YO/Prabhupada 0005 - igbese aye Prabhupada ni iseju meta



Interview -- September 24, 1968, Seattle

Oniroyin: Se e le so fun mi gbolohun kan ni pa igbesi aye yin Eyi ni pe, ni bo le ti lo ile iwe, bawo ni e se di omo leyin Krishna.

Prabhupāda: Ni Kalakuta ni ati bi mi, ati ibe naa ni mo ti se eko mi Omo ilu Kalakuta ni mo je A bi mi ni odun 1896, emi si ni omo oju baba mi Bee ni eko mi ko se tete bere Bi be na mo si losi ile iwe giga, mo se ile iwe giga fun odun mejo. Ni ile iwe akoko, odun merin, ile iwe giga, odun mejo ni koleji, odun merin Ni igba na ni mo fi ara mo egbe Gandhi, egbe orile ede wa Ni pa ori rere, mo pade Guru Maharaja mi, oluko igbala mi, ni odun 1922 Ati lati igba naa ni ona yi ti fami mora be na ni mo rora fi igbesi aye abiyamo si le Mo gbe yawo ni odun 1918 ni gba ti mo si je omo ile ego giga meta. Be naa ni mo se ni awon omo mi Mo nse ise oja rira ati ti ta Ni gba to ya mo fi ehin ti fun igbesi aye abiyamo ni odun 1954 Fun odun merin mo da duro lai ni ara ile Be ni mo se se ajemu ojise Oluwa alarinka aye ni odun 1959 Ni igba naa ni mo ba bere si se iwe ki ko. Iwe mi akoko jade ni odun 1962, leyin naa ni iwe meta tun te le. igba yen ni mo ba fo ri le orile ede yin ni odun 1965 mo si de bi ni osu kesan odun 1965 Lati igba naa, mo ngbi yan ju lati se iwasu ti imole okan Oluwa ni Amerika, Kanada ati ni gbogbo awon orile ede oyibo Bee naa ni awon ile isin wa se nda gbasoke die die Awon omo leyin wa na npo si A nfi oju sile lati wo nkan ti o se le.

Oniroyin: Bawo ni eyin gangan se di omo eleyin oluwa Kini e je te le, tabi ona wo ni e nte le ki e to di omo leyin oluwa?

Prabhupāda: Eto kan na ti mo ti nba e so, igbagbo Ore mi kan, lo fa mi lo pelu agidi lati lo ri oluko igbala mi. Nigbati mo ba Olu lana mi soro, okan mi te le. Lati igba naa, ni eso na ti beresi nta ewe.