YO/Prabhupada 0131 - Iwa adayeba ni lati teriba fun baba re



Lecture on BG 7.11-16 -- New York, October 7, 1966

Asínwín, itanra-ẹni, ati isoro aye yi le lati rekọja O le gan. sugbon Olorun Krsna sowipe, mām eva ye prapadyante māyām etāṁ taranti te (BG 7.14). tabale teriba fun Kṛṣṇa lais'agidi, " Kṛṣṇa mi moti gbagbe nipare fun iwonba aye topo gan. Nisin otiyemi wipe eyin ni baba mi, eyin ni Ologbala timoni. Mosi teriba funyin". gege bi omode toba sonu sen loba baba re, " baba mi, nitori aimo timoni nimose sakuro labe aabo tefunmi, sugbon nisin moti jiya gan. Moti pada wa nisin. " Baba re si ká môra, " Omomi, pada wale. Otipe ti motin reti re. Inumi sidun pe oti pada wale". baba yi nínú rere. Ipo kanna lawa. lesekese tawana ba teriba fun Olorun... Eleyi o le. TI omode ba teriba fun baba re, se nkan nla niyen? Seyin rope ise nla niyen? iwa adayeba niwipe omode gbudo teriba fun baba re. kosejo itiju. Agba ni baba wa. Gege na tinba teriba fun babami, tabi tinba fowokan ese re, ogo loje funmi. ogoloje funmi. Kosoro itiju. Kosi le rara. Kilode tawa o le tertiba fun Krsna?

Itosona towa niyen. Mām eva ye prapadyante. "gbogbo awon eda wanyi toni idamu, tonba teriba funmi," māyām etāṁ taranti te (BG 7.14), kole niisoro laaye re mo." lesekese loma bosinu idaabo baba wa . Ema ri ka l'opin Bhagavad-gītā, ahaṁ tvāṁ sarva-pāpebhyo mokṣayiṣyāmi mā śucaḥ (BG 18.66). ti omode ba gbori lori oyon mama re, iya re asi toju re. t'ewu bade iyare si gbaradi ati ku fun omore, ki'ku tole pa. gege na tawa ba wa labe aabo Olorun kosejo iberu.