YO/Prabhupada 0141 - Iya ton funyin ni wara eyin sin fiku pa
Garden Conversation -- June 14, 1976, Detroit
Jayādvaita: Ni awon ile-iwe giga ti awan ko awon eyan leko, emi ati Satsvarūpa Mahārāja ti bere sini ko awon eyan nipa eto varṇāśrama-dharma. Nitoripe awon eyan wanyi femo nipa ọ̀wọ́ Hindu, nitorina wanle feti sile. Lehin na awan na ma soro lori eto varṇāśrama-dharma. kodesi bonsele fi eto na segbekan. wanni awon ariyanjiyan die tonle tisiwajum sugbon ko daju.
Prabhupāda: Iru ariyanjiyan wo loni?
Jayādvaita: Wan sowipe kole si ilosiwaju ninu awujo bayi, nitoripe awon eyan ma bere sini se idayato lori iru ebi teyan tiwa.
Prabhupāda: Rara, oto-oro koniyen.
Jayādvaita: Rara.
Prabhupāda: eto idayato niyen.
Jayādvaita: Lehin igbati awa bafiye wan tan, wakan joko laimo nkan tonle so. lehin na awa si bere lowo wan kinidi fun awujo teyin? Ipinnu wo loni? Kosi bonsele daun.
Prabhupāda: Laisi pinpin ninu ise, kosi basele se nkan gidi. idayato yi ti wan gan ninu ara wa - Ori, apa, ikun ati ese. gege na, ninu ara awujo eyan, agbudo ni ori na, awon eyan Ologbon, brāhmaṇa. gbogbo nkan asi lo jeje. lasiko tawayi kos'awon okurin t'ologbon. afi awon okurin alabasise. kosi awon eyan lati ipo kini tabi keji. Nitorina ni awujo wa seni isoro to po. kos'opolo nibe.
Jayādvaita: Ifura toni taba tin soro nipa brahmacārī, gṛhastha, vānaprastha, sannyāsa, niwipe, lesekese lo mani ikanra nitoripe wanmo pe awa osi feran eto igbadun ara.
Prabhupāda: Beeni. Igbadun ara lairori wo, iwa awujo awon eranko niyen. idari lori iye-ara wa ni eto awoju eda.... Awujo eda kokin sefun Igbadun ara lairoro wo. Awujo eda kokin sefun Igbadun ara lairoro wo. Rara. Awon eyan yi o mobe. Igbadun ara ni Ipinnu toni. asise toni niyen wansi sise ninu awujo awon eranko biwipe awujo eyan loje. asise tonni niyen. Igbadun ara lara rori wo, eto awon erank loje. Sugbon eranko lasan niwan. ton bale fiiku pa omo tonbi, iwa eranko niyen. gege bi awon aja ati ologbo, ton fiiku pa omo wan. Kini yen? Eranko ni. Se'ni ton ba omode na soro lotim'ẹru?
Hari-śauri:Ninu awon atimole . Trivikrama Mahārāja, Ni orile-ede Japan. Osowipe awon omo na ju ẹgbàawǎ lo, wansi ti wan mo atimole wa de fi wan sile.
Prabhupāda: ibudo bosi? tabi ibudo reluwe? wansi fi eru na sile. wanma fi wansi le, lai pada. lehin igba die, t'omo na bati ku a bere sini run. Awujo awon erankpo leleyi. wansi gba gbogbo wara lati maalu, toba ya wa ranwan lo si ile-iperan. wansi yo gbogbo wara kuro ninu maalu konto ran lo si ile-iperan. wan de pa wan lesekese. eyin si feran wara, eti gba wara to po na, eranko ton funyin ni wara na, iya loje siyin. wanti gbagbe. Iya ton funyin ni wara lati ara re,kilode t'efe fiku pa? Se ilosiwaju niyen? teyin paa iya yin? Wara si se pataki gan, nitorina lesen fa gbogbo wara to wa ninu maalu na. Nitorin kilode teyin sen fa gbogbo wara to wa ninu maalu na? Osi wulo. kilode teyin o lee fi maalu na sile ko bale fun awon eyan ni wara, bayi eyin na le se awon ounje to po repete lati wara? Ibo l'ogbon na wa? Iyipada eje ni wara je. kada tema fiku pa maalu na, emu wara re kese gbe bi awon okurin jeje. Rara. Awon okurin jeje ko ni wan eyan yi. awon odaran, alai -nilaju eyan. Tebafe jeran ele pa awon eranko bi elede ati aja ti oni iwulo. Ele je awon eranko bayi, teba fe. Ele se bayi, wan le gba laaye. Nitoripe kos'okurin jeje toma jeran. Ounje awon eyan to kere ju niyen. " teba fe ele je awon elede, śvapaca." Awon eyan pelu iwa to woo le, awon eyan bayi lon jeran. Teba fe jeran ele pa awon erank wanyi ti to niyi. Kilode tesen fiku pa awon eranko ton funyin ni wara? Iru ogbon wo lowa nbe/ teba wo Kṛṣṇa, lehin igbato pa Pūtanā, osi fun ni ipo iya. Nitoripe Kṛṣṇa si rowipe ounkooun to bawa ninu okan Pūtanā, moti mu oyon re gege na iya loje simi." Eyin sin mu wara lati maalu. se iya ko ni maalu je funyin? Talole gbe ninu ayeyi lai mu wara? talole sowipe oun mu wara maalu ri? l'owurọ teba ji, eyin na ma mu wara. eranko tosin fun yin ni wara, se iya ko loje? Ogbon wo lowa nibe? Awujo awon eyan ton fi ku pa iya wan. Eyin sin wa idunnu. Nitorina ni ogun sen sele, awon eyan asi fi ku pa ara wan.