YO/Prabhupada 0168 - Asa ton kowa basele resile



Room Conversation -- February 4, 1977, Calcutta

Prabhupada: Ale toro. Ni India, awon sannyasi alakowe gan man toro. Wan gbalaaye. Bhikṣu. Wan feran re. Tridaṇḍī-bhikṣu. gege na ninu ofin Veda teyan ba toro, nkan itiju ko tabi arufin - toba je eni toye ko s. Awon brahmacārīs ati sannyāsīs le toro. Kosi itiju nibe. Tridaṇḍī-bhikṣu. Alagbe ni'tumo Bhikṣu.

Satsvarūpa: Tridaṇḍī-bhikṣu.

Prabhupāda: Beeni. Ninu asa India awon brahmacārī, sannyāsī ati brāhmaṇa, wanle toro je. Asa Veda niyen. Awon onile asi toju wan gege bi wipe omo lon je siwan. Ibasepo towa niyen.

Satsvarūpa: sugbon teyan base iru nkan bayi ninu asa to yato si asa India?

Prabhupāda: Nitorina "hippie" ni iru awon bayi. Asa ilu yin niyen - awon "hippie" at'awon apeyan, gbogbo e na ni oruko esin. Asa wan niyen. Ati iṣẹyun Nitoripe ko s'asas kankan, awon eyan man ṣẹyun wan si pa awon eda, nitorina ni gbogbo agbaye sen baje bayi. Asa teni niyen. Ija laarin awon Alatẹnumọ ati awon katoliki. Eru n'ba awon eyan. Awon eya o le jade si titi. Asa yin niyen. Kilowa buru tryan ba toroje. Sugbon kema feru ba gbogbo awon, nkan to da niyen, sugbon teyan ba toroje, laise ijogbon, nkan tio da niyen. Asa yin leleyi. Asa Veda niwipe awon brahmacari ni lati toro konbale mo bon sen rẹ̀ sílẹ̀, kon sepe wan kon toroje. Lati awon ebi to niyi lonti wa, sugbon wan gbudo ko lati toro. Atoroje ko leleyi. Wan ko lati rẹ̀ sílẹ̀ Jesu Kristi si sowipe , " awon ton ba rẹ̀ sílẹ̀, Olorun asi wa fun wan." Konsepe wan kon toroje. Eyin o mo nkan t'asa gidi je. Eyin ni asa yin, asa esu, tojepe eyan le fiku pa omo ti e. Bawo lese femo nkan t'asa gidi je? S'oto ni abi iro?

Satsvarūpa: Ooto le so.

Prabhupāda: Beeni. Awon eyan ni ilu yi wan kere ju eyan ni ipo kerin tabi kewa. bawo lesefe mo nipa asa to ko awon eyan lati re sile?

Satsvarūpa: Adajo l'agbegbe wa fe mu wa losi ile-ejo. Ādi-keśava, ti salaaye asiri re funwa, nitoripe awon adajo ti sowipe awa o le s'esin wa. Onikaluku le s'esin toba wun.

Prabhupada: Ofe ni.. Esin to daju. Satsvarūpa: O sowipe "Sugbon esin ko leleyi." O sowipe, " iyato wa laarin esin ati awon eyan ton fe n'idari lori okan wa. Sugbon ejo onikaluku niyen. Mio rope enikankan to gbon ajek'eloi ni idari lori okan re. gege bi awon eyan tonle p'ase sori okan eleomi.

Prabhupada: Gbogbo nkan ni idari lori okan yi je.

Satsvarūpa: Ounkooun.

Prabhupada: Nkankanna ni awon na n'se. Nisin wan fe f'agidi fi gba awon eyan to wa pelu wa Iru idari lori okan awon eyan na niyen. Wanti fun fun l'okan wan, sugbon eyin na fe gba wan pelu agidi, jí ènìyàn gbé . Se idari lori okan ko niyen? Nibi enina ti gbokan le imoye Krsna, sugbon eyin fe yo enina kuro pelu agidi. Se idari lori okan onitoun ko niyen? " Sugbon nkan teyin se si okan wan da, temi ni oda." Se nkan teyin so niyen. Enikieni le dede ji ko sowipe, " Gbogbo nkan timon se da, sugbon nkan tiwan se o da."