YO/Prabhupada 0178 - Dharma ni awon ase ti Krishna funwa
Lecture on SB 1.10.1 -- Mayapura, June 16, 1973
Nkan t'Olorun ti fun wa nituo Dharma. Dharma leleyi. Kosi besele da dharma sile. Gege bi asiko tawayi, orisirisi dharma lonti daale. Dharma ko lonje. Awon ofin Olorun nitumo dharma. Dhanrma niyen. Gege bi Krsna se so, sarva-dharman parityajya mam ekam saranam vraja (BG 18.66). Ati da orisirisi dharma sile: dharma awon Hindu, dharma awon Musluman, dharma awon Kristiani, dharma awon Parsee, dharma awon Buddha, dharma tibi. dharma ko ni gbogbo awon nkan yi. awon nkan afori ro lonje. Bibeko, idapo ma wa. Fun apeere awon Hindu sowipe teba pa maalu, nkan to da loje. Awon musulman sowipe nkan to da niyen. Ewo lo daju nisin? Se pipa maalu da tabi ko da?
Awon nkan afori ro nigbogbo eleyi. Caitanya-caritamrta karaca sowipe, ei bhala ei manda saba manodharma, " Oro afori da." Dharma to daju ni Olorun fe ka se. Dharma niyen. Nitorina ni Krsna se sowipe, sarva-dharman parityajya mam ekam saranam vraja: (BG 18.66) "E fi gbogbo dharma te daa sile. Dharma to daju leleyi." Saranam vraja. " E teriba funmi, dhram to daju leleyi." Dharmam tu saksad bhagavat-pranitam (SB 6.3.19). gege bi awon ofin. Ale da awon ofin sile tabi ka gba awon ofin ijoba. Kosi besele da awon ofin ninu ile yin. Ofin koniyen. Ilan ti'joba nitumo ofin. Olorun ni'joba to gaju. Aham sarvasya prabhavo (BG 10.8) mattah parataram nanyat (BG 7.7). Koseni kankna to gaju Krsna lo. Nitorina dharma ni awon ilani ti Krsna funwa. Egbe imoye Krsna wa yi ni dharma na. Krsna sowipe sarva-dharman parityajya mam ekam saranam vraja: (BG 18.66) " Efi gbogbo awon dharma iro wanyi sile. E teriba funmi."
Ofin kanna lanwa fi sewaasu, Caitanya Mahaprabhu de ti passe si.. Amara ajnaya guru hana tara' ei desa, yare dekha tare kaha krsna-upadesa (CC Madhya 7.128). Dharma niyen. Caitanya Mahaprabhu o da dharma kankan sile. Rara. Krsna fun ara re ni Caitanya Mahaprabhu. Namo maha-vadanyaya krsna-prema-pradaya te, krsnaya krsna-caitanya-namne (CC Madhya 19.53). Krsna fun ara re loje. Iyato pere to wa nibe niwipe, Krsna sowipe " Efi gbogbo iranu yi sile, ke teriba fun mi." Krsna leleyi. Nitoripe Olorun loje, o funwa ni awon ofin fun ara re. Krsna kanna loje sugbon awon eyan o feti si oro to so.. Awon alakowe gan sowipe, " Nkan ti Krsna so ti po ju." Sugbon asiwere niwan. Wan o mo. Kosi bonsele mo eni ti Krsna je. Nitoripe awon o ni oye nipa nkan to so lose pada wa bi elesin lati ko wan bonsele teriba fun. Krsna wa. Nigbami iranse mi man funmi n'ifọwọra. Sugbon tin ba fe fi han, ma fowo t ori re, " Se bayi." Sugbon iranse re ko nimo je, mofe fi han. Gege na Krsna ni Sri Caitanya Mahaprabhu je fun ara re, Sugbon o wa kowa basele summon Krsna, basel sise fun Krsna. Ofin kanna loje. Krsna sowipe, " E teriba funmi," Caitanya Mahaprabhu sowipe " E teriba fun Krsna." Kosi iyasoto lori ofin na.