YO/Prabhupada 1079 - Iwe mimo ti gbogbo awon eyan gbodo ka dada ni Bhagavdad-gita je: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0001 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 1: Line 1:
<!-- BEGIN CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN CATEGORY LIST -->
[[Category:1080 Yoruba Pages with Videos]]
[[Category:1080 Yoruba Pages with Videos]]
[[Category:Prabhupada 0001 - in all Languages]]
[[Category:Prabhupada 1079 - in all Languages]]
[[Category:YO-Quotes - 1966]]
[[Category:YO-Quotes - 1966]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]
Line 10: Line 10:
[[Category:Yoruba Language]]
[[Category:Yoruba Language]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 1078 - Ton ronu t'okan t'ara wakati merin le-logun nipa Oluwa|1078|YO/Prabhupada 1080 - Isonisoki ti Bhagavad-gita - Oluwa ni Krishna. Oluwa fun awon egbe eyan kan soso ko ni Krishna je|1080}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 18: Line 21:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|4TS_6xy7bcY|Bhagavad-gita is a Transcendental Literature Which One Should Read Very Carefully - Prabhupāda 1079}}
{{youtube_right|4TS_6xy7bcY|Iwe mimo ti gbogbo awon eyan gbodo ka dada ni Bhagavdad-gita je - Prabhupāda 1079}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>File:660220BG-NEW_YORK_clip23.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/660220BG-NEW_YORK_clip23.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 30: Line 33:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Teyan ba gbo awon oro Bhagavad-gita tabi Srimad- Bhagavatam lati awon eda ton wa ni pipe, eleyi ma jek'eni na bere sini ronu nia Eledumara fun wakati merin le logun, eleyi asi ranlowo lati de ipo to gaju, anta-kale, lati ranti Eledumare, toba de ti f'ara eda yi sile, asi ni ara eda mimo, ara eda mimo, tole fi ni asepo pel'Oluwa. Nitorina Oluwa sowipe,  
Bhagavad Gita jẹ iwe mimọ eyi ti o yẹ ki a fi pẹlẹpẹlẹ ka gan Gbigbọ ọrọ Bhagavad Gita lati ọdọ onimọran eniyan, yoo dari oluwarẹ sinu ero ti Atobijulọ fun wakati mẹrin le logun, yoo ja si ìrántí Ọlọrun Ọba, anta-kale, yoo si jẹki oluwarẹ, lẹyin ti o ba ti fi ara yi silẹ ni anfaani ati gba, ara ẹmí, eyi ti o wulo lati ni irẹpọ pẹlu Ọlọrun Ọba. Nitorina Oluwa sọ wipe,  


:abhyāsa-yoga-yuktena
:abhyāsa-yoga-yuktena
Line 36: Line 39:
:paramaṁ puruṣaṁ divyaṁ
:paramaṁ puruṣaṁ divyaṁ
:yāti pārthānucintayan
:yāti pārthānucintayan
:([[Vanisource:BG 8.8|BG 8.8]])  
:([[Vanisource:BG 8.8 (1972)|BG 8.8]])  


