YO/Prabhupada 0019 - Ounkoun t'eba gbo, E sofun elomi



Jagannatha Deities Installation Srimad-Bhagavatam 1.2.13-14 -- San Francisco, March 23, 1967

E gba pe ti e ba fe mo mi tabi nkankan ni pa mi e le bere lowo ore kan, "Ah, Bawo ni Swamiji? O le so nkankan, elo miran, a so nkan miran. Sugbon ti mo ba se alaaye fun yin fun rara mi, "Ipo mi re, nkan ti mo je re" iyen pe ju. Iyen lo pe. Nitorina ti e ba fe mo otito ti Oluwa Alaaye ti o ga ju lo. eyin ko le s'awawi, tabi se asaro. Ko le see se, nitori wipe awon ipa imo yin je aipe pupo. Nitorina kini ona na? Eni lati fi eti Si. Nitori eyi ni O se wa ninu ti anu re lati fun wa ni Bhagavad-gītā. "E sa gbiyanju lati fi eti si. Śrotavyaḥ ati kīrtitavyaś ca. Ti e ba si farabale feti si le gbo eko ti isokan Oluwa, ti e si ja de ti e gbagbe, ah, iyen ko dara Eleyi ko ni je ki e ni ilosiwaju. Ewo wa ni? Kīrtitavyaś ca: "Ikan ki nkan ti e ba ngbo, e gbo do tun so fun awn elo miran." Iyen ni asepe.

Nitori eyi a ti da Ipada Si Oluwa Olorun si le. Awon omo eleko ni ase lati pe, nkan ki nkan ti won ba ngbo, won gbodo fi se ironu ki won si ko sile. Kīrtitavyaś ca. Ki ise lati ma gbo nikan ni. "Ah, Mo ti ngbo fun opolopo odun; sibe sibe, ko ti le ye mi" nitori wipe e o ko lorin, eyin ko se a tun wi nkan ti e ti gbo. E gbodo se a tun wi. Kīrtitavyaś ca. śrotavyaḥ kīrtitavyaś ca dhyeyaḥ. Ati pe bawo ni eyin se le ko iwe tabi se alaaye a fi ti e ba nfi Se riro. E ngbo ni pa Olorun;. e gbodo ronu, igba na leyin lee ri oro so. Bi beko, ko le see se. Nitorina śrotavyaḥ kīrtitavyaś ca dhyeyaḥ and pūjyaś ca. E gbodo se isin pelu. Nitori eyi a ni lo aworan yi fun esin. A gbodo ronu si, a gbodo soro re, a gbodo feti s'oro a gbodo se esin, pūjyaś ca... Ni igba naa? Fun akoko ko kan? Rara. Ni deede. Nityadā, eyi ni eto na. Bee na eni keni ti o ba gba eto yi, o le ni iye Otito ti o Ga ju lo. Eyi ni ikede to daju ti Srimad Bhagavatam.