YO/Prabhupada 0108 - Titẹ sita ati sise ni itumo gbọdọ tesiwaju



Room Conversation "GBC Resolutions" -- March 1, 1977, Mayapura

Prabhupāda: Ki lonakona, titẹ sita ati sise ni itumo gbọdọ tesiwaju. Iyen ni owo wa akoko. A ko le da duro. E tesiwaju Bi mo se ntenumo, bayi ati ni awon ọpọlọpọ iwe ni ede Hindi Mo kan nse atenumo, "Nibo ni Hindi wa? Nibo ni Hindi wa?" Bẹ ni o ti wa si irisi ojulowo diẹ. Mo kan sa nbi leere: "Nibo ni Hindi wa? Nibo ni Hindi wa?" Be ni o si ti mu daju. Bakanna fun ede Faranse, o se pataki pupo. Agbodo se won ni itumo ati te won jade, bi ọpọlọpọ bi o se ye. "Tewe jade" tumo si a ti ni iwe tẹlẹ. E kan se won ni tumo ni pato ede ki e si tejade. Gbogbo e niyen. ero yi ti wa. Ko ye ke da nkan yin sile. Nítorí náà, France se pataki l'orilẹ-ede. Ki titejade ati iso nitunmo gbodo ma losiwaju. Iyen ni mo beere.