Anucintayan, ton ronu nipa ara re nikan. Ilana to rorun leleyi. Eyan gbodo k'ogon yi lati awon eyan tonti ni iriri lori eto yi. Tad vijñānārthaṁ sa gurum evābhigacchet (MU 1.2.12). Eyan gbodo summo awon eyan tonti se ise adase yi. Beena abhyāsa-yoga-yuktena. Nkan ton pe ni abhyāsa-yoga, ise adase. Abhyāsa..... basele ranti Oluwa nigbogbo'gba. Cetasā nānya-gāminā. Okan, Okan wa kole duro sibikan. Beena eyan gbodo gbokan le irisi Oluwa Sri Krnsa nigbogbo'gba, tabi ninu ohun, ninu oruko re tosi rorun gan. Dipo ta ma gbokan le - okan mi o le duro sibikan, o sa kaakiri, sugbon mole f'eti si ohun Krsna, iyen na ma ranmilowo. Nkan ton pe ni abhyasa-yoga niyen. Cetasā nānya-gāminā paramaṁ puruṣaṁ divyaṁ. Paramaṁ puruṣa, Eledumare ninu odo metalokan, ninu sanmo mimo, eyan le summo, anucintayan, ton ronu nigbogbo'gba Beena awon ilana wanyi, wanti juwe won ninu Bhagavad-gita, Kode s'ihamo fun enikan kan. Konsepe awon ipo okunrin kan lole wa ninu imoye yi. Ironu ati igboran nipa Krsna, nkan ti gbogbo eyan le se niyen. Oluwa sowipe ninu Bhagavad-gita,
Anucintayan, ti o nse iranti Rẹ ninu ọkàn nigbagbogbo. Eleyi ki ise ilana ti o soro gan. Sugbọn, eniyan gbọdọ kọ ilana na lọdọ ẹni ti o ti ni irirÍ aye ninu ọna yi. Tad vijñānārthaṁ sa gurum evābhigacchet (MU 1.2.12). Oluwarẹ gbọdọ sunmọ ẹni ti o wa ninu asa na tẹlẹ. Bẹ na abhyāsa-yoga-yuktena. Eyi ni a npe ni abhyāsa-yoga, lilo niwa. Abhyāsa..... bi a se le ranti Oluwa nigbogbo'gba. Cetasā nānya-gāminā. Ọkan, Ọkan ẹni ki duro jẹ. ṣugbọn a gbọdọ se niwa lati maa fọkansi irisi Ọlọrun Ọba nigbogbogba, ninu ohùn kike pe orukọ Ọlọrun ti o ti wa ni rọrun. Dipo ti mo ma fi fọkansi -- inu riro ko njẹki ọkan eniyan le sinmi, ko le duro jẹ, ṣugbọn mo le fọkansi ifeti si ohùn kike pe Ọlọrun, eyini na ma ranmilọwọ. Eyini na ni abhyasa-yoga. Cetasā nānya-gāminā paramaṁ puruṣaṁ divyaṁ. Paramaṁ puruṣa, Ẹni Isaju Eledumare ninu ijọba ẹmí, eniyan le sumọn, sakaani ọrun, anucintayan, ni sise bayi ni nigbogbo'gba. Be na awon ilana wanyi, awọn ọna ati iwa ti a le gba, wọn ti ni mẹnuba ninu Bhagavad Gita, Kosi idina fun ẹni kankan. Ki ise wipe awọn eniyan iru ipo kan pato ni o le sunmọ. nitori gbigbero Oluwa Ọlọrun, ati gbígbọ nipa Rẹ ṣee ṣe fun gbogbo eniyan. Oluwa si sọ ninu Bhagavad-gita,  


:māṁ hi pārtha vyapāśritya
:māṁ hi pārtha vyapāśritya
Line 44: Line 47:
:striyo vaiśyās tathā śūdrās
:striyo vaiśyās tathā śūdrās
:te 'pi yānti parāṁ gatim
:te 'pi yānti parāṁ gatim
:([[Vanisource:BG 9.32|BG 9.32]])  
:([[Vanisource:BG 9.32 (1972)|BG 9.32]])  


:kiṁ punar brāhmaṇāḥ puṇyā
:kiṁ punar brāhmaṇāḥ puṇyā
Line 50: Line 53:
:anityam asukhaṁ lokam
:anityam asukhaṁ lokam
:imaṁ prāpya bhajasva mām
:imaṁ prāpya bhajasva mām
:([[Vanisource:BG 9.33|BG 9.33]])  
:([[Vanisource:BG 9.33 (1972)|BG 9.33]])  


