YO/Prabhupada 0132 - Awujo laisi idayato, awujo tio wulo niyen



Lecture on BG 7.1 -- Hyderabad, April 27, 1974

Ninu Bhagavad-gītā awa leri gbogbo ọna abayọ fun awon isoro wa. Cātur-varṇyaṁ mayā sṛṣṭaṁ guṇa-karma-vibhāgaśaḥ (BG 4.13). Agbudo pin awujo awon eyan si merin, brāhmaṇa, kṣatriya, vaiśya ati śūdra... Egbudo pin wan. Kosejo pe afeni " awujo laisi idayato". awujo tio wulo niyen. awujo awon eyan tioni idayato awujo tioni iwulo niyen. Agbudo ni awon eyan to l'ogbon gan, lehin na lale mope " awujo eyan leleyi". brāhmaṇa. Cātur-varṇyaṁ mayā sṛṣṭaṁ guṇa-karma... (BG 4.13). afi tiawon eyan ba ri awon Okurin to daju, bawo niwan sefe tele? Yad yad ācarati śreṣṭhaḥ, lokas tad anuvartate (BG 3.21) Awon brāhmaṇa dabi opolo ara wa. afi taba ni oplo, kini iwulo owo ati ese? teyan bani opolo toti baje, asiwere, kosi nkan tole se. nisin, aito awon okurin to lopolo wa ninu awujo eda.. konsepe awon Brāhmaṇa wafun awon eyan lati orile-ede India Krsna o sowipe cātur-varṇyaṁ mayā sṛṣṭam (BG 4.13) fun awon eyan lati Orile-ede India nikan lowa fun, tabi fun awon ipo okurin toyato. Ninu awujo awon eda, agbudo ni eni tologbon gan ti awon eyan le tele. awon eyan toje ọpọlọ ni awujo awon eyan. Akeko Bhagavad-gita niyen. kosi besele sowipe " awa le sise laisi opolo lori wa" Tonba ge ori eyan kuro, eyan na ti tan. kini ese ati owo lese tonba ti ge ori re kuro? Ni asiko tawayi, aito awon opolo wa niju awujo eda. Nitorina ni gbogbo wahala se wa. gege bi iwe Bhagavad-gita se so, agbudo se atunse fun gbogbo awujo awon eyan. Awon eyan to l'opolo siwa. Awon eya to wa ninu ipo kini, ipo kejim keta, bayi bayi lo. awon towa ninu ipo kini wan gbudo di brāhmaṇa, peli iwa brāhmaṇa wan gbudo ni imoye Krsna. Lehin na ni wanle fun gbogbo agbaye ni itosona, teyi basele koni si wahala mo. Egbe Imoye Krsna niyen.

Krsna de ti kowa basele ni oye nipa re ise awon brāhmaṇa, tabi awon alakowe niyen Krsna ti salaaaye. Kini alaaye na? Mayy āsakta-manāḥ: " Egbudo gbokan lemi, Krsna" Ibere leleyi. Agbudo gbokan le nkan. Kosi b'okan wa sele wa laise nkankan oun tafe si po gan. ati somokan ni ise Okan wa. nitorina lasele gba nkan, katun file. Ise Okan wa niyen Kosi besele wa kema ni nkan tefe lokan. Kolesese rara. Awon eyan mi, masowipe eyo gbogbo nkan kuro l'okan yin" Oro iranu niyen. talole se komani nkan tofe? kolesese. Afi tinba ku nikan nimole sowipe kosi nkan timo fe. oku o lenikan to fe kolesese. Agbudo ya gbogbo nkan tafe si mimo. Nkan toye kase niyen. ya gbogbo nkan tafe si mimo. Sarvopādhi-vinirmuktaṁ tat-paratvena nirmalam (CC Madhya 19.170). Ìpalẹ̀mọ́ niyen. Nirmalam. Tat-paratvena. Itumo Tat-paratvena ni imoye Olorun, imoye Krsna, lehin na ni okan wa le yasi mimo.

Gege na kon sepe awa o ni nkan tafe mo, sugbon gbogbo nkan tafe tidi mimo. Nkan tafe kosele niyen. Nitorina wansi sowipe, mayy āsakta-manāḥ: "Kosi besele yo gbogbo nkan tefe latinu okan re, sugbon egbokan lemi". Nkan tafe niyen. Mayy āsakta-manāḥ pārtha. Eto yoga niyen. Nkan tawan'pe ni bhakti-yoga niyen, yoga t'ipo kini. Wande ti salaaye re ninu Bhagavad-gītā, pe yoginām api sarveṣāṁ mad-gatenāntar-ātmanā (BG 6.47). yogi, lati'po kin yogi, yoginām api sarveṣām... Orisirisi eto yogha lowa, sugbo enikeni toba gba bhakti-yoga s'okan, gbogbo igba lon ronu mi" gege bi awon omo Okurin ati Obirin wanyi, asin kowan bonsele ranti Krsna nigbogbo igba "Hare Kṛṣṇa, Hare Kṛṣṇa, Kṛṣṇa Kṛṣṇa, Hare Hare/ Hare Rāma, Hare Rāma, Rāma Rāma, Hare Hare." teba ka Bhagavad-gītā te korin Hare Kṛṣṇa, lesekese lema ko gbogbo sayensi besele faramo Krsna. eleyi lonpe ni mayy āsakta-manāḥ. Mayy āsakta-manāḥ pārtha yogaṁ yuñjan,, Bhakti yoga leleyi. Mad-āśrayaḥ. "labe itosona mi" nitumo Mad-āśrayaḥ." Āśraya.