YO/Prabhupada 0014 - Awon Elesin se pataki gan



The Nectar of Devotion -- Calcutta, January 30, 1973

Fun onigbagbo, Olorun wa ni atewo olujosin. Ajita, jito 'py asau. Bi o ti le je wipe ajase ni Olorun, o dun mo ninu lati ni isubu lowo iranse Re. Ipo nkan na ni yen. Gege bi tinutinu Re, O jowo ara Re fun Iya Yaśodā,lati segun, lati segun lowo Rādhārāṇī, lati segun lowo awon ore Re. Krishna gba iyimole O si gbe ore Re si ejika. Bi o se wa wulo, nigba miran Oba a gba alawada ninu awon olooye re, ati pe o le sele wipe alawada naa le fi oro awada ri Oba fin, eyi o si dun mo Oba ninu. Alawada naa ni igba miran... Bi o ti wa ri alawada kan ti o gba jumo, Gopāla Bon, ni Bengali. O wa sele pe ni ojo kan, ni Oba ba bi lee re, "Gopāla, kini iyato laarin ire ati ketekete?" Bee ni o ba bere kia kia a ti se iyan wo aye ti o wa laarin re ati Oba na. O ba si da Oba lohun pe, "Ese meta pere ni, Oga mi" Iyato na ko ju ese meta pere lo" Bee na ni, oni kaluku ba bere si rerin. Oba naa si gbadun re. Nitori pe lee ko kan o wa wu lo.

Nitori eeyi Olorun naa... Gbogbo eniyan lo nya logo ni ipo giga Re. Lai ku enikan. Eyi ni ipo Olorun - Oluwa ti O ga ju lo. Ni Vaikuntha, won kan nse logo ni. Ko si nkan to jo eleyi. Sugbon ni Vṛndāvana Kṛṣṇa ni ominira a ti je bakanna pelu awon olusin Re, bi won ti le Rii fin Awon eniyan ko mo eleyi, kini igbesi aye Vṛndāvana. Nitorina awon onigbagbo ododo ni iyi pupo Rādhārāṇī pa ofin, "Ma je ki Krishna wa si ibi bayi" Krishna o le wole. O fi oro pon awon gopis le: "E joo e je ki nlo bee" " Rara , rara o. Ko si ofin pe a le gba o wole. Iwo ko le loo si be" Bee ni, Olorun ni ife si.