugbọn awọn alasẹ giga ni wọn ṣe ipinnu yi. gege ba sen ni ilosiwaju tabi ifaseyin ninu ise wa. Bakanna ni ibamu pẹlu awọn akitiyan wa... Igbesi aye yi jẹ igbaradi fun aye atunwa. A nse igbaradi fun aye atunwa nipa awon akitiyan ti ile aye yi. Nitorina, ti a ba le mura, ninu aye yi lati ni igbega si ijọba Ọlọrun, o ti daju nigbana, lẹhin ti a ba fi ara yi silẹ... Oluwa so wipe yaḥ prayāti, eni to ba lo, sa mad-bhāvaṁ yāti (BG 8.5), mad-bhāvam... Oluwarẹ yio ni anfaani ara ẹmí kanna bi ti Oluwa. Bi a ti salaye ṣaaju tẹlẹ, awọn orisirisi eniyan mimọ ni wọn wa Awọn brahma-vādī, paramātma-vādī ati awọn olufọkansin.. Ninu Brahma-jyotir (ọrun imọlẹ) awọn ibugbe ọrun ni wọn wa nibẹ. bi a ti wi tẹlẹ, awọn aimoye ibugbe ọrun ni wọn wa nibẹ. Iye awọn ibugbe ọrun wọnyi tobi ju gbogbo awọn aye ti wọn wa ninu agbaye yi jina, jina. ekāṁśena sthito jagat (BG 10.42) ni ile aye yi jẹ. Ikan ninu awọn afa mẹrin gbogbo agbaye yi lo jẹ. afa mẹta lori mẹrin to ku jẹ isalu ọrun ninu apa kan lorin merin yi, ninu afa ilẹ yi awọn ọkẹ ati awọn ọkẹ aimoye agbaye bi eleyi t'awa ti jeerisi nisin. ninu agbaye kan aimoye awon isogbe to wa. awọn ọkẹ aimoye agbaye ati awọn aye ọrun pẹlu awọn oorun, awọn irawọ ati awọn osupa ti wọn o lonka ni wọn wa nibẹ. sugbon ikan ninu merin ni gbogbo agbayi yi ninu iseda aye. afa mẹta lori mẹrin to ku jẹ isalu ọrun. Nisin, mad-bavam yi, Ẹni ti o ba fẹ darapọ mọ aye ti Brahman to ga julọ, wọn a si darapọ mọ Brahma-jyotir ti Oluwa Atobiju. brahma-jyotir ati awon isogbe mimo iyoku ninu brahma-jyotir nitumo Mad-bhāvam awon ẹlẹsin, ti o fẹ ni irẹpọdun pẹlu Oluwa, wọn ma wọ inu aye ọrun Vaikuṇṭha. Awọn aye ọrun Vaikuṇṭha wa ni aimoye, ati Oluwa, Ọlọrun Eledumare nipa apero awọn ilọpo Rẹ bi Narayana ọlọwọ mẹrin pẹlu orisirisi orukọ, bi Pradyumna, Aniruddha ati Govinda... ọpọlọpọ awọn ainiye awọn orukọ ni o wa fun Narayana ọlọwọ merin yi. Beena ikan ninu awon isogbe wanyi, mad-bhavam na niyen, iyen na wa ninu iseda mimo. Nitorina ti aye ba de opin eyikeyi ninu awọn eniyan mimọ le fi boya Brahma-jyotir, Paramātmā tabi Śrī Krishna Eledumare gbiro, ni ọnakọna, gbogbo wọn ni wọn o wọ inu isalu ọrun. sugbọn olufọkansin nikan, tabi ẹniti o ni asepọ timọtimọ pẹlu Oluwa Ọba, ni o ma wọ inu ajule ọrun Vaikuṇṭha tabi ajule ọrun Goloka Vrndavana. Oluwa so wipe, yaḥ prayāti sa mad-bhāvaṁ yāti nāsty atra saṁśayaḥ (BG 8.5). "ko si iyemeji nibẹ." Igbagbọ wa gbọdọ duro sinsin lori eyi. Ẹ ti nfi gbogbo aye yin nka Bhagavad-gita, sugbọn ti Oluwa ba sọ nkan ti ko ni ibamu pẹlu ero wa, a kọ ọ Ki ise ọna kika iwe mimọ Bhagavad-gita niyi. o yẹ ki iwa wa jẹ bi ti Arjuna: sarvam etaṁ ṛtam manye, "Mo gba gbogbo ohun ti iwọ ti sọ gbọ." Bakanna, igboran. Nitorina nigbati Oluwa wi pe ni akoko iku ẹnikẹni ti o ba ronu Rẹ bi, Brahman tabi Paramātmā tabi bi Ọlọrun Eledumare, dajudaju yio lọ sinu sàkaani ọrun, ko si iyemeji nipa eyi. Ko si ọrọ pe a ko le gbà gbọ. ipilẹsẹ ti gbogboogbo na tun ti ni alaye ninu Bhagavad-gītā bi o se le ṣee ṣe lati wọ ijọba ọrun nipa fifi Ọlọrun nìkan gbiro ni akoko iku. Nitoripe ipilẹsẹ ti gbogboogbo na ti ni imẹnuba:

yaṁ yaṁ vāpi smaran bhāvaṁ
tyajaty ante kalevaram
taṁ tam evaiti kaunteya
sadā tad-bhāva-bhāvitaḥ
(BG 8.6)