YO/Prabhupada 0166 - Kosi besele fi ipari si yinyin ton ro
Lecture on BG 2.7-11 -- New York, March 2, 1966
Oyeka ranti nigbagbogbo pe awan jiya. Ijiya orisirisi meta lowa. Mio soro nipa awon isoro oro-aje tabi ... Ijiya toyato niyen. sugbon imoye Veda ti fi yewa pe - tabi otooro no loje- pe orisirisi ijiya meta lowa. Ikan ninu awon ijiya yi wa pelu ara wa at'okan... Nisin, kasowipe moni orififo. Nisin otutu sin mumi, ara sin romi. gege bayi laseni awon ijiya lat'okan wa. Okan mi o bale leni. Eyankan pemi ni oruko tioda. Nisin mon jiya. tabi awo oremi ti fimisile, orisirisi nkan bayi. awon ijiya t'ara wa a t'okan wa pelu awon ton t'iseda wa adhidaivika l'Oruko wan, awon eleyi koja idari wa. ninu awon ijiya yi, kos'idari kankan tani, Kasowipe yinyin ro pupo. Gbogbo ilu New York kun fun yinyin, gbogbo wa lama ni isoro pupo. Iru ijiya t'awa o ni idari lori re leleyi, sugbon eyin na o ni idari lori re. Kosi besele fi ipaari si yinyin ton ro. Se ri bayi? T'ategun bafe gan kosi besele daduro. Ijiya adhidaivika lelyi Awon ijiya ara yi at'okan wa l'on pe ni adhyātmika. awon ijiya imi si wa bi adhibhautika, ija lati awon eda toyato si wa. ota mi, tabi awon erank tabi awon kokoro, wan po gan. Awon ijiya meta wanyi si po gan. sugbon awa osi fe iru awon ijiya meta wanyi. Sugbon ti ebere yi ba de..
Nisin Arjuna ti mowipe " Ogun ti de, mode gbudo jagun pelu awon ota mi nitoripe ise mi niyen, sugbon isoro wan'be nitoripe awon ara ile mi wa pelu wan." Nkan ton ro niyen. Gege na afi ti awon eyan ba ji ton dide s'oke si otooro wipe awon eyan jiya sugbon awa o si fe jiya mo... Iru eyan bayi gbudo loba Oluko ninu eto emi toba l'ogbon. Seri bayi? Sugbon to wa bi eranko kole mowipe iya n'je.. Kole mo, kode le ronu si, tabi ko fe ronu si, tabi kofe wa ona abayo si. nisin Arjuna tin jiya, osi fewa ona abayo si, nitorina lose fe gba oluko ninu eto emi. taba ji, ta dide soke si gbogbo iya tan je, Ijiya yi wan'be. Igbagbe tabi aimo nipa ijiya ko le funwa ni ona abayo kankan. Ijiya yi wan'be sugbon teyan ba ni okan lati wa ona abayo si awon isoro aye re, lehin na ogbudo wa Oluko ninu eto emi. Gege bi Arjuna sefe Oluko ninu eto emi. So ye yin? Beeni. Ijiya yi wa n'be. Kosejo pe afe keko latile mo, teba ronu die oma ye yin, Pe " io fe jiya bayi, sugbon mon jiya. Kilode? Se ona abayo kankan wa? So wa? sugbon ona abayo wa. Gbogbo awon iwe mimo, pelu iwe mimo Veda, gbogbo e.. sugbon Imoye awon Veda nikankan ko... Oh, kilode teyin sen losi ile-iwe? Kilode teyin sen losi ile-iwe giga? Kilode teyin sen keko nipa sayensi? Kilode teyinsen keko nipa awon ofin? Gbogbo nkan wa lati le fi ipari si ijiya wa. Toba jewipe awon eyan o jiya koseni toma keko. Se ri bayi? Sugbon awon eyan rowipe tinba losi ile-iwe, tinba di dokita tabi tinba di agbẹjọro tabi tinba di elero, inu mi adunsi." Idunnu. Opin gbogbo wa. " tin ba ri ise gidi se, tabi ise ijoba. Inumi adun."
Gege na idunnu ni opin gbogbo eto aye yi. sugbon gbogbo awon ona abayo yi fun iya tan je, fun igba die ni. Ijiya wa nitori ile-aye yi tawa ni, awon ijiya meta wanyi. Gege na teyan ba ni oye nipa awon ijiya toni, tosi fe ona abayo fun, ogbudo gba oluko ninu eto Oluko. Nisin, teba fe fi ipaari si gbogbo ijiya teni, tesi fe wa eni to le bayin se, iru eyan wo lema loba tole bayin yonju gbogbo ijiya wanyi? Yiyan yi gbudo wan'be teba fe ra okuta iyebiye, tabi nkan to ba niyi,sema lo sile eni ton ta ounje... Iru aimokan wo leleyi - wan ma tan yinje. wan ma tan yinje. Egbudo losi ibi ton ta awon ileke iyebiye. se ri bayi. Egbudo l'ogbon lori.