YO/Prabhupada 0113 - O je isoro gidigidi gan lati ni idari lori ahon

From Vanipedia
Jump to: navigation, search
Go-previous.png Previous Page - Video 0112
Next Page - Video 0114 Go-next.png

It is Very Difficult to Control the Tongue
- Prabhupāda 0113


Lecture on SB 5.6.2 -- Vrndavana, November 24, 1976

Nítorí Raghunātha dāsa Gosvāmī tẹle gan muna, Caitanya Mahāprabhu na tun tẹle gan o muna, awọn Rūpa-Sanātana Gosvāmī na tẹlé gan muna. Ko nse wipe nitori eniyan ti wa ngbe ni Vrndavana pẹlu asọ penpe nitorina o ti da bi Rūpa Gosvāmī ... gbogbo asiko ni Rūpa Gosvāmī n'sise Nānā-śāstra-vicāraṇaika-nipuṇau sad-dharma-saṁsthāpakau lokānāṁ hita-kāriṇau. Wọn wà ni Vrndadava, ṣùgbọn nigbagbogbo ni won lerongba bawo ni lati ṣe rere si awọn eniyan, ninu aye yi. Gege bi Prahlāda Mahārāja. Śoce tato vimukha-cetasa. Aniyan Sādhu ni lati ronu nipa awon ti won ti fiipa jayejaye s'onu. nigbagbogbo ni won ronú, ṣiṣe awọn eto bawo ni lati gbe wọn soke,nigbagbogbo ni won ronú, ṣiṣe awọn eto bawo ni lati gbe wọn soke, kuro ninu ijiya. Sādhu niyen. Lokānāṁ hita-kāriṇau. Sādhu, ko je wipe "Mo ti yi imura mi pada ni iru ọna ti, awọn eniyan o si jade ni itara yio si fun mi ni roti, emi o si jẹun ki n sun." Sadhu ko ni yen.. Sādhu... Bhagavān, Olorun so eniti o je sādhu, Api cet su-durācāro bhajate mām ananya-bhāk sādhur eva sa mantavyaḥ (BG 9.30). Ìyẹn ni sādhu. Eniti o fi aye rẹ ni kikun fun Olorun, oun ni sādhu. Koda bi o ti le ni awon iwa buburu diẹ... Iwà Buburu, sādhu kan ko le ni iwà buburu, nitori ti eniyan ba je sadhu, ti o ba ti ni awon iwà buburu ni ibẹrẹ, won a si ni atunse. Śaṣvad bhavati dharmātmā. Kṣipraṁ bhavati dharmātmā śaśvac-chāntiṁ nigacchati Ti o ba je sādhu gangan, iwà buburu aye rẹ yio si wa ni atunse gan laipe, gan laipe, kii se wipe o duro ninu iwà buburu re ki o si tun je sādhu. Ko le see se. Iyen ki se sādhu. Boya nitori isesi ti kọja rẹ o le ti ṣe àwọn asise kan. Eyi le ni yònda. sugbon ni orukọ ti sādhu ati eni ti o ti ni igbala, o maa ṣe gbogbo isekuse, atannije eyan ni. Ko nse sādhu. Api cet su-durācāro. Cet, yadi, toba lesese. Sugbon ti o ba faramo isokan Olorun, lehin na ṣipraṁ bhavati dharmātmā śaśvac-chāntiṁ nigacchati. Ni ibẹrẹ awọn asise kan le wa nibẹ, sugbon a gbọdọ ri pe "Boya awọn aṣiṣe mi ti tọnà bayi ?" O yẹ ki o wa ni isora. Ma gbẹkẹle lokan. itosona ton funwa nibi ni wipe, Ero okan ko se gbẹ́kẹ̀lẹ́. Guru Mahārāja mi ma n so wipe "Lehin igbati o ba ji lati oju-orun, mu bata re kosi lu okan re fun igba ogorun. Eleyi jẹ owo akọkọ rẹ. Ati nigba ti o ba nlọ si ibusun, mu igbale ki o lu ọkàn rẹ okan fun igba ọgọrun. Nigbana o le dari ọkàn rẹ. Bibẹkọ o jẹ soro gidigidi."

Nítorí eyi ni ... Lilu pẹlu bata yi ati igbale, tun je tapasya miran. Fun eniyan bi awa, ti won o ni akoso lori okan won, o yẹ ki a fi tapasya yi se niwa, lilu okan pẹlu bata ati igbale. Nigbana ni o le wa ni iṣakoso. Ati Swami tumo si ẹniti o ni akoso lori okan. Vāco-vegam, krodha-vegam, udara-vegam, upastha-vegam, manasa-vegam, krodha-vegam, etān vegān yo viṣaheta dhīraḥ pṛthivīṁ sa śiṣyāt (NOI 1). Eleyi jẹ ẹk ti Rūpa Gosvāmī. Nigba ti a ba le dari vāco-vegam... krandana-vegam ni eleyi (erin) Wọn o le sakoso. Wọn o le sakoso. Nitorina nwọn wa ni ọmọde. A le se iyònda awọn ọmọde, sugbon ti o ba ti kan eniyan ti o wa ninu aye ti emi , ti ko le sakoso, ko si ireti nigbana. Nigbana o ti jẹti àìnírètí. ainireti loro enina bosi. Eyi yẹ ki o wa ni iṣakoso. Vaco-vegam, krodha-vegam, udara-vegam, upastha vegam. Ṣugbọnohun ti o ṣe pàtàkì jù ni udara-vegam ati jihvā-vegam. jihvā-vegam, o ni lati wa ni dari gidigidi. Bhaktivinoda Ṭhākura sowipe "Gbogbo iye-ara wa ni nibẹ, sugbon ninu wọn, jihvā yi lo lewu gidigidi." Tā'ra madhye jihvā ati lobhamoy sudurmati tā'ke jetā kaṭhina saṁsāre. O je isoro gidigidi gan lati ni idari lori ahon.