YO/Prabhupada 0167 - Kolesi alebu ninu awon ofin Olorun



Lecture on SB 6.1.8-13 -- New York, July 24, 1971

Awon ofin eda, oro n'la loje teyan [a fiku pa elomi. Wan gbudo pa apànìyàn na. Kilode tawan o le se bayi fun awon erank na? Eda bi awa na ni awon eranko je. Eda na ni okurin je. Gege na teba l'ofin to sowipe teyan ba pa elomi wan gbudo fiku pa onitoun, kilode teyin o le s'ofin wipe teyan ba pa awon eranko oye kan fiku pa? Kini'di fun eleyi? Ofin tawan eda okurin da niye, ko daju. sugbon kosejo pe awon ofin Olorun ni alebu kankan. Ninu ofin Olorun teba fiku pa awon eranko egbudo jiya fun, gege bi teba pa eda eyan. Ofin Olorun niyen. Kosejo ikewo, teba fiku pa Okurin egbudo jiya fun, sugbon teba fiku pa eranko kosi nkankan toma sele. Iranu ni gbogbo eleyi. Ofin wa o daju. Nitorina ni Jesu Kristi se juwe ninu awon "Ofin mewa: Ema fiku pa." Ofin to daju niyen. Kon sepe kese iyasoto pe " Mi ole pa awon okurin sugbon mole fikupa awon eranko."

ètùtù orisirisi lowa. Ninu ofin Veda, ti maalu ba pokunso.. nitoripe okun ton fi so loorun ti fun ju, eni toni maalu na gbudo s'ètùtù. maalu na ti pokunso nitoripe koseni to foju ti gege na egbudo s'ètùtù. Nisin teyin ba fiku pa awon maalu ati orisirisi eranko, selo fori ro aduro gbese teni lati san? Nitori gbogbo iru nkan bayi ni ogun se wa, gege na awon eyan fi ku pa opolopo eyan - ofin iseda niyen. Kosi besele fi ipaari si gbogbo awon ogun wanyi teba fe ma pa awon eranko. Kolese se. Awon ijamba to po ma sele nitori awon eranko teyin pa. Ti Krsna ba fe fiku pa awon eryan na, ni odindin loma se. Sugbon teyin ba fe pa - ikan kan lele se. Sugbon ti Krsna ba fe pa wan, asi kowan jo sibi kan koto pa wan. Nitorina a le sowipe etutu wa ninu awon sastras. Gege bi iwe Bibeli yin, etutu, ijẹwọ ati sisan awon nkan. Sugbon leyin igba tonba s'etutu yi tan kilode tonse tun awon ese yi se? Nkan toye ko ye wa niyen.