YO/Prabhupada 0128 - Mio le ku lailai



Press Conference -- July 16, 1975, San Francisco

Onirohin: Elesin melo leni nu Orile-ede America? Mogbo pe ẹgbẹrun meji. Se oto oro leleyi?

Prabhupāda: wanle so bayi.

Jayatīrtha: sugbon awon eyan ninu ẹgbẹ ni gbo ilu aye to ẹgbẹrun mewa. Awon elesin melo lowa ni Orile-ede America bayi.

Onirohin: Ni odun marun tokoja mose ise kan lori egbe yi, mode ripe awon elesin ni ilu to ẹgbẹrun meji.

Prabhupāda: Oti posi.

Onirohin: On po si?

Prabhupāda: Oh, Beeni. dandani.

Jayatīrtha: Mosowipe iwonba awon elesin wa nin gbogbo agbaye to egberun mewa.

Onirohin: Beeni, Oyemi. Sele sofun mi omo odun melo leyin?

Jayatīrtha: Ofemo odun melo leni, Śrīla Prabhupāda.

Prabhupāda: Ni Osu kan, odun mi ato ogorin.

Onirohin(2): Ogorin?

Prabhupada: Omo odun Ogorin.

Onirohin: Kilo masele..

Prabhupada: Odun 1896 lon bim, elesiro teba fe.

Onirohin: Kilomasele si egbe yi ni Orile-ede America teyin ba ku?

Prabhupāda: Mio le ku lailai.

Elesin: Jaya! Hari bol! (Erin)

Prabhupāda: Masi walaaye ninu awon iwe mi, teba ka wan.

Onirohin: Seyin tini eyan toma ti egbe yi siwaju teba lo?

Prabhupāda: Beeni, Guru Mahārāja mi wan bi. aworan Guru Mahārāja mi da?

Onirohin: Kilode ti egbe Hare Kṛṣṇa o kin jade fun awon atako?

Prabhupāda: Koseni tonse ise ore-ofe juwa lo. Ode ati were ni awon eyan yi Awa sin kowan nipa imoye Olorun. Koseni ton sise afenifere juwa lo. Awa ma fi ipaari si gbogbo irufin. Iru ise afenifere wo leyin se? Eyin so awon eyan di omo-ọdaran. Ise afenifere ko niyen. Itumo Ise afenifere niwipe awon olugbe gbudo ni alaafia, gbudo logbon, wan gbudo ni oye Olorun, lati di Okurin t'ipo kini. Ise afenifere niyen. Iru ise afenifere wo leyin se, ti awon eyan to wan'be je awon eyan lati ipo kerin, karun? Awon Okurin to lari lawan fun leko nibi Awon Okurin wanyi kosenikeni ninu wan toni iwa tio da, wanti fi ipaari si isekuse laarin Okurin ati Obirin, wanti fi'paari si Oti mimu, wanti fi ipaari si eran jije, tabi tẹtẹ awon okurin l'ododo ni gbogbo wan. Sugbon wanti fi iwa wanyi sile. Ise afenifere niyen.

Bhaktadāsa: Śrīla Prabhupāda, wan femo nkan ti egbe Hare Krsna lese ninu eto oselu?

Prabhupāda: Gbogbo nkan ma lari ti awon ba gba egbe Hare Krsna yi s'okan. Yasyāsti bhaktir bhagavaty akiñcanā sarvair guṇais tatra samāsate surāḥ (SB 5.18.12). Ti awon eyan ba sewaasu imoye Olorun yi, gbogbo nkan si dara. eto ẹkọ tawan soro nipa l'aaro yi kole wulo ti awon eyan o bani imoye Olorun. wankan soro.

Prabhupāda: Ki lansoro nipa laaro yi?

Bahulāśva: oroinuokan

Prabhupāda: Abajade towa njiwipe awon akeko sin fo lati ori-oke nitoripe wani ibanuje. sugbon wansi fi gilasi dabo wan.

Bahulāśva: ni Odun 1960 ni ilu Berkeley awon akeko man fo lati ori ile-iso lati lefiku paara wan. Nitorina lanse fi gilasi bo, ki awon akeko maba le fo lati be mo. Nkan ti Prabhupāda fe salaaye niwipe lehin igbati awon akeko yi ba paari ninu ile-iwe, wa lo pokunso (erin)

Prabhupāda: Iru eko wo niyen. Vidyā dadhāti namratā. Itumo alakowe niwipe onitoun niwa toda, ose jeje, o l'ogbon, osile lo awon nka to ko ninu aye re, onisuuru,oni ifokan bale, oni idari lori ara re. itumo eko niyen. Iru eko wa leleyi?

Onirohin: Seyin fe da ile-iwe sile?

Prabhupāda: Beeni, igbiyanju mi to'kan niyen, wansi fi idayato fi ko wan. awon lati ipo kini, keji, keta titi de ikerin. lehin na awon ton wani ikarun si kefa na mawa n'be. Awon Okurin lati ipo Kini gbudo wa ninu awujo awon eyan onitoun lama ko bosele ni idari lori okan re, toni idari lori iye-ara re, tosi mo gan, to looto lenu, toni isuuru, tose jeje, to mowe gan, tole lo nkan to ko ninu aye re, tosi nigbagbo ninu Olorun. okurin lati ipo kini niyen.