YO/Prabhupada 0104 - Fi opin si ojiji iku ati aye



Lecture on BG 9.1 -- Melbourne, April 19, 1976

Puṣṭa Kṛṣṇa: Bawo ni emi okan ti eranko se nwonu ara omo eniyan?

Prabhupāda: Gege bi ole to wa ninu l'ewon. Bawo lo sele di ominira? Nigbati asiko rẹ ni ile ẹwọn ba ti pari, yi o si tun je eni ominira. Ti o ba si tún jẹ odaran, a lo sinu ewon. Nitori naa ile-aye eda eniyan wa fun nini oye. bi mo ti n se alaye, awọn ohun isoro ti aye mi. Emi ko fe lati ku: iku si fi ni pa. Emi ko fẹ di arugbo ọkunrin; Mo niranyan lati di arugbo eniyan. Janma-mṛtyu-jarā-vyādhi-duḥkha-doṣānudarśanam (BG 13.9). Nitori naa o si... gege bi apeere kanna nipa ole Nigbati o wa ni ominira, ti o ba ro, ti o ba nlero, pe "Kilode ti a fi mi sinu ipo ibanuje fun osu mefa ninu ewon? O je ohun iron gidi. lehinna ni o di eniyan gangan. Bẹ bakanna, awọn eniyan ti ni agbara to ti ni ilọsiwaju fun idaro. Ti o ba ronu pe "Kilode ti a fi mi sinu ipo ibanuje yi? Gbogbo eniyan ni o ni lati gba wipe o wa ni ipo ibanuje. O ngbiyanju lati di alayo, sugbon ko si idunnu. Nitori naa bawo ni ayo na se le waye? Wipe anfaani na wa ninu eda eniyan. Sugbon ti o ba ti gba a, nipa aanu ti iseda, ara eniyan ti a ko si lo daradara, bi a ba lo ni ilokulo bi awon aja ati ologbo tabi awon eranko miiran. lẹhinna a ni lati gba lẹẹkansi awọ eranko ati nigbati asiko na ba ti pari ... O gba iye akoko to gun gan nitori ti ilana ati-ran-diran. Nítorí náà lẹẹkansi wa tun wa sinu awo eda eniyan yi, nigbati asiko na ba ti pari. Apeere kanna gangan: Ole kan, bi o ba ti pari asiko ewon re, yi o tun di eni ominira leekansi. Sugbon ti o ba tun hu iwa odaran, , a tun pada lo si ewon. Bee ni ojiji ibi iku ati aye se wa. Ti a ba si lo awo eda ara eniyan wa bi o ti ye, nigba na ni a o si fi opin si ojiji iku ati aye. bee na ti a ko ba lo awo eda ara eniyan yi bi o ti ye, a ma tun lo sinu ojiji iku ati alaaye lekansi.