YO/Prabhupada 0147 - Kosi basele pe iresi lasan ni Iresi to gaju
Lecture on BG 7.1 -- Hong Kong, January 25, 1975
Awon elesin mowipe Olorun nbe, Bhagavan loje. Elepe Olorun ni Bhagavān. Nitorina wanse sowipe .. Kṛṣṇa lo so iwe mimo Bhagavad-gītā, gbogbo eyan lo mo. Sugbon nibomi ninu Bhagavad-gītā wansi salaaye re bi bhagavān uvāca. Bhagavān ati Kṛṣṇa - eni kanna loje. Kṛṣṇas tu bhagavān svayam (SB 1.3.28). oro Bhagavān sini isotunmo.
- aiśvaryasya samagrasya
- vīryasya yaśasaḥ śriyaḥ
- jñāna-vairāgyayoś caiva
- ṣaṇṇāṁ bhaga itīṅganā
- (Viṣṇu Purāṇa 6.5.47)
Bhaga, awa sini oye nipa oro bhāgyavān, bhāgya. oro yi bhāgyavān, bhāgya lati oro bhaga loti wa. owó öröôlá ni Itumo Bhaga Owo ni itumo owó öröôlá. Aduro owo wo ni Okurin kan leeni? Teyan na ba l'owow, toba l'ogbon, toba rewa, toba sini ipo giga, tosi l'ogbon, tosi le gbo'kan kuro lori nkan aye yi - itumo Bhagavān niyen.
Taba soro nipa "Bhagavān," Bhagavān, tabi Parameśvara Īśvara, Parameśvara; Ātmā, Paramātmā; Brahman, Para-brahman - oro meji niyen. Nkan lasan niyen, param n'ikeji. gege bi ounje si se, ale se orisirisi iresi. Iresi si wa. Orisirisi oruko lowa bi: anna, paramānna, puṣpānna, kicoranna. paramānna ni anna to gaju . Enito gaju ni Parama. Anna, iresi na si wa nbe, sugbon oti bosori ipo to ga gan. Kosi basele pe iresi lasan ni Iresi to gaju. Iresi na sini. sugbon teba se iresi pelu kṣīra, wara ni itumo kṣīra, pelu awon orisirisi nkan, paramānna niyen je. gege na ni iyato laarin awon eda ati Bhagavān - Iyato laarin wan si kere. Bhagavān... Awa si l'ara, Bhagavān na si l'ara. Eda ni Bhagavān je, eda na lawa. Bhagavān sini agbara ati da nkan sile, awa na si l'agbara kanna. sugbon iyato to wa niwipe oun lagbara gan. Eko yo bahūnāṁ vidadhāti kāmān. Ti Bhagavān bafe da gbogbo agbaye yi sile, oole se lai gba iranlowo lowo eni kankan. Lat'ofurufu lotin da nkan sile. Lati ofurufu eyan le gbo ohun; lat'ohun la'fefe tiwa; lati afefe ni ina ti wa; lati ina l'omi tiwa, beena lati omi ni ile ti wa.