YO/Prabhupada 0139 - Ibasepo ninu emi niyen



Lecture on SB 3.25.38 -- Bombay, December 7, 1974

Teba feran Kṛṣṇa, konisi bibaje awon nkan ayeyi. Eleni ife fun gege bi Oga yin... teba sise fun Oga yin, inu re adunsi. inu iranse na asi dun ti Oga re ban sonwo fun. Sugbon ni ijoba orun kosi iru nkan bayi. Tin bale sise fun Oga mi nitori awon nkan majemu, Inu Ogami asi dun. Ti Ogami na - tiko bale sonwo - inu iranse asi dunsi. Nkankana niyen je. Apeere towa niyen. Awon akeko to po wa ninu iru ipo bayi. awa o sonwo kankan funwan sugobn wanse ounkoun funmi. Ibasepo toya si mimo niyen. Nigbati paṇḍita Jawaharlal Nehru, wa i ilu London, baba re funni Motilal Nehru, ọ̀ọ́dúrún rupees lati sonwo fun awon iranse re. Sugbon lojokan o si loba ni London , koderi iranse kankan nibe. paṇḍita si beere, " Nibo ni awon iranse re wa?" Osi sowipe, "kini iwulo Iranse? Ounkoun tinba fese molese fun arami". Rara, rara. Mofe ki awon Okurin geesi di iranse re." Ogbudo sonwo fun. Apeere towa niyen. Moni awon iranse to koja egberun lo, sugbon mio ni lati sonwo fun wan. Ibasepo ninu emi niyen. Ibasepo ninu emi niyen. Ise tonse fun owo ko lon se. Kini moni? Talaka ara-ile India nimi. Kini mole son funwan? Sugbon pelu ife , ife mimo niwan sise. Emina mon ko wan lai gbo'wo lowo wan. Nkan mimo leleyi. Pūrṇasya pūrṇam ādāya (Īśo Invocation). Odindin ni gbogbo nkan je. Teba gba Krsna sinu aye yin bi Ore, tabi Ololufe, konisejo iyanje. Egbiyanju kegba Krsna s'okan. Egbagbe awon iranse, omo, ati baba itanran-ẹni wanyi. Wanma tan yin je.