YO/Prabhupada 0148 - Nkankanna laje pelu Olorun



Lecture on SB 7.6.1 -- Madras, January 2, 1976

dharma niyen. Sambandha, abhidheya, prayojana, awon nkan meta wanyi. Ona meta ni Veda pin si. Itumo Sambandha ni abasepo wa pelu Olorun. Sambandha niyen. lehin na abhidheya. gege na agbudo mo basele huwa. abhideya niyen. kinidi fun iwa tani? nitoripe ipinnu aye ni lati aseyori ninu eto yi. kini ipinnu aye yi? Lati le pada si Ijoba Oorun ni ipiinu aye wa. nkankanna la je pelu Olorun. sanātana ni Olorun je nitoripe oni ijoba re, sanātana. Paras tasmāt tu bhāvo 'nyo 'vyakto 'vyaktāt sanātanaḥ (BG 8.20). Ibe si wa fun ayeraye. Fun igba die ni ile aye yi wa fun, hūtvā bhūtvā pralīyate (BG 8.19). Osini ojo to bere. gege bi ara yin ati temi, oni ijo to bere. A wa fun igba die, ani idagbasoke. Asi se ibimo. lehin na ama darugbo, lehin na otan. itumo ṣaḍ-vikāra fun awon nkan aye yi niyen. sugbon osi ni aye towa tio ni ṣaḍ-vikāra. Aye towa fun ayeraye. nkan ton pe ni sanātana-dhāma niyen. awon jiva si ma wa fun ayeraye. Na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20). Wansi pe Olorun ni sanatana. nkan to wan wipe sanatana niwa, Sanatan ni Krsna, sanatana na ni ijoba re je. Taba si pada si sanatana-dharma yi ta gbe pelu olori awon sanatana, Krsna... sanatana na laje. ilana tale gba lati de ippinu yi, ni sanatana-dharma. sanatana-dharma lawan se.

sanātana-dharma ati bhāgavata-dharma, nkankan lonje. Bhāgavata, Bhagavān. lati oro bhagavān ni Bhāgavata ti wa. Śrī Caitanya Mahāprabhu ti salaaye nipa bhāgavata-dharma O sowipe, jīvera svarūpa haya nitya kṛṣṇa dāsa (Cc. Madhya 20.108-109). Iranse ayeraye laje fun Krsna. Otan. Sugbon ni asiko tawayi, pelu asepo tani pelu ile-aye yi, Dipo kadi iranse Olorun, tabi Krsna, Ati di iranse orisirisi nkan, maya nitorina lasen jiya. Awa o sini itelorun. Kolese se. gege bi eyan toba yo irin afi de nkan ninu ero ti irin na ba jabo kuru, koni wulo mo. sugbon ero na kole sise laisi irin afi de ninu re, sugbon teba de ero na pelu irin afi de eron na ma bere sini sise dada, irin na asi ni iwulo. gege na nkankanna laje pelu Olorun, Krsna. Krsna sowipe Mamaivāṁśo jīva-bhūtaḥ (BG 15.7), nisin tati kuro ni ijoba orun, ati sokale si ile-aye yi. Apeere imi to wa ni ina nla ati kekere. Ina kekere ma lagbara toba siwa ninu ina nla. Ti ina kekere na ba jade kuro ninu ina nla, lesekese loma ku. Kole gbina mo. Teba si dapada sinu ina nla asi gbina pada.

Bi ipo wa se ri niyen, bakana ati wa sinu ile-aye yi. nkankanna laje pelu Olorun, sugbon nitoripe ati wa sinu aye yi ati gbagbe ibasepo wa pelu Olorun Manaḥ-ṣaṣṭhānīndriyāṇi prakṛti-sthāni karṣati (BG 15.7). awa sin tiraka pelu awon ofin ile-aye yi, pelu orisirisi nkan. nibi na awa sin sise nitoripe iranse laje. Sugbon nitoripe ati fi ise Olorun sile, atin sise fun orisirisi nkan. Sugbon koseni toni itelorun. Otito to wa niyen. Kosi basele ni itelorun. Kosi basele ni itelorun nitoripe, iranse Olorun laje. sugbon ati wa sinu aye lati sise fun orisirisi nkan tio ye. Nitorina lasen seto ise talese. Irori opolo ni gbogbo eleyi. Manaḥ-ṣaṣṭhānīndriyāṇi prakṛti-sthāni karṣati (BG 15.7). Tiraka loje.