YO/Prabhupada 0103 - E ma se gbiyanju lati kuro laarin awon awujo ti awon olujosin



Lecture on CC Adi-lila 7.91-2 -- Vrndavana, March 13, 1974

Narottama dasa Thakura so wipe "Atunwa" Nitori eni ti o je olufokansin, ko fi gba kan se ilepa lati pada si ile, pada si odo Metalokan. Rara. Ibi kibi, iyen ki se pataki. O kan fe yin Oluwa Atobiju logo nikan., Owo re niyen Kii se owo olufokansin lati ma korin ati m'ajo tabi ko sise Oluwa lati le pada si ijoba Re tabi ni Goloka Vrndavana. Iyen ni ife Olorun. "Ti o ba wun, yi O si gba mi" Gege bi Bhaktivinoda Thakura se so wipe: iccha yadi tora. Janmaobi yadi more iccha yadi tora, bhakta-grhete janma ha-upa mora. Eni ti o je olufokansin ko gbadura kan ju wipe... Ko beere pe "Oluwa jowo mumi pada lo si Vaikuntha tabi Goloka Vrndavana. Rara "Ti O ba si ro pe mo gbodo se atunwa leekansi, gbogbo e lo l'ètô" Sugbon nikan, ìbéèrè mi nikan ni pe je ki npada ninu ile olufokansin Googo e ni yen. Ki mba ma le gabagbe Re." Eleyi nikan ni adura ti olujokansin. Nitori.... gege bi omode yi. O ti ya ibi nini baba ati iya Vaisnava Nitorina o ti gbodo je Vaisnavi tabi Vaisnava ni aye akowa re. Nitori eyi jẹ ẹya anfani lati awọn ... Gbogbo awon omo wa, ti won wa s'aye nipa baba, iya Vaisnava, won je olorire gidigidi gan. Lati ìbéèrè aye won, ni won ti ngbo Hare Krsna maha-mantra. Wọn ti wa ni nkan ṣe pẹlu Vaisnava, nkorin, jijo Bi ni ifarawe tabi òtítọnáà, ko nse pataki. Bee ni nwon je awon omo olorire gidigidi gan. Sucinam srimatam gehe yoga-bhrastah-sanjayate (BG 6.41) Bee ni won ki nse awon arinrin omo. Won ti wa ni... Awon omo wonyi nigbogbo igba ni won feran lati ni nkan se po pelu awon olufokansin. Ti won nkorin Hare Krsna, won si nwa s'odo wa. Bee ni won ki nse awon arinrin omo. Bhakti-sange vasa, na. Eleyi je awon anfaani to dara gidigidi, bhakti-sange vasa.

Bee ni egbe isokan Olorun wa, bhakta-sanga lo je. awujo awon elesin. E ma se gbiyanju lati kuro. E ma se gbiyanju lati kuro. Ede aiyede le wa nibe, E s'atunse. Kikorin ati jijo yi na laarin, laarin awọn awujọ ti awọn olujosin ti ni anfanni nla, iye nla. O ti wa ni ifi mulẹ. nibi, ati pe gbogbo awon Vaisnava ti fi mulẹ.

tandera carana-sevi-bhakta-sane vasa
janame janame mora ei abhilasa

itumo Janame janame mora ni wipe ko fe pada Iyen kii se ife re.. "Nigba ti Olorun ba fe, Oun ma funmi l'aye. Iyen je ohun iyato. bibeko, eje kin ma sise mi lo bayi igbesi aye ni awujo awon ijosin ati ki korin, ka si ma jo ni owo mi." Ohun ti a fe niyen. Ko nse ohunkohun miran. Ohunkohun miran. se'fe ohunkohun, iyen ni anyabhilasa. Anyabhilasita-sunyam (Brs. 1.1.11). Eni ti o je olufokansin ko ye ki o fe ohunkohun ayafi eleyi. wipe "Je kin gbe pelu awon awujo awon josin, ki nsi korin Hare Krsna maha mantra". Ile-aye wa niyen.

E seun pupo