YO/Prabhupada 0165 - Bhakti ni awon ise ton yasi mimo



Lecture on BG Introduction — New York, February 19-20, 1966

Eda to mo nipa oun gbogbo, wanti salaaye nipa re ninu Bhagavad-gītā ninu akori ton soro nipa iyato laarin jīva ati īśvara Kṣetra-kṣetra-jña. Wanti salaaye na wipe Olorun ni kṣetra-jña tabi mimọ sinu awon jiva ati awon eda na sini mimọ sinu. Sugbon iyato to wa niwipe mimi sinu fun awon eda lopin sugon t'Oluwa bo ti gbogbo eda. Īśvaraḥ sarva-bhūtānāṁ hṛd-deśe 'rjuna tiṣṭhati (BG 18.61). Oluwa nbe ninu okan gbogbo awon eda, nitorina lose mo gbogbo ise ti onikaliku nse. Awa o gbudo gbagbe. Wanti salaaye na wipe Paramātmā, tabi Olorun gbogbo agbaye, wa ninu okan gbogbo awon eda bi īśvara, Oludari loje fun gbogbo eda, oun lonsi fun wa ni itosona. Oun fun ara re lon funwa. Sarvasya cāhaṁ hṛdi sanniviṣṭhaḥ (BG 15.15). O wa ninu okan gbogbo eyan, oun lo sin funwa ni itosona basele huwa bosefe.

Awon eda man gbagbe nkan toye kan se. Ni alakoko oun lon je ki awon eda huwa, toba ya asi yipo ninu gbogbo nkan toti se, ati awon ibajade ise re ti tele, karma. Sugbon nigbato ba fara kan sile, to wonu ara imi... gege bi awa sen boso kan fun ikeji, gege na Bhagavad-gita ti salaaye wipe āsāṁsi jīrṇāni yathā vihāya (BG 2.22). Bi awon eyan sen boso kan fun ikeji ni awon eda na sen farale fun ara imi, iparo emi kan fun ikeji, ati awon ibajade gbogbo nkan toti se teletele. Gege na awon eda le paaro gbogbo awon iwa ton hu ton bale yi okan wan si iwa to dara, bayi o le mo iru iwa tole hu, toba le se bayi gbogbo awon abajade fun nkan tose teletele a yipada. Nitorina fun igba die ni karma wa fun. awon nkan merin toku ni - īśvara, jīva, prakṛti, kāla, ati karma - awon nkan merin wa fun ayeraye, sugbon karma, fun igba die lowa.

Nisin īśvara to l'ogbon, īśvara toni mimo gbogbo nkan, iyato towa laarin īśvara, tabi Olorun ati awon eda ninu ayidayida tawayi leleyi. Imoye, t'Oluwa ati awon eda Imoye yi yato si imoye t'aye yi. Konsepe lati ibasepo pelu awon nkan aye yi ni imoye yi ti jade. aṣiṣe towa ninu irori yi leleyi. Alaye ton fun wa wipe imoye awon nkan man dede jade tonba wa ninu awon ilopo aye yi, Eleyi o baramu pelu ilana ti Bhagavad-gita funwa. Kosi bonsele se. A le ri nkan to jo Imoye awon eda, gege b'ina to wòye pelu awọ lehin igba to ba tansi gilaasi pelu awọ orisirisi. Gege na awa o le ri imoye Olorun bayi. Olorun, gege bi Krsna sowipe, mayādhyakṣeṇa prakṛtiḥ (BG 9.10). Imoye re o ni nkankan se pelu awon nkan aye yi nigbato ba sokale wa toba jewipe imoye re ni asepo pelu awon nkan aye yi, kosi bosele soro lori awon nkan nipa emi tose pataki ninu Bhagavad-gita. Kosi beyan sele soro lori awon aye yi lai jade kuro ninu imoye aye yi to doti.

Gege bayi a le riwipe kosi nkankan t'aye yi to sopo Olorun. Sugbon imoye wa doti gan pelu awon nkan aye yi. Nitorina loyeka so imoye wa di tuntun gege bi Bhagavad-gita se so Lehin na ninu imoye yi to mole, a le huwa to da. Inu wa a si dun. Kosi basele se ka ma sise. Sugbon a le se ka ma huwa tio da, a gbudo yipo si awon nkan to da ton pe ni bhakti. Itumo Bhakti niwipe wan jo awon ise lasan sugbon ise lasan ko lonje. Ise to ya si mimo lon je. Awon eyan tio l'ogbon le rowipe ise lasan ni awon elesin se, sugbon awon eyan tio l'ogbon, kole se iyato laarin ise awon elesin tabi t'Olorun, awon eyan yi o le ni nkan nkan se pelu awon nkan aye yi, idoti lati awon guna meta, ipo ile aye yi, sugbon imoye to gaju . Gege na agbudo mowipe imoye wa ti doti pelu awon nkan aye yi.