Oluwa sowipe awon eranko gan ton resile gan ninu ipo aye to kere ju, tabi obirin to niwa ti da, tabi onisowo, tabi alabasise.. Awon onisowo, alabasise, at'obirin, won wa lori ipo kanna nitoripe ogbon won o fibe po titi. Sugbon Oluwa sowipe, awon gan at'awon eyan to kere juwon lo, māṁ hi pārtha vyapāśritya ye 'pi syuḥ ([[Vanisource:BG 9.32|BG 9.32]]), awon nikan ko tabi awon eyan ton kere ju won lo, tabi enikeni. kosejo lori eni toje, boya obirin tab'okurin, enikeni le gba awon ofin bhakti-yoga ko gba Oluwa bi ipinnu aye re, afojusun to gaju ile aye wa.... Māṁ hi pārtha vyapāśritya ye 'pi syuḥ, te 'pi yānti parāṁ gatim. param gatim ninu odo metalokan ati sanmo mimo ti gbogbo wa le summo. Eyan gbodo gbiyanju lati ko nipa eto na. Bhagavad-gita ti salaaye dada eyan le gba ilana yi lati je ki ile aye re ni ilosiwaju to da, beena o le ni ona abayo to daju fun aye re. Koko oro ninu gbogbo Bhagavad-gita niyen. Nitorina, ipari oro niwipe, iwe mimo ni Bhagavad-gita gbogbo awon eyan gbodo ka dada. Gītā-śāstram idaṁ puṇyaṁ yaḥ paṭhet prayataḥ pumān. toba tele awon ilana towa ninu iwe na dada, ibajade towa niwipe, lehin na o le bolowo gbogbo awon isoro aye yi. Bhaya-śokādi-varjitaḥ. Awon ijaya aye yi, gege bi t'aye to kan.
Bayi ni Oluwa wi pe ani awọn eniyan ti wọn jẹ ero-ẹhin, tabi paapa obinrin to wọpọ, eniyan oniṣowo, tabi alagbaṣe... Awọn onisowo, awọn alagbase, ati awọn obirin, nwọn ti kà wọn bi ẹka kanna nitori ọgbọn wọn ko se bẹ ni idagbasoke. Sugbon Oluwa sọ wipe, ani awọn eniyan ti wọn lọ sẹhin ju wọn lọ, māṁ hi pārtha vyapāśritya ye 'pi syuḥ ([[Vanisource:BG 9.32 (1972)|BG 9.32]]), awon nikan kọ tabi awọn eniyan ti wọn kere ju wọn lọ, tabi ẹnikẹni. Ko ṣe pataki ẹni ti o jẹ, botiwu ki o ri, ẹnikẹni ti o ba gbà ilana ti bhakti-yoga yi ti o si gbà Ọlọrun Ọba bi ipilẹsẹ aye, ifọkansi to ga julọ, ìlépa igbẹhin... Māṁ hi pārtha vyapāśritya ye 'pi syuḥ, te 'pi yānti parāṁ gatim. param gatim ti ijoba ọrun ati ti ọrun ẹmí ti gbogbo eniyan le sunmọ. A kan ni lati kọ ọna sise niwa. Ọna sise na ti wa ni alaaye dàdà ninu Bhagavad-gita. ti eniyan ba gba awọn ilana ti wọn fi lelẹ ninu Bhagavad Gita, o le ṣe ojutu to yẹ si gbogbo awọn isoro aye. Eleyi jẹ aropọ gbogbo nkan ti Bhagavad Gita jẹ. Nitorina, ipari ọrọ ni wipe, Bhagavad-gita jẹ iwe imọlẹ eyi ti o yẹ ki a fi tọkantọkan ka gan. Gītā-śāstram idaṁ puṇyaṁ yaḥ paṭhet prayataḥ pumān. bi o ba tẹle awọn ilana Gita daradara, iyọrisi rẹ yio si jẹ, nigbana o see se ki o le ni ominira ninu gbogbo awọn inira ati àníyàn aye. Bhaya-śokādi-varjitaḥ. Oluwarẹ a bọ ninu ibẹrubojo ti aye yi, aye atunwa rẹ yio si jẹ ti ẹlẹmí.  


:gītādhyāyana-śīlasya
:gītādhyāyana-śīlasya
:prāṇāyama-parasya ca
:prāṇāyama-parasya ca
:naiva santi hi pāpāni
:naiva santi hi pāpāni
:pūrva-janma-kṛtāni ca  
:pūrva-janma-kṛtāni ca
:(Gītā-māhātmya 2)


Beena anfani imi to wa niwipe, teyan ba ka Bhagavad-gita, dada pelu okan to mo, lehin na pelu ore ofe Oluwa, beena koni jiya awon ese toti se seyin.  
Anfani miran ti o tun wa niwipe, ti eniyan ba ka Bhagavad Gita, tọkàntọkàn gan ti o si mu ni pataki, nigbana nipa ore-ọfẹ Oluwa, ere awọn aisedeede rẹ ti o ti kọja ko ni f’abọ si lori.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:32, 14 June 2018



660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Bhagavad Gita jẹ iwe mimọ eyi ti o yẹ ki a fi pẹlẹpẹlẹ ka gan Gbigbọ ọrọ Bhagavad Gita lati ọdọ onimọran eniyan, yoo dari oluwarẹ sinu ero ti Atobijulọ fun wakati mẹrin le logun, yoo ja si ìrántí Ọlọrun Ọba, anta-kale, yoo si jẹki oluwarẹ, lẹyin ti o ba ti fi ara yi silẹ ni anfaani ati gba, ara ẹmí, eyi ti o wulo lati ni irẹpọ pẹlu Ọlọrun Ọba. Nitorina Oluwa sọ wipe,

abhyāsa-yoga-yuktena
cetasā nānya-gāminā
paramaṁ puruṣaṁ divyaṁ
yāti pārthānucintayan
(BG 8.8)

