YO/Prabhupada 0013 - Ise fun wakati merinlelogun



Lecture on BG 2.49-51 -- New York, April 5, 1966

Yogaḥ karmasu kauśalam. Kauśalam tumo si oje ti o daju Gege bi okunrin meji ti won nsise Ikan wa daju daju; ikeji ko wa damoran Bee na ni awon irin ise. Nkan o lo dede ninu irin ise. Eni ti ko wa daju, oun gbi yanju losan ati loruu, bawo ni o se ma fi si po, sugbon eni ti o daju wa ati lowo kan na lo ri nkan ti ko se deede bee lo se ta okun irin kan, lowo kan ni meji, ni irin ise ba bere si nsi se Hrzum, hrzum, hrzum, hrzum, hrzum, hrzum. Se e ri? Bee na ni, ni igba miran, a le ni wahala pelu ero asoro magbesi wa yi, igba na ni Ogbeni Karl tabi elo miran ma wa tun se. Nitori na gbogbo nkan loni lo imoran to daju. Bee ni karma, karma tumo si ise. A gbo do se ise. Lai se ise ara wa paa pa, ara ati emi yi won o le wa po. Ero aimokan gidi lo je pe eni ti o ba je..., fun iseyori ti emi, eniyan o gbo do se ise. Rara o, o gbo do se ise gan ju lo. Awon ti won o ni okan fun iseyori ti emi, won le se ise fun wakati mejo pere, sugbon awon ti won se ise ni pa aseyori ti emi, koda, awon nse ise fun gbogbo wakati ojo ati oru, wakati merin-le-logun Iyen ni iyato. Ati pe iyato na ni... E maa ri eyi ni akose ti aye yi, ni igbagbo pe awa nse eran ara, ti e ba se ise fun wakati mejo pere, yi o si re yin. Sugbon ni ipa ti emi, bi eti le se ise ju wakati merin-le-logun... Subgon abawi, e ko ni ju wakati merin-le-logun ni akoso yin Bi bee na, ko ni re yin. Mo so fun yi. Eyi je iriri fun ra ra mi. Iriri oju ara mi ni eleyi. Bee ni mo se wa nibi, ti mo si nse ise titi, boya mo nka iwe tabi nko iwe, nipa iwe kika tabi ni ki ko, wakati merin-le-logun. Afi pe ti ebi ba npa mi, ma si jeun. Ati pe ti orun ba nkun mi, ma si lo sun. Bibeko, nigbo gbo igba, ko nre mi. E le beere lowo Ogbeni Paulu, ti mi o ba nse bayi. Nitorina o je nkan idunu, pelu inu didun ni mo fin nse. Ko nre mi rara. Bakanna, ni gbati a ba ti dagaba ninu emi, ko ni ni ifunra... Koda, a kori ra lati lo sun. lati lo sun, " Ah, orun ti wa di mi lowo" Seri ba yen? O fe din igba orun ku. Bee na... Nisinyi, bi ase nwi ninu adura, vande rūpa-sanātanau raghu-yugau śrī-jīva-gopālakau. Awon Goswami mefa yi, Oluwa Chaitanya fun won ni akoso lati se alaaye imo ijinle yi. Won ti ko opolopo awon iwe ni pa eyi. Se e ri ? Nitorina a ya yin lenu fun oye igba ti won fi nsun fun wakati kan ati abo lolojumo, ko ju bee lo. Iyen na, ni igba miran won a tun fi iyen si le.