YO/Prabhupada 0016 - Mofe sise
Lecture on BG 7.1 -- San Francisco, March 17, 1968
Nitori na a gbôdô mô bi a sé le so-po mo Olôrun. Olôrun wa kaari ayé. Eyi ni ègbè isôkan Krishna. Eyi ni isôkan Olôrun. A gbôdô mô bi a se le ri mu ninu awon ifarahan Olorun ni igi, tabi irin, tabi fadaka... Ko se nkan kan. Olorun wa kaari ayé. E gbôdô kô bi a sé le ni ipade Olôrun nipa gbogbo nkan. A o sé alaayé éyi ni nu eto yoga. E maa kô nipa eléyi. Isokan Olôrun yi na yoga ni, yoga pipe, yoga to ga julô, ninu gbogbo awon etoo yoga. Eni keni, iru ki ru yogi le wa, a si le fi daa la ya a si le sô wipe, eyii ni akôkô ninu awon eto yoga. Eyi ni akôkô, ati pe o si rorun bakananna. Ki isé dan dan lati se idaraya. E gba pe o se yin wèrè tabi pe o rè yin, sugbon ninu isokan Krishna ko si ifunra bè. Gbogbo awon ômô êlêyin wa, won ko ni iro miran ju bawo ni won se le se isè Oluwa ni ikunrèrè, iyèn ni isôkan Olôrun. "Swamiji, Ojisè OLuwa, Kini mo le sé, Kini nma sé? Won nsi séé, Daradara. Dara gan. Ko dè nrè won. Iyen ni isokan Olôrun. Ni igbe aye yi, ti e ba se isè fun igba diè, yi o si rè yin. Eni lati simi. Daju daju, emi oun sé, eyi ni pé, mi o nfi ôrô pon ara mi le. Arugbo ara odun meji le laadorin ni mi Ah, ara mi o se dédé. Ni mo ba pada si India. Mo si tun pa da wa. Mo tun bèrè si nsi sè. Mo fè si sé. Bi o se ni ti eda ni, maa ti gba isimi kuro ni nu awon isè yi, sugbon emi ko ni ifunra... Ibi ti agbara mi ba to, mo fe sé sè. Mo fè... osan ati oru. Ni àlè mo nsé sè pelu dictaphone. Nirorina o se mi laanu ... O se mi laanu ti mi o ba le se sè. Eyi ni isôkan Oluwa. Agbôdô ni ôyayâ lati se sè. Ki isé ègbè fun awon ti ko ni nkan sé A ni awon isè ti o pô ti o ngba ni lôwô. Awon ti won nse akoso iwé, awon ti won nta iwé. E kan gbinyanju lati mô bi a sè lè sè ikèdè isokan Oluwa, ni iwon yi. Eyi wulo.