Anucintayan, ti o nse iranti Rẹ ninu ọkàn nigbagbogbo. Eleyi ki ise ilana ti o soro gan. Sugbọn, eniyan gbọdọ kọ ilana na lọdọ ẹni ti o ti ni irirÍ aye ninu ọna yi. Tad vijñānārthaṁ sa gurum evābhigacchet (MU 1.2.12). Oluwarẹ gbọdọ sunmọ ẹni ti o wa ninu asa na tẹlẹ. Bẹ na abhyāsa-yoga-yuktena. Eyi ni a npe ni abhyāsa-yoga, lilo niwa. Abhyāsa..... bi a se le ranti Oluwa nigbogbo'gba. Cetasā nānya-gāminā. Ọkan, Ọkan ẹni ki duro jẹ. ṣugbọn a gbọdọ se niwa lati maa fọkansi irisi Ọlọrun Ọba nigbogbogba, ninu ohùn kike pe orukọ Ọlọrun ti o ti wa ni rọrun. Dipo ti mo ma fi fọkansi -- inu riro ko njẹki ọkan eniyan le sinmi, ko le duro jẹ, ṣugbọn mo le fọkansi ifeti si ohùn kike pe Ọlọrun, eyini na ma ranmilọwọ. Eyini na ni abhyasa-yoga. Cetasā nānya-gāminā paramaṁ puruṣaṁ divyaṁ. Paramaṁ puruṣa, Ẹni Isaju Eledumare ninu ijọba ẹmí, eniyan le sumọn, sakaani ọrun, anucintayan, ni sise bayi ni nigbogbo'gba. Be na awon ilana wanyi, awọn ọna ati iwa ti a le gba, wọn ti ni mẹnuba ninu Bhagavad Gita, Kosi idina fun ẹni kankan. Ki ise wipe awọn eniyan iru ipo kan pato ni o le sunmọ. nitori gbigbero Oluwa Ọlọrun, ati gbígbọ nipa Rẹ ṣee ṣe fun gbogbo eniyan. Oluwa si sọ ninu Bhagavad-gita,

māṁ hi pārtha vyapāśritya
ye 'pi syuḥ pāpa-yonayaḥ
striyo vaiśyās tathā śūdrās
te 'pi yānti parāṁ gatim
(BG 9.32)
kiṁ punar brāhmaṇāḥ puṇyā
bhaktā rājarṣayas tathā
anityam asukhaṁ lokam
imaṁ prāpya bhajasva mām
(BG 9.33)

Bayi ni Oluwa wi pe ani awọn eniyan ti wọn jẹ ero-ẹhin, tabi paapa obinrin to wọpọ, eniyan oniṣowo, tabi alagbaṣe... Awọn onisowo, awọn alagbase, ati awọn obirin, nwọn ti kà wọn bi ẹka kanna nitori ọgbọn wọn ko se bẹ ni idagbasoke. Sugbon Oluwa sọ wipe, ani awọn eniyan ti wọn lọ sẹhin ju wọn lọ, māṁ hi pārtha vyapāśritya ye 'pi syuḥ (BG 9.32), awon nikan kọ tabi awọn eniyan ti wọn kere ju wọn lọ, tabi ẹnikẹni. Ko ṣe pataki ẹni ti o jẹ, botiwu ki o ri, ẹnikẹni ti o ba gbà ilana ti bhakti-yoga yi ti o si gbà Ọlọrun Ọba bi ipilẹsẹ aye, ifọkansi to ga julọ, ìlépa igbẹhin... Māṁ hi pārtha vyapāśritya ye 'pi syuḥ, te 'pi yānti parāṁ gatim. param gatim ti ijoba ọrun ati ti ọrun ẹmí ti gbogbo eniyan le sunmọ. A kan ni lati kọ ọna sise niwa. Ọna sise na ti wa ni alaaye dàdà ninu Bhagavad-gita. ti eniyan ba gba awọn ilana ti wọn fi lelẹ ninu Bhagavad Gita, o le ṣe ojutu to yẹ si gbogbo awọn isoro aye. Eleyi jẹ aropọ gbogbo nkan ti Bhagavad Gita jẹ. Nitorina, ipari ọrọ ni wipe, Bhagavad-gita jẹ iwe imọlẹ eyi ti o yẹ ki a fi tọkantọkan ka gan. Gītā-śāstram idaṁ puṇyaṁ yaḥ paṭhet prayataḥ pumān. bi o ba tẹle awọn ilana Gita daradara, iyọrisi rẹ yio si jẹ, nigbana o see se ki o le ni ominira ninu gbogbo awọn inira ati àníyàn aye. Bhaya-śokādi-varjitaḥ. Oluwarẹ a bọ ninu ibẹrubojo ti aye yi, aye atunwa rẹ yio si jẹ ti ẹlẹmí.

gītādhyāyana-śīlasya
prāṇāyama-parasya ca
naiva santi hi pāpāni
pūrva-janma-kṛtāni ca
(Gītā-māhātmya 2)

Anfani miran ti o tun wa niwipe, ti eniyan ba ka Bhagavad Gita, tọkàntọkàn gan ti o si mu ni pataki, nigbana nipa ore-ọfẹ Oluwa, ere awọn aisedeede rẹ ti o ti kọja ko ni f’abọ si lori.