YO/Prabhupada 0109 - A ko faaye gba eni kankan to ya ọlẹ



Lecture on SB 1.7.24 -- Vrndavana, September 21, 1976

E ti nse ojuse yin to dara gan. Dharma rẹ tumosi ise ti nse ojuse rẹ. Fun apeere ti eba je ẹlẹrọ. eyin se ise yin dada. Tabi oniwosan, tabi oniṣowo, tabi enikeni - gbogbo eniyan ni o ni lati se nkan. E ko le joko s'oju kan ma s'ole ti e o si ma ri atije-atimu yin. Kod bi o ti le je kiniun o ni lati ṣiṣẹ. Na hi suptasya siṁhasya praviśanti mukhe mṛgāḥ. Eleyi ni... Bi ile-aye yi se ri niyen. Koda, ti e ba tile l'agbara bi kiniun, e ko le sun. Ti o la ba ro pe "Emi ni Kiniun, oba aginju ni mi. Je ki nsun, awon eranko asi wa te sii enu mi." Rara, ko le see se. Te ba tie je eranko, egbudo ri eranko mu keto jeun Bibeko iwo a fi ebi ku. Nitorina Olorun so wipe, niyataṁ kuru karma tvaṁ karma jyāyo hy akarmaṇaḥ. "E gbodo se ojuse yin" Śarīra-yātrāpi ca te na prasiddhyed akarmaṇaḥ. E ma le ro... Awon asiwere so pe "Egbe isokan Olorun nko awon eniyan lati s'àsálà. Rara. iyen ki se ẹkọ ti Krishna. A ko faaye gba eni kankan to ya ọlẹ. O gbudo gba ise. Iyen ni egba isokan Olorun Krsna. Ase ti olorun ni yen. Niyataṁ kuru karma Arjuna ti nko lati ja. O ti ngbiyanju lati se bi omo-okunrin jeje ti ki fi ipa se. sugbon Krsna ko gba laaye. "Rara, rara, o le se be.Ailokun re ni yen." Kutas tvā kaśmalam idaṁ viṣame samupasthitam: "E fi ara yin mo daju bi alaibikita. It is anārya-juṣṭam. Iru ipero yi wa fun awon anārya, awon to ko ni ilaju eniyan. E ma se be. Iyen ni ti Olorun... Nitorinaa e ma ro wipe egbe isokan Olorun, awon ti won nse isokan Olorun,, won ma ya ọlẹ, ati ki won fara we Haridāsa Ṭhākura. Iyen kii se isokan Olorun. Isokan Olorun tumosi wipe, bi Olorun se l'àsẹ, o gbọdọ ma sise gidigidi fun wakati merin-le-logun. Iyen ni isokan Olorun. Kii se ko ya ọlẹ, jeun, ki o sun. Rara.

Nitori naa eyi ni a npe ni dharmasya glāniḥ. Sugbon e ni lati yi igun iran yin pada. Ninu ile-aye ide ifojusi yin ni lati se itelorun ipa ara yin. Ati isokan Olorun tumosi e ni lati sise ninu ẹmí kanna, pelu agbara kanna, sugbon fun igbadun Olorun. Itumo ile-aye mimo niyen. Kii se lati di eni ti o ny' ole. Awọn iyato ni, bi o ti wa ni siso nipa onkowe, Kṛṣṇadāsa, ātmendriya-prīti-vāñchā tāre bali 'kāma' (CC Adi 4.165). Kini itumo Kama? Kāma tumo si nigbati eniyan ni ipinnu lati se itẹlọrun ipa ara rẹ. Ìyẹn ni kāma. Kṛṣṇendriya-prīti-icchā dhare 'prema' nāma. kini itumo prema? Prema tumo si nigbati o ba má kópa ara rẹ fun itelorun àwọn ipa ara Krishna . Kilode ti awon gopi se ni igbega?Nitoripe ìlépa won nikan je lati se itẹlọrun àwọn ipa ara Krishna. Nitorina Caitanya Mahāprabhu se niyanju, amyā kācid upāsanā vraja-vadhū-vargeṇa yā kalpitā. Won o ni owo miran. Vrndavana tumosi, awon ti won wa ni Vrndaavan..... Ti won ba fe gbe gangan ni Vrndavan, owo won yẹ ki o wa bi won ni lati se itẹlọrun awọn ipa ara ti Olorun. Iyen ni Vrndavana. Kii se pe " Mo ngbe ni Vrndavana sugbon mo fe se gbadun ara mi" Iyen kii se vṛndāvana-vāsī. Iru igbesi aye yen ni... Opọlọpọ awon obo, aja ati awon elede naa ni won tun wa nibe; won wa ni Vṛndāvana. Se e fe so wipe gbogbo won lo ngbe ni Vrndavana? Rara o. Enikeni ti o ba fe se itelorun ipa ara re ni Vrndavana, o ma di aja, elede tabi obo ni aye atunwa E gbodo mo pe. Nitori naa ko ye ki eni kankan gbiyanju lati se igbadun ara re ni Vrndavan. Ese nla gan niyen. E kan gbiyanju lati se itẹlọrun awon ipa ara Olorun.