YO/Prabhupada 0101 - Ilera wa ni lati gbadun aye ti olopin
Press Conference -- April 18, 1974, Hyderabad
Alejo: Kini igbeyin ilepa isokan Olorun yi?
Prabhupada: Beeni, igbeyin ilepa re, ni.... Rara. Mo le so pe. Igbeyin ilepa re ni, pe lati mo iyato laarin emi ati ohun elo. Bi ile-aye ohun elo se wa, aye-orun na si wa nibe. Paras tasmāt tu bhāvaḥ anyaḥ avyaktaḥ avyaktāt sanātanaḥ (BG 8.20). Aye orun je ailopin. Ibugbe ni ile aye ohun elo. Awa je emi-okan. Awa fun ayeraye. Nitorina owo wa ni lati pada si ijoba Orun. ki se ka wa ninu aye ohun elo ki a si ma yi ara pada lati buburu si buru tabi buru si buburu. Iyen ki s'owo wa. Iyen je arun. Ilera wa ni lati gbadun aye ti olopin Yad gatvā na nivartante tad dhāma paramaṁ mama (BG 15.6) S'eri, igbesi aye eniyan ye ki o wa nilo fun lati de ipo ainibawon aye wa - ki se lati gba ara ohun elo pupo si ti a tun ni lati yi pada. Eleyi ni ero aye.
Alejo (2): Se asepe na see se ni igbesi aye kan?
Prabhupada: Beeni. lesekese gan, ti e ba gba. Olorun so wipe
- sarva-dharmān parityajya
- mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja
- ahaṁ tvāṁ sarva-pāpebhyo
- mokṣayiṣyāmi mā śucaḥ
- (BG 18.66)
A nyi ara pada nitori akoto awon ise elese. sugbon ti e ba jowo fun Olorun at ki e gba isokan Olorun, lesekese ni e ma wa sori ipo ti emi.
- māṁ ca yo 'vyabhicāreṇa
- bhakti-yogena sevate
- sa guṇān samatītyaitān
- brahma-bhūyāya kalpate
- (BG 14.26)
Kete ti e ba ti di alainibawon olufokansin ti Olorun lesekese ni e ma te siwaju lori ipo awon ohun elo. Brahma-bhūyāya kalpate. E duro sinu ipo ti emi. Ati ti e ba si ku sinu ipo ti emi, e o si lo si ijoba orun.