YO/Prabhupada 0004 - Ema teriba fun iranu



Lecture on BG 10.2-3 -- New York, January 1, 1967

Eto itumo nkan ti a n so...ti iwe mimo Bhagava Gita tun mu enu baa. Tad viddhi praṇipātena paripraśnena sevayā (BG 4.34). Ti e ba fe ni oye imole ti ohun iriri aye ati orun na, nigba na e ni lati tele ilana yi. Kini nkan naa? Tad viddhi praṇipātena Oni lati jowo aye re. Bakanna: Gegebi namanta eva. Ti o ko ba ni iteriba, iwo kole di eniti o ti fi ara re fun Olorun. Ati pee nibo ni? Praṇipāta. Ni bo ni a ti le ri iru eni na ti Oun ni... Eni naa ni yi ti mo le jowo emi mi? Eyi tunmo si pe ani lati se ayewo kekere lati mo odo eni ti a le jowo emi Gede imo yi je dandan ni mi mo fun o. Ma sefi emi re fun nkan nkan ti ko ni lari. O gbodo... Ati bawo ni a sele da oloye tabi eyi ti ko ni itunmo yi mo Eyi na je ifenukan ninu Sastra. O si je siso ninu Katha Upanisad. Tad viddhi praṇipātena pari... BG 4.34). Kaṭha Upaniṣad so wipe tad-vijñānārthaṁ sa gurum evābhigacchet śrotriyaṁ brahma-niṣṭham [MU 1.2.12]. Srotriyam yi tumo si wipe, eni ti o nbo lati ipa itelera awon ojise. Ati wipe kini eri ti o fi han wipe o télè lésésé awon ojise ? Brahma-niṣṭham. Brahma-niṣṭham tumo si pe o ni idaa loju gidi gan nipa Otito Oluwa ti o ga ju lo Gege nibe ni o gbodo jowo ara re ati okan re. Praṇipāta. Praṇipāta tumo si wipe prakṛṣṭa-rūpeṇa nipātam, lai fara ku. Ti o ba ri iru eniyan be, ki o si fi ara re jin. Pranipata.

Oni lati sin, ati lati te ninu, ati lati bere ibere lowo re Gbogbo nkan a si je mi mo Iwo ni lati wadi iru eniyan ti o ni awise be ki o si jowo ara re ati okan re fun. Jijowo ara re ati emi re fun dabi pe o jowo gbogbo re fun Olorun nitori pe o je oluranse ati asoju Olorun Sugbon a gba o laye lati beere ibere lorisirisi, ki ise pe ka fi gba akoko, sugbon fun imo ati oye. Oun naa ni a pe ni pariprasna Awon yi ni eto lati gba ati lati tele Nitorina , gbogbo re wa ni be A kan ni lati gbaa ki a si tele Sugbon ti a ko ba gba tabi lati tele, ti a si fi akoko wa sofo bi eni ti otin npa ati ero kero, pelu gbogbo iwa ki wa, kayi, ko le see-se rara Ti o bari bayi, iwo ko le ni oye nipa Eda Olorun Nitori Olorun awamaridi ni fun awon angeli ati awon alagbara aye yii. Kini gbogbo ilakaka wa?

Nitorina e wo awon ilana lati tele Ti e ba telee, asammūḍhaḥ, asammūḍhaḥ, ti e ba tele awon ilana yio pe sugbon o daju, laisi iyemeji kankan, ti o ba si se.... iyen ni Pratyakṣāvagamaṁ dharmyam. Ti o ba si tele, yio ye o daradara, fun ra re, " pe beeni mo nri kan gba ninu re. Kii si se pe e wa ninu okunkun, tabi wi pe e si ntele bi afoju. Ti o ba tele awon ilana yii, yio si ye o. Oda bi ki eniyan je ounje ti yio se ara lore. Eni naa yio mo lara pe oun ni okun, ebi ko si ni pamo. Ko si ni bere lowo enikeni. Ti yio fi mo lara re. Bakanna,ti o ba gba ona rere ti o si tele ilana, "Beni, mo n te siwaju" Pratyakṣa... ninu ori kesan, Oluwa so wipe pratyakṣāvagamaṁ dharmyaṁ susukham.

Ati pe ko le rara. Ati wipe ole maa se pelu idunun ni gbogbo igba. Kii ni eto na? A npe oruko Olorun, Hare Krishna, a si nje ounje ti ati ya si mimo, prasada ati wipe a nse eko Bhagavad-gita ati imo otito re, a si .ma n gbo orin aladun Nje eyi le bii? Nje eyi le bii? ko le rara Nitorina, nipa ilana yii, iwo o je asammūḍhaḥ. ko si si eda alaye ti yio yan o je. Sugbon ti o ba fe ki won yan o je, awon ti o n yan nije po repete. Nitorina, e mase awujo ayannije a yan niyanje. E sa tele esa a dasile lati ibere wa pampara, bi a ti fi sile ninu awon iwe Veda, tabi Vedic ati bi Krishna se ran sile., Gbiyanju lati imo gbogbo nkan ti a so fun wa lati orisun re wa ki o si gbiyanju lati lo fun igbe aye re. Nigbana, asammūḍhaḥ sa martyeṣu. Martyesu tunmo si.... Martya tunmo sigbogbo awon ti iku di dandan. Awon wo ni? Awon emi ti o wa ni idande lati Brahmā titi ti o fi de ori kokoro ti o kere julo, ti a ko si ka kun, Gbogbo won ni martya. Martya si tun tunmo si wipe akoko iku wa fun won. Nitorina martyeṣu. ninu gbogbo awon eda ti o ma ku, o je eni ti o gbonju laarin won. Asammūḍhaḥ sa martyeṣu. Ki ni idi re? Sarva-pāpaiḥ pramucyate. Oun o si kuro ninu ipinle ese lati iwa ese Ninu aye yi, ninu aye ohun meremere yii, boya a mo tabi akomo a ma n da ese ninu iwuwasi wa.

Nitorina a ni lati kuro ninu ipinle esin Ati baawo ni a se le kuro ninu re? Bhagavad-Gita fi ko wa wi pe Yajñārthāt karmaṇo 'nyatra loko 'yaṁ karma-bandhanaḥ (BG 3.9). Ti a ba ni nkan se, a gbodo se fun Olorun (Krishna).... Yajña tum si Viṣṇu tabi Kṛṣṇa. Ti a ba se nkan ta ba ni se fun Olorun, Krsna, ni kan, nitorina a ko ni jiya ipinle ese Śubhāśubha-phalaiḥ. A nse nkan ti o dara ati nksn ti ko dara Sugbon ti won wa ninu imole Olorun, bi won nba ti le fi iwa wu bayi Won o ni nkan se pelu ipinle ti o dara tabi ti ko dara Nitoripe o wa ni akoso pelu Eni ti O dara julo, Olorun Nitorina sarva-pāpaiḥ pramucyate. Yi o si ye ninu gbogbo esan awon iwa ese Eyi ni eto ati ilana na. Ti a ba si gba eto ati ilana yii, daju daju a o ni igbala lo do Oluwa Olorun. aye wa yi o si yori si rere. Eto na rorun gidigidi, a si le see, gbogbo eniyan le gba lati loo. E se pupo.