YO/Prabhupada 0129 - Gbokan le Krishna - kole si oro aini



Lecture on SB 7.6.1 -- Vrndavana, December 2, 1975

Krsna sowipe, man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru (BG 9.34). L'ojojumo l'awan se waasu, tan sofun awon eyan pe " Krsna leleyi" ni ile-Olorun, Eranti Krsna nigbagbogbo. Ekorin Hare Kṛṣṇa." lehin na, ele ranti pe . Itumo Hare Kṛṣṇa, Hare Kṛṣṇa," niwipe agbudo ranti Krsna nigbagbogbo. Lesekese teba gbo oruko Kṛṣṇa, man-manā. talo mase? Mad-bhakta. Afi teyin badi elesin Krsna, kosi besele lo asiko yin nilokulo, "Kṛṣṇa, Hare Kṛṣṇa, Hare Kṛṣṇa." Itumo re niwipe teba korin Kṛṣṇa, Hare Kṛṣṇa mantra eledi elesin Kṛṣṇa. Man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī.

Nisin, adura si Krsna... Alo asiko ojo lati fi se Kṛṣṇa's maṅgala-āratika, te korin fun Kṛṣṇa, te seounje fun Krsna, te pin kakiri prasadam Krsna,ati orisirisi ona tele gba. gbogbo awon elesin wa - ninu awon ile-adura wa to pe 102 - gbogbo wan lon sise ninu imoye Krsna. Ise-apifunni niyen, kosise mi. Awa o ni iṣowo kankan tanse sugbon awan na ju ọgọ́rùn ọkẹ́ rupees nipaari osu, ọgọ́rùn ọkẹ́ rupees nipaari Osu, sugbon Krsna lon funwa. Teṣāṁ nityābhiyuktānāṁ yoga-kṣemaṁ vahāmy aham (BG 9.22). Teba sise ninu imoye Krsna, tegbokanle Krsna nikan, kolesi oro aini Mo bere ise Krsna yi pelu rupees ogoji, nisin ati lowo repete. Se eyin mo isowo okurin ni aye yi tole bere isowo pelu rupees ogoji lehin odun mewa to sodi Ẹgbẹgbẹrun ọgọrun rupees? Koseni na. Asin se ounje fun prasādam ẹgbàárùn okurin lojojumo imoye Kṛṣṇa leleyi. Yoga-kṣemaṁ vahāmy aham (BG 9.22). lesekese teba ni imoye Krsna, ele gbokan le ke sise niooto fun. lehin na Krsna asi fun in ni gbogbo nkan teba fe.

Awati jerisi gbogbo eleyi. Fun apeere nisin, ni Ilu Bombay, awo ni ile kan tiyi re to egbegberun ogorun rupee. sugbon nigbati mo rale na, koju Ọkẹ-Marundinlogun lo. mokan fomo lai ronu nitoripe odamiloju pe " Ma rowo san. Krsna ma funmi". Kode sowo kankan nigbana. itan-akọọlẹ to po gan niyen, mio sife soro nipare looni. sugbon nisin motini ijerisi pe mole gbarle Krsna - kole si oro aini. Ounkooun teba fe, lema ni. Teṣāṁ nityābhiyuktānām. gege na oyeke sise nigbagbogbo pelu imoye Krsna. Lehin na ounkooun teba fe, gbogbo e loma wa.